ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Hébérù 12
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Hébérù

      • Jésù ni Aláṣepé ìgbàgbọ́ wa (1-3)

        • Àwọsánmà àwọn ẹlẹ́rìí (1)

      • Má fojú kéré ìbáwí látọ̀dọ̀ Jèhófà (4-11)

      • Ẹ ṣe ọ̀nà tó tọ́ fún ẹsẹ̀ yín (12-17)

      • Wọ́n sún mọ́ Jerúsálẹ́mù ti ọ̀run (18-29)

Hébérù 12:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 3:12
  • +1Kọ 9:24, 26; Flp 3:13, 14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 19

    Ilé Ìṣọ́,

    9/15/2011, ojú ìwé 17-18, 20-23

    8/15/2004, ojú ìwé 23-24

    1/15/2003, ojú ìwé 5-6

    1/1/2001, ojú ìwé 29-30

    10/1/1999, ojú ìwé 17-18, 19-21

    1/15/1998, ojú ìwé 13

    1/1/1998, ojú ìwé 6-11

    1/15/1997, ojú ìwé 30

    11/1/1991, ojú ìwé 13-18

    10/15/1991, ojú ìwé 22

    Jí!,

    6/8/2004, ojú ìwé 25

Hébérù 12:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 14:6; Iṣe 5:31; Heb 2:10
  • +Sm 110:1; Heb 10:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2016, ojú ìwé 27

    4/2016, ojú ìwé 12

    ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run’, ojú ìwé 203-204

    Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, ojú ìwé 1709

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2010, ojú ìwé 5

    7/15/2009, ojú ìwé 6-7

    10/15/2008, ojú ìwé 32

    10/1/2006, ojú ìwé 26

    9/15/2005, ojú ìwé 21

    1/1/2005, ojú ìwé 15

    1/1/2001, ojú ìwé 31

    9/1/2000, ojú ìwé 12

    10/1/1999, ojú ìwé 20-21

    5/15/1998, ojú ìwé 10

    2/15/1996, ojú ìwé 28-29

    10/15/1994, ojú ìwé 14

    3/1/1994, ojú ìwé 30

    9/15/1993, ojú ìwé 13-14

    11/1/1991, ojú ìwé 13-14

    9/15/1991, ojú ìwé 12

    1/1/1991, ojú ìwé 16

    “Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn,” ojú ìwé 73-74

Hébérù 12:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “rẹ̀wẹ̀sì nínú ọkàn yín.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 27:39
  • +Ga 6:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    4/2016, ojú ìwé 12

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2008, ojú ìwé 32

    1/15/2008, ojú ìwé 26-27

    1/1/2005, ojú ìwé 15

    12/1/1995, ojú ìwé 13-14

Hébérù 12:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2008, ojú ìwé 32

    4/15/2002, ojú ìwé 30

    2/15/2002, ojú ìwé 29

Hébérù 12:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2012, ojú ìwé 28

Hébérù 12:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

  • *

    Tàbí “bá wí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 3:11, 12

Hébérù 12:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “gba ìdálẹ́kọ̀ọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Sa 7:14; Heb 2:10
  • +Owe 13:24

Hébérù 12:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “àwọn baba tó ni ẹran ara wa.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jem 4:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    9/2019, ojú ìwé 14-15

Hébérù 12:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Pe 1:15, 16

Hébérù 12:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “kó ẹ̀dùn ọkàn báni.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2007, ojú ìwé 19

Hébérù 12:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 35:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 379

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    2/15/1996, ojú ìwé 14

Hébérù 12:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 4:26

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2008, ojú ìwé 32

Hébérù 12:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìjẹ́mímọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 34:14; Ro 12:18; 14:19
  • +Ro 6:19; 1Tẹ 4:3, 4; Heb 10:10

Hébérù 12:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 29:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2008, ojú ìwé 32

    11/1/2006, ojú ìwé 26

Hébérù 12:16

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀, “Ìṣekúṣe.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 25:32, 34

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2017, ojú ìwé 14-15

    Ilé Ìṣọ́,

    5/15/2013, ojú ìwé 28-29

    5/1/2002, ojú ìwé 10-11

Hébérù 12:17

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, láti yí bàbá rẹ̀ lérò pa dà.

  • *

    Ní Grk., “kò rí àyè fún un.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 27:34

Hébérù 12:18

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àwọsánmà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 19:12
  • +Ẹk 19:18
  • +Ẹk 19:16

Hébérù 12:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 19:19
  • +Di 4:11, 12
  • +Ẹk 20:18, 19

Hébérù 12:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 19:12, 13

Hébérù 12:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 9:19

Hébérù 12:22

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ẹgbẹẹgbàárùn-ún.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ifi 14:1
  • +Ifi 21:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 199

Hébérù 12:23

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 7:10
  • +Jẹ 18:25; Sm 94:2; Ais 33:22
  • +Heb 12:9
  • +Heb 10:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    7/1/1995, ojú ìwé 11

Hébérù 12:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ti 2:5; Heb 9:15
  • +Mt 26:27, 28
  • +Jẹ 4:8, 10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2008, ojú ìwé 13-14

Hébérù 12:25

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “wá àwáwí fún.”

  • *

    Tàbí “ẹ ò ṣàìka ẹni tó ń sọ̀rọ̀ sí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 1:2; 2:2-4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2010, ojú ìwé 25-26

Hébérù 12:26

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 19:18
  • +Hag 2:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    9/2021, ojú ìwé 18-19

    Ilé Ìṣọ́,

    5/15/2006, ojú ìwé 31

    4/15/2006, ojú ìwé 20

Hébérù 12:27

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    9/2021, ojú ìwé 18-19

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2008, ojú ìwé 32

    5/15/2006, ojú ìwé 31

    4/15/2006, ojú ìwé 20

Hébérù 12:28

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    9/2021, ojú ìwé 19

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2006, ojú ìwé 24

    4/15/2006, ojú ìwé 20

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 199

Hébérù 12:29

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 4:24

Àwọn míì

Héb. 12:1Heb 3:12
Héb. 12:11Kọ 9:24, 26; Flp 3:13, 14
Héb. 12:2Jo 14:6; Iṣe 5:31; Heb 2:10
Héb. 12:2Sm 110:1; Heb 10:12
Héb. 12:3Mt 27:39
Héb. 12:3Ga 6:9
Héb. 12:6Owe 3:11, 12
Héb. 12:72Sa 7:14; Heb 2:10
Héb. 12:7Owe 13:24
Héb. 12:9Jem 4:10
Héb. 12:101Pe 1:15, 16
Héb. 12:12Ais 35:3
Héb. 12:13Owe 4:26
Héb. 12:14Sm 34:14; Ro 12:18; 14:19
Héb. 12:14Ro 6:19; 1Tẹ 4:3, 4; Heb 10:10
Héb. 12:15Di 29:18
Héb. 12:16Jẹ 25:32, 34
Héb. 12:17Jẹ 27:34
Héb. 12:18Ẹk 19:12
Héb. 12:18Ẹk 19:18
Héb. 12:18Ẹk 19:16
Héb. 12:19Ẹk 19:19
Héb. 12:19Di 4:11, 12
Héb. 12:19Ẹk 20:18, 19
Héb. 12:20Ẹk 19:12, 13
Héb. 12:21Di 9:19
Héb. 12:22Ifi 14:1
Héb. 12:22Ifi 21:2
Héb. 12:23Da 7:10
Héb. 12:23Jẹ 18:25; Sm 94:2; Ais 33:22
Héb. 12:23Heb 12:9
Héb. 12:23Heb 10:14
Héb. 12:241Ti 2:5; Heb 9:15
Héb. 12:24Mt 26:27, 28
Héb. 12:24Jẹ 4:8, 10
Héb. 12:25Heb 1:2; 2:2-4
Héb. 12:26Ẹk 19:18
Héb. 12:26Hag 2:6
Héb. 12:29Di 4:24
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
  • 28
  • 29
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Hébérù 12:1-29

Sí Àwọn Hébérù

12 Nígbà náà, torí pé a ní àwọsánmà àwọn ẹlẹ́rìí tó pọ̀ gan-an yí wa ká, ẹ jẹ́ kí àwa náà ju gbogbo ẹrù tó wúwo nù àti ẹ̀ṣẹ̀ tó máa ń wé mọ́ wa tìrọ̀rùn-tìrọ̀rùn,+ ká sì máa fi ìfaradà sá eré ìje tó wà níwájú wa,+ 2 bí a ṣe ń tẹjú mọ́ Jésù, Olórí Aṣojú àti Aláṣepé ìgbàgbọ́ wa.+ Torí ayọ̀ tó wà níwájú rẹ̀, ó fara da òpó igi oró,* kò ka ìtìjú sí, ó sì ti jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún ìtẹ́ Ọlọ́run.+ 3 Ní tòótọ́, ẹ fara balẹ̀ ronú nípa ẹni tó fara da irú ọ̀rọ̀ kòbákùngbé bẹ́ẹ̀ láti ẹnu àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀,+ tí wọ́n ń ṣàkóbá fún ara wọn, kó má bàa rẹ̀ yín, kí ẹ má sì sọ̀rètí nù.*+

4 Bí ẹ ṣe ń bá ẹ̀ṣẹ̀ yẹn jà, ẹ ò tíì ta kò ó débi pé kí wọ́n ta ẹ̀jẹ̀ yín sílẹ̀ rárá. 5 Ẹ sì ti gbàgbé ọ̀rọ̀ ìyànjú náà pátápátá, tó fi bá yín sọ̀rọ̀ bí ọmọ pé: “Ọmọ mi, má fojú kéré ìbáwí látọ̀dọ̀ Jèhófà,* má sì sọ̀rètí nù nígbà tó bá tọ́ ọ sọ́nà; 6 torí àwọn tí Jèhófà* nífẹ̀ẹ́ ló máa ń bá wí, àní, gbogbo ẹni tó gbà bí ọmọ ló máa ń nà lẹ́gba.”*+

7 Ẹ nílò ìfaradà bí ẹ ṣe ń gba ìbáwí.* Ọlọ́run mú yín bí ọmọ.+ Torí ọmọ wo ni bàbá kì í bá wí?+ 8 Àmọ́ tí gbogbo yín ò bá tíì pín nínú ìbáwí yìí, a jẹ́ pé ọmọ àlè ni yín, ẹ kì í ṣe ọmọ. 9 Bákan náà, àwọn bàbá tó bí wa* máa ń bá wa wí, a sì máa ń bọ̀wọ̀ fún wọn. Ṣé kò wá yẹ kó yá wa lára láti fi ara wa sábẹ́ Baba tó ni ìgbésí ayé wa nípa ti ẹ̀mí, ká lè máa wà láàyè?+ 10 Torí ìgbà díẹ̀ ni wọ́n fi ń bá wa wí, bó ṣe dáa lójú wọn, àmọ́ torí ire wa ni òun ṣe ń ṣe bẹ́ẹ̀, ká lè pín nínú ìjẹ́mímọ́ rẹ̀.+ 11 Lóòótọ́, kò sí ìbáwí tó jẹ́ ohun ayọ̀ báyìí, àmọ́ ó máa ń dunni;* síbẹ̀, tó bá yá, ó máa ń so èso àlàáfíà ti òdodo fún àwọn tí a ti fi dá lẹ́kọ̀ọ́.

12 Torí náà, ẹ fún àwọn ọwọ́ tó rọ jọwọrọ àti àwọn orúnkún tí kò lágbára lókun,+ 13 kí ẹ sì máa ṣe ọ̀nà tó tọ́ fún ẹsẹ̀ yín,+ kí ohun tó rọ má bàa yẹ̀ kúrò ní oríkèé, àmọ́ ká lè wò ó sàn. 14 Ẹ máa lépa àlàáfíà pẹ̀lú gbogbo èèyàn+ àti ìsọdimímọ́,*+ tó jẹ́ pé láìsí i, èèyàn kankan ò lè rí Olúwa. 15 Ẹ kíyè sára gidigidi ká má bàa rí ẹnikẹ́ni tí kò ní gba inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí Ọlọ́run, kí gbòǹgbò kankan tó ní májèlé má bàa rú yọ láti dá wàhálà sílẹ̀, kó sì sọ ọ̀pọ̀ di aláìmọ́;+ 16 kí ẹ sì máa kíyè sára, kó má bàa sí ẹnì kankan láàárín yín tó jẹ́ oníṣekúṣe* tàbí ẹnikẹ́ni tí kò mọyì àwọn ohun mímọ́, bí Ísọ̀, tó fi àwọn ẹ̀tọ́ àkọ́bí tó ní tọrẹ nítorí oúnjẹ ẹ̀ẹ̀kan ṣoṣo.+ 17 Torí ẹ mọ̀ pé lẹ́yìn náà, nígbà tó fẹ́ gba ìbùkún náà, a kọ̀ ọ́; torí bó tiẹ̀ sunkún bó ṣe gbìyànjú gan-an láti mú kí èrò yí pa dà,*+ pàbó ló já sí.*

18 Torí kì í ṣe ohun tó ṣeé fọwọ́ bà,+ tí a sì dáná sí,+ lẹ sún mọ́, kì í ṣe ìkùukùu* tó ṣú dùdù àti òkùnkùn biribiri àti ìjì,+ 19 àti ìró kàkàkí+ àti ohùn tó ń sọ̀rọ̀,+ èyí tó jẹ́ pé nígbà tí àwọn èèyàn náà gbọ́ ọ, wọ́n bẹ̀bẹ̀ pé ká má ṣe bá àwọn sọ̀rọ̀ mọ́.+ 20 Torí wọn ò lè mú àṣẹ náà mọ́ra pé: “Tí ẹranko pàápàá bá fara kan òkè náà, ẹ gbọ́dọ̀ sọ ọ́ lókùúta.”+ 21 Bákan náà, ohun tí wọ́n rí bani lẹ́rù débi pé Mósè sọ pé: “Ẹ̀rù ń bà mí, jìnnìjìnnì sì bò mí.”+ 22 Àmọ́ ẹ ti sún mọ́ Òkè Síónì+ àti ìlú Ọlọ́run alààyè, Jerúsálẹ́mù ti ọ̀run+ àti ọ̀kẹ́ àìmọye* àwọn áńgẹ́lì 23 tí wọ́n kóra jọ+ àti ìjọ àwọn àkọ́bí tí a ti kọ orúkọ wọn sílẹ̀ ní ọ̀run àti Ọlọ́run Onídàájọ́ gbogbo ẹ̀dá+ àti ìgbésí ayé àwọn olódodo nípa ti ẹ̀mí,+ àwọn tí a ti sọ di pípé+ 24 àti Jésù alárinà+ májẹ̀mú tuntun  + àti ẹ̀jẹ̀ tí a wọ́n, tó ń sọ̀rọ̀ lọ́nà tó dáa ju ẹ̀jẹ̀ Ébẹ́lì lọ.+

25 Ẹ rí i pé ẹ ò di etí yín sí* ẹni tó ń sọ̀rọ̀.* Torí tí àwọn tó kọ̀ láti fetí sí ẹni tó ń kéde ìkìlọ̀ Ọlọ́run ní ayé kò bá yè bọ́, báwo wá ni àwa ṣe lè yè bọ́ tí a bá yí pa dà kúrò lọ́dọ̀ ẹni tó ń sọ̀rọ̀ láti ọ̀run!+ 26 Nígbà yẹn, ohùn rẹ̀ mi ayé jìgìjìgì,+ àmọ́ ní báyìí, ó ti ṣèlérí pé: “Lẹ́ẹ̀kan sí i, kì í ṣe ayé nìkan ni màá mì jìgìjìgì, màá mi ọ̀run pẹ̀lú.”+ 27 Ọ̀rọ̀ náà “lẹ́ẹ̀kan sí i” tọ́ka sí i pé a máa mú àwọn ohun tí a mì kúrò, àwọn ohun tí a ti ṣe, kí àwọn ohun tí a ò mì lè dúró. 28 Torí náà, bí a ṣe rí i pé a máa tẹ́wọ́ gba Ìjọba kan tí kò ṣeé mì, ẹ jẹ́ ká túbọ̀ máa gba inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí, èyí tí a lè tipasẹ̀ rẹ̀ ṣe iṣẹ́ ìsìn mímọ́ tí Ọlọ́run máa tẹ́wọ́ gbà pẹ̀lú ìbẹ̀rù Ọlọ́run àti ọ̀wọ̀. 29 Torí Ọlọ́run wa jẹ́ iná tó ń jóni run.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́