ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Jòhánù 2
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Jòhánù

      • Ó fi Jésù ṣe ẹbọ ìpẹ̀tù (1, 2)

      • Ká máa pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́ (3-11)

        • Àṣẹ àtijọ́ àti àṣẹ tuntun (7, 8)

      • Ìdí tó fi kọ̀wé sí wọn (12-14)

      • Ẹ má ṣe nífẹ̀ẹ́ ayé (15-17)

      • Ìkìlọ̀ nípa aṣòdì sí Kristi (18-29)

1 Jòhánù 2:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “agbẹnusọ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 8:34; Heb 7:25
  • +1Ti 2:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 27

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 159-160

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2004, ojú ìwé 19

    3/15/2000, ojú ìwé 3-4, 5-9

    10/1/1993, ojú ìwé 23

    3/1/1991, ojú ìwé 27

1 Jòhánù 2:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ètùtù; ohun tí a fi ń tuni lójú.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 5:7
  • +Ais 53:5; Ro 3:25; 1Ti 1:15; Heb 2:17; 1Pe 2:24; 1Jo 4:10
  • +Mt 20:28; Jo 1:29

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/1/2009, ojú ìwé 11-12

    12/15/2008, ojú ìwé 27

    4/15/1991, ojú ìwé 29

1 Jòhánù 2:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Jo 4:18
  • +Jo 14:20; 17:21

1 Jòhánù 2:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 13:15; 1Pe 2:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/15/2005, ojú ìwé 21-25

1 Jòhánù 2:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 13:34; 2Jo 5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/15/2013, ojú ìwé 10

    8/1/2011, ojú ìwé 29-30

    12/15/2008, ojú ìwé 27

1 Jòhánù 2:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 1:9; 8:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2008, ojú ìwé 27

1 Jòhánù 2:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ef 4:31; Kol 3:8
  • +1Kọ 13:2; 1Jo 3:15

1 Jòhánù 2:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ef 5:8

1 Jòhánù 2:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Jo 4:20
  • +Jo 12:35

1 Jòhánù 2:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Lk 24:47; Iṣe 4:12; 10:43

1 Jòhánù 2:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jem 4:7; 1Jo 5:19; Ifi 12:10, 11
  • +Jo 17:25

1 Jòhánù 2:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ef 6:10
  • +3Jo 3
  • +Ro 8:37

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2003, ojú ìwé 8

1 Jòhánù 2:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 12:2; 1Kọ 7:31; Tit 2:11, 12
  • +Mt 6:24; Jem 4:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 52

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2013, ojú ìwé 24-27

    1/15/2010, ojú ìwé 14-15

    1/15/2006, ojú ìwé 24-25

    1/1/2005, ojú ìwé 10

    3/1/2002, ojú ìwé 14-15

    10/1/1991, ojú ìwé 21

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 258

1 Jòhánù 2:16

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “fífi ohun téèyàn ní fọ́nnu.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 5:28; Ro 13:14
  • +Jẹ 3:6; Owe 27:20; Mt 4:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    7/2020, ojú ìwé 6-7

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2013, ojú ìwé 24-27

    1/15/2006, ojú ìwé 24-25

    1/1/2005, ojú ìwé 10

    8/15/2002, ojú ìwé 23-24

    3/1/2002, ojú ìwé 14-15

    10/1/1991, ojú ìwé 21

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 258

1 Jòhánù 2:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 7:31; 1Pe 1:24
  • +Sm 37:29; Mt 7:21; Jo 6:40

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    4/2017, ojú ìwé 9-13

    Jí!,

    No. 1 2016 ojú ìwé 7

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2013, ojú ìwé 27

    1/1/2013, ojú ìwé 5-6

    8/15/2005, ojú ìwé 28-29

1 Jòhánù 2:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Tẹ 2:3; 2Pe 2:1
  • +2Tẹ 2:7; 2Jo 7; Jud 4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    6/1/2015, ojú ìwé 14

1 Jòhánù 2:19

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “wọn kì í ṣe tiwa.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 20:30
  • +1Kọ 11:19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    6/1/2015, ojú ìwé 14

1 Jòhánù 2:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kọ 1:21; 1Jo 2:27

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2020, ojú ìwé 22

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2016, ojú ìwé 17

1 Jòhánù 2:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 8:31, 32
  • +Jo 8:44

1 Jòhánù 2:22

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Jo 4:3; 2Jo 7
  • +1Jo 2:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    6/1/2015, ojú ìwé 14

    Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, ojú ìwé 1696

1 Jòhánù 2:23

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 5:23; 2Jo 9
  • +Ro 10:9, 10
  • +1Jo 4:15

1 Jòhánù 2:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 14:23; 2Jo 6

1 Jòhánù 2:25

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 17:3; 1Jo 1:2

1 Jòhánù 2:27

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kọ 1:21; 1Jo 2:20
  • +Jo 14:26; 16:13
  • +Jo 17:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2020, ojú ìwé 22

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2016, ojú ìwé 17

1 Jòhánù 2:28

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Jo 4:17

1 Jòhánù 2:29

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Pe 1:23; 1Jo 4:7

Àwọn míì

1 Jòh. 2:1Ro 8:34; Heb 7:25
1 Jòh. 2:11Ti 2:5
1 Jòh. 2:21Kọ 5:7
1 Jòh. 2:2Ais 53:5; Ro 3:25; 1Ti 1:15; Heb 2:17; 1Pe 2:24; 1Jo 4:10
1 Jòh. 2:2Mt 20:28; Jo 1:29
1 Jòh. 2:51Jo 4:18
1 Jòh. 2:5Jo 14:20; 17:21
1 Jòh. 2:6Jo 13:15; 1Pe 2:21
1 Jòh. 2:7Jo 13:34; 2Jo 5
1 Jòh. 2:8Jo 1:9; 8:12
1 Jòh. 2:9Ef 4:31; Kol 3:8
1 Jòh. 2:91Kọ 13:2; 1Jo 3:15
1 Jòh. 2:10Ef 5:8
1 Jòh. 2:111Jo 4:20
1 Jòh. 2:11Jo 12:35
1 Jòh. 2:12Lk 24:47; Iṣe 4:12; 10:43
1 Jòh. 2:13Jem 4:7; 1Jo 5:19; Ifi 12:10, 11
1 Jòh. 2:13Jo 17:25
1 Jòh. 2:14Ef 6:10
1 Jòh. 2:143Jo 3
1 Jòh. 2:14Ro 8:37
1 Jòh. 2:15Ro 12:2; 1Kọ 7:31; Tit 2:11, 12
1 Jòh. 2:15Mt 6:24; Jem 4:4
1 Jòh. 2:16Mt 5:28; Ro 13:14
1 Jòh. 2:16Jẹ 3:6; Owe 27:20; Mt 4:8
1 Jòh. 2:171Kọ 7:31; 1Pe 1:24
1 Jòh. 2:17Sm 37:29; Mt 7:21; Jo 6:40
1 Jòh. 2:182Tẹ 2:3; 2Pe 2:1
1 Jòh. 2:182Tẹ 2:7; 2Jo 7; Jud 4
1 Jòh. 2:19Iṣe 20:30
1 Jòh. 2:191Kọ 11:19
1 Jòh. 2:202Kọ 1:21; 1Jo 2:27
1 Jòh. 2:21Jo 8:31, 32
1 Jòh. 2:21Jo 8:44
1 Jòh. 2:221Jo 4:3; 2Jo 7
1 Jòh. 2:221Jo 2:18
1 Jòh. 2:23Jo 5:23; 2Jo 9
1 Jòh. 2:23Ro 10:9, 10
1 Jòh. 2:231Jo 4:15
1 Jòh. 2:24Jo 14:23; 2Jo 6
1 Jòh. 2:25Jo 17:3; 1Jo 1:2
1 Jòh. 2:272Kọ 1:21; 1Jo 2:20
1 Jòh. 2:27Jo 14:26; 16:13
1 Jòh. 2:27Jo 17:21
1 Jòh. 2:281Jo 4:17
1 Jòh. 2:291Pe 1:23; 1Jo 4:7
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
  • 28
  • 29
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
1 Jòhánù 2:1-29

Ìwé Kìíní Jòhánù

2 Ẹ̀yin ọmọ mi kéékèèké, mò ń kọ àwọn nǹkan yìí sí yín kí ẹ má bàa dẹ́ṣẹ̀. Síbẹ̀, tí ẹnikẹ́ni bá dẹ́ṣẹ̀, a ní olùrànlọ́wọ́* lọ́dọ̀ Baba, Jésù Kristi,+ ẹni tó jẹ́ olódodo.+ 2 Òun sì ni ẹbọ ìpẹ̀tù*+ fún àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa,+ síbẹ̀ kì í ṣe fún ẹ̀ṣẹ̀ tiwa nìkan, àmọ́ fún gbogbo ayé pẹ̀lú.+ 3 Tí a bá ń pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́, èyí á jẹ́ ká mọ̀ pé a ti wá mọ̀ ọ́n. 4 Òpùrọ́ ni ẹni tó bá sọ pé, “Mo ti wá mọ̀ ọ́n,” síbẹ̀ tí kò pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́, òótọ́ ò sí nínú ẹni náà. 5 Àmọ́ ẹnikẹ́ni tó bá ń pa ọ̀rọ̀ rẹ̀ mọ́, ó dájú pé ìfẹ́ Ọlọ́run ti di pípé nínú ẹni náà.+ Èyí la fi mọ̀ pé a wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú rẹ̀.+ 6 Ẹni tó bá sọ pé òun wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú rẹ̀, òun fúnra rẹ̀ gbọ́dọ̀ máa rìn bí ẹni yẹn ṣe rìn.+

7 Ẹ̀yin ẹni ọ̀wọ́n, àṣẹ tí mò ń kọ̀wé rẹ̀ sí yín kì í ṣe tuntun, àmọ́ ó jẹ́ àṣẹ àtijọ́ tí ẹ ti ní láti ìbẹ̀rẹ̀.+ Àṣẹ àtijọ́ yìí ni ọ̀rọ̀ tí ẹ gbọ́. 8 Síbẹ̀, àṣẹ tuntun ni mò ń kọ̀wé rẹ̀ sí yín, ó jẹ́ òótọ́ nínú ọ̀rọ̀ tirẹ̀ àti nínú tiyín, torí òkùnkùn ń kọjá lọ, ìmọ́lẹ̀ tòótọ́ sì ti tàn báyìí.+

9 Ẹni tó bá sọ pé òun wà nínú ìmọ́lẹ̀, síbẹ̀ tó kórìíra+ arákùnrin rẹ̀, inú òkùnkùn ló ṣì wà.+ 10 Ẹni tó nífẹ̀ẹ́ arákùnrin rẹ̀ wà nínú ìmọ́lẹ̀,+ kò sì sí ohun tó lè fa ìkọ̀sẹ̀ nínú rẹ̀. 11 Àmọ́ ẹni tó bá kórìíra arákùnrin rẹ̀ wà nínú òkùnkùn, ó ń rìn nínú òkùnkùn,+ kò sì mọ ibi tó ń lọ,+ torí òkùnkùn ò jẹ́ kó ríran.

12 Ẹ̀yin ọmọ kéékèèké, mò ń kọ̀wé sí yín torí a ti dárí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ yín jì yín nítorí orúkọ rẹ̀.+ 13 Mò ń kọ̀wé sí ẹ̀yin bàbá, torí ẹ ti wá mọ ẹni tó wà láti ìbẹ̀rẹ̀. Mò ń kọ̀wé sí ẹ̀yin ọ̀dọ́kùnrin, torí ẹ ti ṣẹ́gun ẹni burúkú náà.+ Mo kọ̀wé sí ẹ̀yin ọmọdé, torí ẹ ti wá mọ Baba.+ 14 Mo kọ̀wé sí ẹ̀yin bàbá, torí ẹ ti wá mọ ẹni tó wà láti ìbẹ̀rẹ̀. Mo kọ̀wé sí ẹ̀yin ọ̀dọ́kùnrin, torí ẹ jẹ́ alágbára,+ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run wà nínú yín,+ ẹ sì ti ṣẹ́gun ẹni burúkú náà.+

15 Ẹ má ṣe nífẹ̀ẹ́ ayé tàbí àwọn nǹkan tó wà nínú ayé.+ Tí ẹnikẹ́ni bá nífẹ̀ẹ́ ayé, kò ní ìfẹ́ Baba;+ 16 torí gbogbo ohun tó wà nínú ayé—ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ara,+ ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ojú+ àti fífi ohun ìní ẹni ṣe àṣehàn*—kò wá látọ̀dọ̀ Baba, àmọ́ ó wá látọ̀dọ̀ ayé. 17 Bákan náà, ayé ń kọjá lọ àti ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ rẹ̀,+ ṣùgbọ́n ẹni tó bá ń ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run ló máa wà títí láé.+

18 Ẹ̀yin ọmọdé, wákàtí ìkẹyìn nìyí, bí ẹ sì ṣe gbọ́ pé aṣòdì sí Kristi ń bọ̀,+ kódà ọ̀pọ̀ aṣòdì sí Kristi ló ti fara hàn báyìí,+ ìyẹn sì jẹ́ ká mọ̀ pé wákàtí ìkẹyìn nìyí lóòótọ́. 19 Wọ́n kúrò lọ́dọ̀ wa, àmọ́ wọn kì í ṣe ara wa;*+ torí ká ní wọ́n jẹ́ ara wa ni, wọn ò ní fi wá sílẹ̀. Ṣùgbọ́n wọ́n kúrò lọ́dọ̀ wa kó lè hàn pé kì í ṣe gbogbo èèyàn ló jẹ́ ara wa.+ 20 Ẹni mímọ́ ti yàn yín,+ gbogbo yín sì ní ìmọ̀. 21 Kì í ṣe torí pé ẹ ò mọ òótọ́+ ni mo ṣe kọ̀wé sí yín, àmọ́ torí pé ẹ mọ̀ ọ́n àti pé kò sí irọ́ kankan nínú òótọ́.+

22 Ta ni òpùrọ́ tí kì í bá ṣe ẹni tó sọ pé Jésù kọ́ ni Kristi?+ Ẹni yìí ni aṣòdì sí Kristi,+ ẹni tó sẹ́ Baba àti Ọmọ. 23 Ẹnikẹ́ni tó bá sẹ́ Ọmọ kò ní Baba.+ Ẹnikẹ́ni tó bá sọ pé òun mọ Ọmọ+ ní Baba pẹ̀lú.+ 24 Ní tiyín, àwọn nǹkan tí ẹ ti gbọ́ láti ìbẹ̀rẹ̀ kò gbọ́dọ̀ kúrò nínú yín.+ Tí àwọn nǹkan tí ẹ ti gbọ́ láti ìbẹ̀rẹ̀ kò bá kúrò nínú yín, ẹ̀yin àti Ọmọ máa wà ní ìṣọ̀kan, ẹ sì máa wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Baba. 25 Bákan náà, ohun tí òun fúnra rẹ̀ ṣèlérí fún wa ni ìyè àìnípẹ̀kun.+

26 Torí àwọn tó fẹ́ ṣì yín lọ́nà ni mo ṣe kọ àwọn nǹkan yìí sí yín. 27 Ní tiyín, yíyàn tó yàn yín+ kò kúrò nínú yín, ẹ ò sì nílò kí ẹnikẹ́ni máa kọ́ yín; àmọ́, yíyàn tó yàn yín ń kọ́ yín ní ohun gbogbo,+ òótọ́ ni, kì í ṣe irọ́. Kí ẹ wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú rẹ̀ bó ṣe kọ́ yín gẹ́lẹ́.+ 28 Torí náà, ẹ̀yin ọmọ kéékèèké, ẹ wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú rẹ̀, ká lè sọ̀rọ̀ ní fàlàlà  + nígbà tí a bá fi í hàn kedere, kí a má bàa fi ìtìjú kúrò lọ́dọ̀ rẹ̀ nígbà tó bá wà níhìn-ín. 29 Tí ẹ bá mọ̀ pé olódodo ni, ẹ tún máa mọ̀ pé gbogbo ẹni tó bá ń fi òdodo ṣe ìwà hù ni a bí látọ̀dọ̀ rẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́