ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 14
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Ísírẹ́lì máa gbé ní ilẹ̀ tirẹ̀ (1, 2)

      • Wọ́n fi ọba Bábílónì ṣe ẹlẹ́yà (3-23)

        • Ẹni tó ń tàn máa já bọ́ láti ọ̀run (12)

      • Ọwọ́ Jèhófà máa fọ́ ará Ásíríà túútúú (24-27)

      • Ọ̀rọ̀ ìkéde sí Filísíà (28-32)

Àìsáyà 14:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “fún wọn ní ìsinmi.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 26:42
  • +Sek 1:17
  • +Di 30:1-3; Ais 66:20; Jer 24:6; Isk 36:24
  • +Ais 56:6, 7; 60:3; Sek 8:22, 23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 181-182

Àìsáyà 14:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 61:5; Sek 2:8, 9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/1/2006, ojú ìwé 11

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 181-182

Àìsáyà 14:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹsr 3:1; 9:8; Jer 30:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 182

Àìsáyà 14:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “sọ̀rọ̀ ẹ̀gàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 50:23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/15/2002, ojú ìwé 30

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 183

Àìsáyà 14:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 125:3

Àìsáyà 14:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 36:17; Jer 50:17
  • +Hab 1:6; Sek 1:15

Àìsáyà 14:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 126:2; Ais 49:13; Jer 51:48; Ifi 18:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 183

Àìsáyà 14:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 183

Àìsáyà 14:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ṣìọ́ọ̀lù,” ìyẹn ibojì aráyé. Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

  • *

    Tàbí “ti sọ di aláìlágbára.”

  • *

    Ní Héb., “àwọn òbúkọ ayé.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 183-184

Àìsáyà 14:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 183-184

Àìsáyà 14:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ṣìọ́ọ̀lù,” ìyẹn ibojì aráyé. Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ifi 18:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 183-184

Àìsáyà 14:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 36:17; Jer 51:7; Isk 29:19; Da 5:18, 19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 136-137

    Ilé Ìṣọ́,

    9/15/2002, ojú ìwé 30

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 184

Àìsáyà 14:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 47:7; Da 4:30
  • +Da 5:22, 23
  • +Sm 48:1, 2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2006, ojú ìwé 26

    9/15/2002, ojú ìwé 30

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 184-185

Àìsáyà 14:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìkùukùu.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2006, ojú ìwé 26

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 184-185

Àìsáyà 14:15

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ṣìọ́ọ̀lù,” ìyẹn ibojì aráyé. Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 185

Àìsáyà 14:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 51:25

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 185-187

Àìsáyà 14:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 25:21; Ais 64:10
  • +2Ọb 24:12, 14; 25:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 185-187

Àìsáyà 14:18

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ilé.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 185-187

Àìsáyà 14:19

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ẹ̀ka.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 185-187

Àìsáyà 14:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 185-187

Àìsáyà 14:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 187

Àìsáyà 14:22

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 43:14; Jer 50:25; 51:56
  • +Jer 51:62

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 188

    Ìwé fún Gbogbo Ènìyàn, ojú ìwé 27-29

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    5/15/1993, ojú ìwé 6

Àìsáyà 14:23

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 13:1, 21; Jer 50:35, 39; Ifi 18:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 188

    Ìwé fún Gbogbo Ènìyàn, ojú ìwé 27-29

Àìsáyà 14:24

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 17-18

Àìsáyà 14:25

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 32:21, 22; Ais 30:31; 31:8; 37:36, 37
  • +Ais 10:24

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 189

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 15-17

Àìsáyà 14:26

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “Ìmọ̀ràn tí a gbà.”

  • *

    Tàbí “tó ṣe tán láti kọ lu.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 189-190

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 17-18

Àìsáyà 14:27

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 33:11; Owe 19:21; 21:30; Ais 46:11
  • +2Kr 20:5, 6; Ais 43:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 189-190

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 17-18

Àìsáyà 14:28

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 16:20; 2Kr 28:27

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 190-191

Àìsáyà 14:29

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ejò olóró tó ń yára kánkán.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 18:1, 8
  • +2Kr 26:3, 6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 190-191

Àìsáyà 14:30

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 47:1; Isk 25:16; Joẹ 3:4; Emọ 1:6-8; Sef 2:4; Sek 9:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 191-192

Àìsáyà 14:32

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 48:1-3; 87:1, 2; 132:13, 14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 191

Àwọn míì

Àìsá. 14:1Le 26:42
Àìsá. 14:1Sek 1:17
Àìsá. 14:1Di 30:1-3; Ais 66:20; Jer 24:6; Isk 36:24
Àìsá. 14:1Ais 56:6, 7; 60:3; Sek 8:22, 23
Àìsá. 14:2Ais 61:5; Sek 2:8, 9
Àìsá. 14:3Ẹsr 3:1; 9:8; Jer 30:10
Àìsá. 14:4Jer 50:23
Àìsá. 14:5Sm 125:3
Àìsá. 14:62Kr 36:17; Jer 50:17
Àìsá. 14:6Hab 1:6; Sek 1:15
Àìsá. 14:7Sm 126:2; Ais 49:13; Jer 51:48; Ifi 18:20
Àìsá. 14:11Ifi 18:22
Àìsá. 14:122Kr 36:17; Jer 51:7; Isk 29:19; Da 5:18, 19
Àìsá. 14:13Ais 47:7; Da 4:30
Àìsá. 14:13Da 5:22, 23
Àìsá. 14:13Sm 48:1, 2
Àìsá. 14:16Jer 51:25
Àìsá. 14:172Ọb 25:21; Ais 64:10
Àìsá. 14:172Ọb 24:12, 14; 25:11
Àìsá. 14:22Ais 43:14; Jer 50:25; 51:56
Àìsá. 14:22Jer 51:62
Àìsá. 14:23Ais 13:1, 21; Jer 50:35, 39; Ifi 18:2
Àìsá. 14:252Kr 32:21, 22; Ais 30:31; 31:8; 37:36, 37
Àìsá. 14:25Ais 10:24
Àìsá. 14:27Sm 33:11; Owe 19:21; 21:30; Ais 46:11
Àìsá. 14:272Kr 20:5, 6; Ais 43:13
Àìsá. 14:282Ọb 16:20; 2Kr 28:27
Àìsá. 14:292Ọb 18:1, 8
Àìsá. 14:292Kr 26:3, 6
Àìsá. 14:30Jer 47:1; Isk 25:16; Joẹ 3:4; Emọ 1:6-8; Sef 2:4; Sek 9:5
Àìsá. 14:32Sm 48:1-3; 87:1, 2; 132:13, 14
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
  • 28
  • 29
  • 30
  • 31
  • 32
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 14:1-32

Àìsáyà

14 Torí Jèhófà máa ṣàánú Jékọ́bù,+ ó sì máa tún Ísírẹ́lì yàn.+ Ó máa mú kí wọ́n gbé* ní ilẹ̀ wọn,+ àwọn àjèjì máa dara pọ̀ mọ́ wọn, wọ́n sì máa sọ ara wọn di ará ilé Jékọ́bù.+ 2 Àwọn èèyàn máa mú wọn, wọ́n á mú wọn wá sí àyè wọn, ilé Ísírẹ́lì sì máa fi wọ́n ṣe ẹrúkùnrin àti ẹrúbìnrin+ ní ilẹ̀ Jèhófà; wọ́n máa mú àwọn tó mú wọn lẹ́rú, wọ́n sì máa di olórí àwọn tó fipá kó wọn ṣiṣẹ́.

3 Ní ọjọ́ tí Jèhófà bá mú kí o bọ́ nínú ìrora rẹ, rúkèrúdò rẹ àti bí wọ́n ṣe ń fipá mú ọ sìnrú,+ 4 o máa pa òwe* yìí sí ọba Bábílónì pé:

“Ẹ wo bí òpin ṣe dé bá ẹni tó ń fipá kó àwọn míì ṣiṣẹ́!

Ẹ wo bí ìfìyàjẹni ṣe wá sí òpin!+

 5 Jèhófà ti kán ọ̀pá àwọn ẹni burúkú,

Ọ̀pá àwọn tó ń ṣàkóso,+

 6 Ẹni tó ń fìbínú kan àwọn èèyàn lẹ́ṣẹ̀ẹ́ láìdáwọ́ dúró,+

Ẹni tó ń fi ìkannú tẹ àwọn orílẹ̀-èdè lórí ba, tó sì ń ṣe inúnibíni sí wọn láìṣíwọ́.+

 7 Gbogbo ayé ti wá sinmi, ó bọ́ lọ́wọ́ ìyọlẹ́nu.

Àwọn èèyàn ń kígbe ayọ̀.+

 8 Àwọn igi júnípà pàápàá ń yọ̀ torí rẹ,

Pẹ̀lú àwọn igi kédárì Lẹ́bánónì.

Wọ́n sọ pé, ‘Látìgbà tí o ti ṣubú,

Kò sí agégi kankan tó dìde sí wa.’

 9 Isà Òkú* tó wà nísàlẹ̀ pàápàá ti ru sókè,

Láti pàdé rẹ tí o bá dé.

Nítorí rẹ, ó jí àwọn tí ikú ti pa,*

Gbogbo àwọn aṣáájú ayé tó ń fìyà jẹni.*

Ó ń mú kí gbogbo ọba àwọn orílẹ̀-èdè dìde lórí ìtẹ́ wọn.

10 Gbogbo wọn sọ fún ọ pé,

‘Ṣé ìwọ náà ti di aláìlágbára bíi tiwa ni?

Ṣé o ti dà bíi wa ni?

11 A ti mú ìyangàn rẹ lọ sínú Isà Òkú,*

Ìró àwọn ohun ìkọrin rẹ olókùn tín-ín-rín.+

Àwọn ìdin tẹ́ rẹrẹ lábẹ́ rẹ bí ibùsùn,

Kòkòrò mùkúlú sì ni ìbora rẹ.’

12 Wo bí o ṣe já bọ́ láti ọ̀run,

Ìwọ ẹni tó ń tàn, ọmọ òwúrọ̀!

Wo bí a ṣe gé ọ já bọ́ lulẹ̀,

Ìwọ tó ṣẹ́gun àwọn orílẹ̀-èdè!+

13 O sọ lọ́kàn rẹ pé, ‘Màá gòkè lọ sí ọ̀run.+

Màá gbé ìtẹ́ mi ga ju àwọn ìràwọ̀ Ọlọ́run,+

Màá sì jókòó sórí òkè ìpàdé,

Láwọn ibi tó jìnnà jù ní àríwá.+

14 Màá gòkè lọ sórí àwọsánmà;*

Màá mú ara mi jọ Ẹni Gíga Jù Lọ.’

15 Kàkà bẹ́ẹ̀, a máa sọ̀ ọ́ kalẹ̀ lọ sínú Isà Òkú,*

Sí àwọn ibi tó jìnnà jù nínú kòtò.

16 Àwọn tó rí ọ máa tẹjú mọ́ ọ;

Wọ́n máa yẹ̀ ọ́ wò fínnífínní, wọ́n á sọ pé,

‘Ṣé ọkùnrin tó ń mi ayé tìtì nìyí,

Tó kó jìnnìjìnnì bá àwọn ìjọba,+

17 Tó mú kí ilẹ̀ ayé tí à ń gbé dà bí aginjù,

Tó sì gba àwọn ìlú rẹ̀,+

Tí kò jẹ́ kí àwọn ẹlẹ́wọ̀n rẹ̀ pa dà sílé?’+

18 Gbogbo ọba àwọn orílẹ̀-èdè yòókù,

Àní, gbogbo wọn dùbúlẹ̀ nínú ògo,

Kálukú nínú ibojì* rẹ̀.

19 Àmọ́ a sọ ìwọ nù láìní sàréè,

Bí èéhù* tí a kórìíra,

Tí wọ́n fi àwọn tí a fi idà gún pa, bò bí aṣọ,

Tó sọ̀ kalẹ̀ lọ bá àwọn òkúta inú kòtò,

Bí òkú tí wọ́n fẹsẹ̀ tẹ̀ mọ́lẹ̀.

20 O ò ní lọ bá wọn nínú sàréè,

Torí o run ilẹ̀ rẹ,

O pa àwọn èèyàn tìrẹ.

A ò ní dárúkọ ọmọ àwọn aṣebi mọ́ títí láé.

21 Ẹ ṣètò ibi ìpẹran fún àwọn ọmọ rẹ̀,

Torí ẹ̀bi àwọn baba ńlá wọn,

Kí wọ́n má bàa dìde, kí wọ́n sì gba ayé,

Kí wọ́n wá fi àwọn ìlú wọn kún ilẹ̀ náà.”

22 “Màá dìde sí wọn,”+ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí.

“Màá pa orúkọ àti àṣẹ́kù run, màá sì pa àtọmọdọ́mọ àti ìran tó ń bọ̀ run kúrò ní Bábílónì,”+ ni Jèhófà wí.

23 “Màá sọ ọ́ di ibùgbé àwọn òòrẹ̀ àti agbègbè tó ní irà, màá sì fi ìgbálẹ̀ ìparun gbá a,”+ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí.

24 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ti búra pé:

“Bí mo ṣe gbèrò gẹ́lẹ́ ló máa rí,

Ohun tí mo sì pinnu gẹ́lẹ́ ló máa ṣẹ.

25 Màá fọ́ ará Ásíríà náà túútúú ní ilẹ̀ mi,

Màá sì tẹ̀ ẹ́ mọ́lẹ̀ lórí àwọn òkè mi.+

Àjàgà rẹ̀ máa kúrò lọ́rùn wọn,

Ẹrù rẹ̀ sì máa kúrò ní èjìká wọn.”+

26 Ohun tí a ti pinnu láti ṣe* sí gbogbo ayé nìyí,

Ọwọ́ tí a sì nà jáde sí* gbogbo orílẹ̀-èdè nìyí.

27 Torí pé Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ti pinnu,

Ta ló lè dà á rú?+

Ó ti na ọwọ́ rẹ̀ jáde,

Ta ló sì lè dá a pa dà?+

28 Ní ọdún tí Ọba Áhásì kú,+ ìkéde yìí wáyé, pé:

29 “Kí ẹnì kankan nínú rẹ má yọ̀, ìwọ Filísíà,

Torí pé ọ̀pá ẹni tó ń lù ọ́ ti kán.

Torí ejò olóró+ máa jáde látinú gbòǹgbò ejò,+

Ọmọ rẹ̀ sì máa jẹ́ ejò oníná tó ń fò.*

30 Tí àkọ́bí àwọn ẹni rírẹlẹ̀ bá ń jẹun,

Tí àwọn aláìní sì dùbúlẹ̀ láìséwu,

Màá fi ìyàn pa gbòǹgbò rẹ,

A sì máa pa ohun tó bá ṣẹ́ kù lára rẹ.+

31 Pohùn réré ẹkún, ìwọ ẹnubodè! Ké jáde, ìwọ ìlú!

Ọkàn gbogbo yín máa domi, ẹ̀yin Filísíà!

Torí èéfín ń rú bọ̀ láti àríwá,

Kò sì sẹ́ni tí kì í ṣe kánkán nínú ọ̀wọ́ ọmọ ogun rẹ̀.”

32 Báwo ni kí wọ́n ṣe dá àwọn ìránṣẹ́ orílẹ̀-èdè náà lóhùn?

Pé Jèhófà ti fi ìpìlẹ̀ Síónì lélẹ̀+

Àti pé àwọn tó rẹlẹ̀ nínú àwọn èèyàn rẹ̀ máa fi ibẹ̀ ṣe ààbò.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́