ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Hébérù 13
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Hébérù

      • Ọ̀rọ̀ ìyànjú àti ìkíni tó fi parí ọ̀rọ̀ rẹ̀ (1-25)

        • Ẹ má gbàgbé láti máa ṣe aájò àlejò (2)

        • Kí ìgbéyàwó ní ọlá (4)

        • Ẹ máa ṣègbọràn sí àwọn tó ń mú ipò iwájú (7, 17)

        • Ẹ máa rú ẹbọ ìyìn (15, 16)

Hébérù 13:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Tẹ 4:9; 1Pe 1:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2016, ojú ìwé 4-5

    Ìwé Ọdọọdún—2016, ojú ìwé 2-3

    Ilé Ìṣọ́,

    8/1/1997, ojú ìwé 14-19

Hébérù 13:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ṣe inúure sí àwọn àjèjì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 12:13; 1Ti 3:2
  • +Jẹ 18:2, 3; 19:1-3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    10/2016, ojú ìwé 8-12

    1/2016, ojú ìwé 6

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2012, ojú ìwé 18-19

    10/1/1996, ojú ìwé 11-12

Hébérù 13:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “àwọn tí a dè; àwọn tó wà nínú ìdè.”

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “bí ẹni pé ẹ jọ ń jìyà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Kol 4:18
  • +Ro 12:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2016, ojú ìwé 6

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 29

Hébérù 13:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀, “Ìṣekúṣe.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 5:16, 20; Mt 5:28
  • +Owe 6:32; 1Kọ 6:9, 10, 18; Ga 5:19, 21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 41

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2018, ojú ìwé 10

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2016, ojú ìwé 6-7

    ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run’, ojú ìwé 123-132

    Jí!,

    5/8/2004, ojú ìwé 28

    1/8/2001, ojú ìwé 10

    Ìmọ̀, ojú ìwé 122

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    2/15/1993, ojú ìwé 12-17

Hébérù 13:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ti 6:10
  • +Owe 30:8, 9; 1Ti 6:8
  • +Di 31:6, 8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 37

    Jí!,

    No. 1 2021 ojú ìwé 8

    11/2015, ojú ìwé 5

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    11/2020, ojú ìwé 12

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2016, ojú ìwé 7

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2014, ojú ìwé 26

    10/1/2006, ojú ìwé 29

    10/15/2005, ojú ìwé 8-11

    6/1/2001, ojú ìwé 8

    9/1/1998, ojú ìwé 20-21

    8/15/1998, ojú ìwé 10-11

Hébérù 13:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 118:6; Da 3:17; Lk 12:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 59

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    11/2020, ojú ìwé 12-17

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2016, ojú ìwé 7

    Ilé Ìṣọ́,

    6/1/2001, ojú ìwé 8

Hébérù 13:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ti 5:17; Heb 13:17
  • +1Kọ 11:1; 2Tẹ 3:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    A Ṣètò Wa, ojú ìwé 17, 20-21, 22-23

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    2/2017, ojú ìwé 28

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2016, ojú ìwé 8

    Ilé Ìṣọ́,

    4/1/2007, ojú ìwé 28

    3/15/2002, ojú ìwé 17-18

    5/15/1998, ojú ìwé 11, 18

    1/15/1994, ojú ìwé 20

Hébérù 13:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, àwọn òfin nípa oúnjẹ.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 14:17; 1Kọ 8:8; Kol 2:16

Hébérù 13:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 9:13; 10:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2003, ojú ìwé 29-30

    7/1/1996, ojú ìwé 14-15

Hébérù 13:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 16:27

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 153-154

Hébérù 13:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “nítòsí ẹnubodè.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 19:17
  • +Heb 9:13, 14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 153-154

Hébérù 13:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 15:3; 2Kọ 12:10; 1Pe 4:14

Hébérù 13:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 11:10; 12:22

Hébérù 13:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 7:12; Sm 50:14, 23
  • +Sm 69:30, 31; Ho 14:2
  • +Ro 10:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/1/2007, ojú ìwé 20

    12/1/2003, ojú ìwé 17

    5/1/2003, ojú ìwé 28-29

    8/15/2000, ojú ìwé 20-21

    6/1/1993, ojú ìwé 11

    Ọjọ́ Jèhófà, ojú ìwé 167-168, 178

    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba,

    10/1995, ojú ìwé 1

    Yiyan, ojú ìwé 57-59

Hébérù 13:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 12:13
  • +Flp 4:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2012, ojú ìwé 24

    11/1/2005, ojú ìwé 7

    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba,

    4/2005, ojú ìwé 1

    Yiyan, ojú ìwé 57-59

Hébérù 13:17

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọkàn yín.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Tẹ 5:12
  • +Ef 5:21; 1Pe 5:5
  • +Iṣe 20:28

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run’, ojú ìwé 48-49

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2013, ojú ìwé 21-25

    6/15/2011, ojú ìwé 25-26

    4/1/2007, ojú ìwé 24, 28-30

    3/15/2002, ojú ìwé 15-17

    6/15/2001, ojú ìwé 20-21

    6/1/1999, ojú ìwé 17-18

    5/15/1998, ojú ìwé 18

    7/15/1993, ojú ìwé 25

    7/1/1992, ojú ìwé 15

    6/1/1992, ojú ìwé 17-18

Hébérù 13:18

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “aláìlábòsí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kọ 1:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 36

    Jí!,

    No. 1 2021 ojú ìwé 8

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde),

    No. 1 2016 ojú ìwé 6-7

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 207

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2005, ojú ìwé 28-29

    2/1/2004, ojú ìwé 32

Hébérù 13:19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 207

Hébérù 13:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Pe 5:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 9/2019, ojú ìwé 2

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2008, ojú ìwé 32

    4/15/1998, ojú ìwé 31

    2/15/1998, ojú ìwé 16

    2/1/1998, ojú ìwé 22-23

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 103, 104-105

Hébérù 13:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 27:1

Àwọn míì

Héb. 13:11Tẹ 4:9; 1Pe 1:22
Héb. 13:2Ro 12:13; 1Ti 3:2
Héb. 13:2Jẹ 18:2, 3; 19:1-3
Héb. 13:3Kol 4:18
Héb. 13:3Ro 12:15
Héb. 13:4Owe 5:16, 20; Mt 5:28
Héb. 13:4Owe 6:32; 1Kọ 6:9, 10, 18; Ga 5:19, 21
Héb. 13:51Ti 6:10
Héb. 13:5Owe 30:8, 9; 1Ti 6:8
Héb. 13:5Di 31:6, 8
Héb. 13:6Sm 118:6; Da 3:17; Lk 12:4
Héb. 13:71Ti 5:17; Heb 13:17
Héb. 13:71Kọ 11:1; 2Tẹ 3:7
Héb. 13:9Ro 14:17; 1Kọ 8:8; Kol 2:16
Héb. 13:101Kọ 9:13; 10:18
Héb. 13:11Le 16:27
Héb. 13:12Jo 19:17
Héb. 13:12Heb 9:13, 14
Héb. 13:13Ro 15:3; 2Kọ 12:10; 1Pe 4:14
Héb. 13:14Heb 11:10; 12:22
Héb. 13:15Le 7:12; Sm 50:14, 23
Héb. 13:15Sm 69:30, 31; Ho 14:2
Héb. 13:15Ro 10:9
Héb. 13:16Ro 12:13
Héb. 13:16Flp 4:18
Héb. 13:171Tẹ 5:12
Héb. 13:17Ef 5:21; 1Pe 5:5
Héb. 13:17Iṣe 20:28
Héb. 13:182Kọ 1:12
Héb. 13:201Pe 5:4
Héb. 13:24Iṣe 27:1
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Hébérù 13:1-25

Sí Àwọn Hébérù

13 Ẹ túbọ̀ máa ní ìfẹ́ ará.+ 2 Ẹ má gbàgbé láti máa ṣe aájò àlejò,*+ torí àwọn kan ti tipa bẹ́ẹ̀ ṣe àwọn áńgẹ́lì lálejò láìmọ̀.+ 3 Ẹ máa rántí àwọn tó wà nínú ẹ̀wọ̀n,*+ bí ẹni pé ẹ jọ wà lẹ́wọ̀n+ àti àwọn tí wọ́n ń fìyà jẹ, torí pé ẹ̀yin fúnra yín náà wà nínú ara.* 4 Kí ìgbéyàwó ní ọlá láàárín gbogbo èèyàn, kí ibùsùn ìgbéyàwó má sì ní ẹ̀gbin,+ torí Ọlọ́run máa dá àwọn oníṣekúṣe* àti àwọn alágbèrè lẹ́jọ́.+ 5 Ẹ yẹra fún ìfẹ́ owó nínú ìgbésí ayé yín,+ bí ẹ ṣe ń jẹ́ kí àwọn nǹkan tó wà báyìí tẹ́ yín lọ́rùn.+ Torí ó ti sọ pé: “Mi ò ní fi ọ́ sílẹ̀ láé, mi ò sì ní pa ọ́ tì láé.”+ 6 Ká lè nígboyà gidigidi, ká sì sọ pé: “Jèhófà* ni olùrànlọ́wọ́ mi; mi ò ní bẹ̀rù. Kí ni èèyàn lè fi mí ṣe?”+

7 Ẹ máa rántí àwọn tó ń mú ipò iwájú láàárín yín,+ tí wọ́n ti sọ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run fún yín, bí ẹ sì ṣe ń ṣàyẹ̀wò bí ìwà wọn ṣe rí, ẹ máa tẹ̀ lé àpẹẹrẹ ìgbàgbọ́ wọn.+

8 Ọ̀kan náà ni Jésù Kristi lánàá, lónìí àti títí láé.

9 Ẹ má ṣe jẹ́ kí wọ́n fi oríṣiríṣi ẹ̀kọ́ àtàwọn ẹ̀kọ́ tó ṣàjèjì ṣì yín lọ́nà, torí ó sàn kí inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí fún ọkàn lókun ju oúnjẹ* lọ, èyí tí kì í ṣàǹfààní fún àwọn tó gbà lọ́kàn.+

10 A ní pẹpẹ kan, tí àwọn tó ń ṣe iṣẹ́ ìsìn mímọ́ níbi àgọ́ kò láṣẹ láti jẹ níbẹ̀.+ 11 Torí wọ́n máa ń sun ara àwọn ẹran tí àlùfáà àgbà máa ń mú ẹ̀jẹ̀ wọn wọnú ibi mímọ́ láti fi rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ lẹ́yìn ibùdó.+ 12 Torí náà, Jésù náà jìyà lẹ́yìn odi* ìlú+ kó lè fi ẹ̀jẹ̀ ara rẹ̀ sọ àwọn èèyàn di mímọ́.+ 13 Tó bá rí bẹ́ẹ̀, ẹ jẹ́ ká lọ bá a lẹ́yìn ibùdó, ká ru ẹ̀gàn tó rù,+ 14 torí a ò ní ìlú kan níbí tó ṣì máa wà, àmọ́ à ń fi gbogbo ọkàn wá èyí tó ń bọ̀.+ 15 Ẹ jẹ́ ká máa rú ẹbọ ìyìn sí Ọlọ́run nípasẹ̀ rẹ̀ nígbà gbogbo,+ ìyẹn èso ètè wa+ tó ń kéde orúkọ rẹ̀ ní gbangba.+ 16 Bákan náà, ẹ má gbàgbé láti máa ṣe rere, kí ẹ sì máa pín ohun tí ẹ ní pẹ̀lú àwọn ẹlòmíì,+ torí inú Ọlọ́run máa ń dùn gan-an sí irú àwọn ẹbọ bẹ́ẹ̀.+

17 Ẹ máa ṣègbọràn sí àwọn tó ń mú ipò iwájú láàárín yín,+ kí ẹ sì máa tẹrí ba,+ torí wọ́n ń ṣọ́ ẹ̀ṣọ́ lórí yín* bí àwọn tó máa jíhìn,+ kí wọ́n lè ṣe é tayọ̀tayọ̀, kì í ṣe pẹ̀lú ẹ̀dùn ọkàn, torí èyí máa pa yín lára.

18 Ẹ túbọ̀ máa gbàdúrà fún wa, torí ó dá wa lójú pé a ní ẹ̀rí ọkàn rere,* bó ṣe ń wù wá láti jẹ́ olóòótọ́ nínú ohun gbogbo.+ 19 Àmọ́ ní pàtàkì, mo rọ̀ yín pé kí ẹ máa gbàdúrà, kí n lè tètè pa dà sọ́dọ̀ yín.

20 Kí Ọlọ́run àlàáfíà, tó jí Jésù Olúwa wa dìde, olùṣọ́ àgùntàn ńlá+ fún àwọn àgùntàn, pẹ̀lú ẹ̀jẹ̀ májẹ̀mú àìnípẹ̀kun, 21 fi gbogbo ohun rere mú yín gbára dì láti ṣe ìfẹ́ rẹ̀, kí ó máa ṣe ohun tó dáa gan-an nínú wa lójú rẹ̀ nípasẹ̀ Jésù Kristi, ẹni tí ògo jẹ́ tiẹ̀ títí láé àti láéláé. Àmín.

22 Ẹ̀yin ará, mò ń rọ̀ yín pé kí ẹ fara balẹ̀ tẹ́tí sí ọ̀rọ̀ ìṣírí yìí, torí lẹ́tà kúkúrú ni mo kọ sí yín. 23 Mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ pé wọ́n ti tú Tímótì arákùnrin wa sílẹ̀. Tó bá tètè dé, a jọ máa wá nígbà tí mo bá fẹ́ wá rí yín.

24 Ẹ bá mi kí gbogbo àwọn tó ń mú ipò iwájú láàárín yín àti gbogbo àwọn ẹni mímọ́. Àwọn tó wà ní Ítálì+ kí yín.

25 Kí inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí wà pẹ̀lú gbogbo yín.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́