ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 9
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Ìmọ́lẹ̀ tó tàn yòò fún ilẹ̀ Gálílì (1-7)

        • A bí “Ọmọ Aládé Àlàáfíà” (6-7)

      • Ọwọ́ Ọlọ́run máa kọ lu Ísírẹ́lì (8-21)

Àìsáyà 9:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 15:29

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    12/2016, ojú ìwé 4

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 59, 161

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2011, ojú ìwé 10-11

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 124-126

Àìsáyà 9:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 4:13-16; Lk 1:78, 79; 2:30-32; Jo 1:9; 8:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    12/2016, ojú ìwé 4

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 59, 161

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2011, ojú ìwé 10-11

    4/1/1993, ojú ìwé 10-11

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 125-128

Àìsáyà 9:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2001, ojú ìwé 14-15

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 128

Àìsáyà 9:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ond 8:12, 28; Ais 10:26, 27

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 128-129

Àìsáyà 9:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 129

Àìsáyà 9:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ìjọba; Ìṣàkóso ọmọ aládé.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Lk 1:35; 2:11
  • +Jẹ 49:10; Sm 2:6; Sek 6:13; Lk 22:29; Ifi 19:16
  • +Ais 11:2; Mt 7:28, 29; 12:42
  • +Sm 45:3; Jo 1:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2014, ojú ìwé 12

    10/1/2010, ojú ìwé 24

    5/15/2007, ojú ìwé 6

    4/1/1992, ojú ìwé 26

    1/15/1992, ojú ìwé 22

    4/15/1991, ojú ìwé 5-6

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 211-213

    “Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn,” ojú ìwé 23, 189

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 129-132

    Mẹtalọkan, ojú ìwé 28

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 13-14, 162-169, 173-179

    “Kí Ijọba Rẹ Dé,” ojú ìwé 21-22

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 124

Àìsáyà 9:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ìjọba; Ìṣàkóso ọmọ aládé.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 72:1, 7; Da 2:44
  • +Lk 1:32, 33
  • +2Sa 7:16, 17; Ifi 11:15
  • +Ais 42:1; Mt 12:18
  • +Sm 45:6; Ais 32:1; Jer 23:5; Heb 1:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2006, ojú ìwé 4-5

    4/15/1991, ojú ìwé 5-6

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 132

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 13-14

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 124

Àìsáyà 9:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 17:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 133-134

Àìsáyà 9:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 134-135

Àìsáyà 9:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Emọ 5:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 135

Àìsáyà 9:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 135-136

Àìsáyà 9:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “láti ẹ̀yìn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 28:18
  • +Di 31:17
  • +Ais 5:25; 10:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 134, 136-137

Àìsáyà 9:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 17:13, 14; Ho 7:10; Emọ 4:6; 5:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 137

Àìsáyà 9:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “imọ̀ ọ̀pẹ àti koríko etí omi.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 17:6; Ho 10:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 137-138

Àìsáyà 9:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 13:1-3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 137-138

Àìsáyà 9:17

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “aláìlóbìí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 4:25, 26
  • +Ais 5:25

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 134, 138

Àìsáyà 9:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 139-140

Àìsáyà 9:19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 139-140

Àìsáyà 9:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 139-140

Àìsáyà 9:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 28:6
  • +Ais 5:25

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 134, 139-140

Àwọn míì

Àìsá. 9:12Ọb 15:29
Àìsá. 9:2Mt 4:13-16; Lk 1:78, 79; 2:30-32; Jo 1:9; 8:12
Àìsá. 9:4Ond 8:12, 28; Ais 10:26, 27
Àìsá. 9:6Lk 1:35; 2:11
Àìsá. 9:6Jẹ 49:10; Sm 2:6; Sek 6:13; Lk 22:29; Ifi 19:16
Àìsá. 9:6Ais 11:2; Mt 7:28, 29; 12:42
Àìsá. 9:6Sm 45:3; Jo 1:18
Àìsá. 9:7Sm 72:1, 7; Da 2:44
Àìsá. 9:7Lk 1:32, 33
Àìsá. 9:72Sa 7:16, 17; Ifi 11:15
Àìsá. 9:7Ais 42:1; Mt 12:18
Àìsá. 9:7Sm 45:6; Ais 32:1; Jer 23:5; Heb 1:8
Àìsá. 9:82Ọb 17:6
Àìsá. 9:10Emọ 5:11
Àìsá. 9:122Kr 28:18
Àìsá. 9:12Di 31:17
Àìsá. 9:12Ais 5:25; 10:4
Àìsá. 9:132Ọb 17:13, 14; Ho 7:10; Emọ 4:6; 5:6
Àìsá. 9:142Ọb 17:6; Ho 10:15
Àìsá. 9:15Di 13:1-3
Àìsá. 9:17Di 4:25, 26
Àìsá. 9:17Ais 5:25
Àìsá. 9:212Kr 28:6
Àìsá. 9:21Ais 5:25
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 9:1-21

Àìsáyà

9 Àmọ́, ìṣúdùdù náà kò ní rí bí ìgbà tí ìdààmú bá ilẹ̀ náà, bí ìgbà àtijọ́ tí wọ́n hùwà àbùkù sí ilẹ̀ Sébúlúnì àti ilẹ̀ Náfútálì.+ Àmọ́ tó bá yá, Ó máa mú kí a bọlá fún un, ní ọ̀nà ibi òkun, ní agbègbè Jọ́dánì, Gálílì àwọn orílẹ̀-èdè.

 2 Àwọn èèyàn tó ń rìn nínú òkùnkùn

Ti rí ìmọ́lẹ̀ tó mọ́lẹ̀ yòò.

Ní ti àwọn tó ń gbé ilẹ̀ tó ṣókùnkùn biribiri,

Ìmọ́lẹ̀ ti tàn sórí wọn.+

 3 O ti sọ orílẹ̀-èdè náà di púpọ̀;

O ti mú kó máa yọ̀ gidigidi.

Wọ́n ń yọ̀ níwájú rẹ

Bí àwọn èèyàn ṣe ń yọ̀ nígbà ìkórè,

Bí àwọn tó ń fayọ̀ pín ẹrù ogun.

 4 Torí o ti fọ́ àjàgà ẹrù wọn sí wẹ́wẹ́,

Ọ̀pá tó wà ní èjìká wọn, ọ̀pá ẹni tó ń kó wọn ṣiṣẹ́,

Bíi ti ọjọ́ Mídíánì.+

 5 Gbogbo bàtà tó ń kilẹ̀ bó ṣe ń lọ

Àti gbogbo aṣọ tí wọ́n rì bọnú ẹ̀jẹ̀

Ló máa di ohun tí wọ́n fi ń dá iná.

 6 Torí a ti bí ọmọ kan fún wa,+

A ti fún wa ní ọmọkùnrin kan;

Àkóso* sì máa wà ní èjìká rẹ̀.+

Orúkọ rẹ̀ á máa jẹ́ Àgbàyanu Agbani-nímọ̀ràn,+ Ọlọ́run Alágbára,+ Baba Ayérayé, Ọmọ Aládé Àlàáfíà.

 7 Àkóso* rẹ̀ á máa gbilẹ̀ títí lọ,

Àlàáfíà kò sì ní lópin,+

Lórí ìtẹ́ Dáfídì+ àti lórí ìjọba rẹ̀,

Kó lè fìdí rẹ̀ múlẹ̀ gbọn-in,+ kó sì gbé e ró,

Nípasẹ̀ ìdájọ́+ tí ó tọ́ àti òdodo,+

Láti ìsinsìnyí lọ àti títí láé.

Ìtara Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun máa ṣe èyí.

 8 Jèhófà fi ọ̀rọ̀ kan ránṣẹ́ sí Jékọ́bù,

Ó sì ti wá sórí Ísírẹ́lì.+

 9 Gbogbo èèyàn sì máa mọ̀ ọ́n,

Éfúrémù àti àwọn tó ń gbé ní Samáríà,

Tí wọ́n ń fi ìgbéraga àti àfojúdi ọkàn sọ pé:

10 “Àwọn bíríkì ti wó,

Àmọ́ òkúta tí wọ́n gbẹ́ la máa fi kọ́lé.+

Wọ́n ti gé àwọn igi síkámórè lulẹ̀,

Àmọ́ á máa fi àwọn igi kédárì rọ́pò wọn.”

11 Jèhófà máa gbé àwọn elénìní Résínì dìde sí i,

Ó sì máa ru àwọn ọ̀tá rẹ̀ sókè láti jagun,

12 Síríà láti ìlà oòrùn àti àwọn Filísínì láti ìwọ̀ oòrùn,*+

Wọ́n máa la ẹnu wọn, wọ́n á sì jẹ Ísírẹ́lì run.+

Pẹ̀lú gbogbo èyí, ìbínú rẹ̀ kò tíì yí pa dà,

Àmọ́ ó ṣì na ọwọ́ rẹ̀ jáde láti lù wọ́n.+

13 Torí àwọn èèyàn náà kò tíì pa dà sọ́dọ̀ Ẹni tó ń lù wọ́n;

Wọn ò wá Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun.+

14 Jèhófà máa gé orí àti ìrù, ọ̀mùnú àti koríko etídò*

Kúrò ní Ísírẹ́lì, ní ọjọ́ kan ṣoṣo.+

15 Àgbà ọkùnrin àti ẹni tí àwọn èèyàn bọ̀wọ̀ fún gidigidi ni orí,

Wòlíì tó ń fúnni ní ìtọ́ni èké sì ni ìrù.+

16 Àwọn tó ń darí àwọn èèyàn yìí ń mú kí wọ́n rìn gbéregbère,

Nǹkan sì ti dà rú mọ́ àwọn tó ń tẹ̀ lé wọn lójú.

17 Ìdí nìyẹn tí inú Jèhófà ò fi ní dùn sí àwọn ọ̀dọ́kùnrin wọn,

Kò sì ní ṣàánú àwọn ọmọ aláìníbaba* àti àwọn opó wọn

Torí apẹ̀yìndà àti aṣebi ni gbogbo wọn,+

Gbogbo ẹnu sì ń sọ ọ̀rọ̀ òpònú.

Pẹ̀lú gbogbo èyí, ìbínú rẹ̀ kò tíì yí pa dà,

Àmọ́ ó ṣì na ọwọ́ rẹ̀ jáde láti lù wọ́n.+

18 Torí pé ìwà burúkú máa ń jó bí iná,

Ó ń jó àwọn igi ẹlẹ́gùn-ún àti èpò run.

Ó máa dáná sí igbó tó díjú,

Èéfín wọn tó ṣú sì máa ròkè lálá.

19 Torí ìbínú Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun,

A ti dáná sí ilẹ̀ náà,

Wọ́n á sì fi àwọn èèyàn náà dáná.

Ẹnì kankan ò ní dá ẹ̀mí arákùnrin rẹ̀ pàápàá sí.

20 Ẹnì kan máa gé nǹkan lulẹ̀ ní ọwọ́ ọ̀tún,

Àmọ́ ebi á ṣì máa pa á;

Ẹnì kan sì máa jẹun ní ọwọ́ òsì,

Àmọ́ kò ní yó.

Kálukú máa jẹ ẹran apá rẹ̀,

21 Mánásè máa jẹ Éfúrémù run,

Éfúrémù sì máa jẹ Mánásè run.

Wọ́n máa para pọ̀ gbéjà ko Júdà.+

Pẹ̀lú gbogbo èyí, ìbínú rẹ̀ kò tíì yí pa dà,

Àmọ́ ó ṣì na ọwọ́ rẹ̀ jáde láti lù wọ́n.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́