ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 111
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Sáàmù

      • Ẹ yin Jèhófà nítorí àwọn iṣẹ́ rẹ̀ tóbi

        • Orúkọ Ọlọ́run jẹ́ mímọ́, ó sì yẹ fún ọ̀wọ̀ (9)

        • Ìbẹ̀rù Jèhófà ni ọgbọ́n (10)

Sáàmù 111:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Halelúyà!” “Jáà” ni ìkékúrú Jèhófà.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 68:4; 113:1; Ifi 19:1
  • +Sm 9:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 14

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2009, ojú ìwé 20

Sáàmù 111:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 98:1; 139:14; Ifi 15:3
  • +Sm 77:12; 143:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 14

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2009, ojú ìwé 20-21

Sáàmù 111:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 103:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2009, ojú ìwé 21-22

Sáàmù 111:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “olóore ọ̀fẹ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 31:19; Joṣ 4:5-7
  • +Ẹk 34:6; Jem 5:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2009, ojú ìwé 21-22

Sáàmù 111:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 37:25; Mt 6:33
  • +Sm 89:34; 105:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2009, ojú ìwé 22

Sáàmù 111:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 44:2; 105:44

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2009, ojú ìwé 22-23

Sáàmù 111:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 32:4
  • +Sm 19:8; Ais 55:10, 11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2009, ojú ìwé 23

Sáàmù 111:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 19:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 3

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2009, ojú ìwé 23

Sáàmù 111:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 15:13; Lk 1:68; Ifi 7:10
  • +Sm 89:7; Ais 6:2, 3; Lk 1:49; Ifi 4:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2009, ojú ìwé 24

Sáàmù 111:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “pa wọ́n.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Job 28:28; Owe 1:7; Onw 12:13
  • +Di 4:6; Joṣ 1:7, 8; 1Ọb 2:3; Sm 119:100; 2Ti 3:14, 15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2009, ojú ìwé 24

    3/15/1995, ojú ìwé 16

Àwọn míì

Sm 111:1Sm 68:4; 113:1; Ifi 19:1
Sm 111:1Sm 9:1
Sm 111:2Sm 98:1; 139:14; Ifi 15:3
Sm 111:2Sm 77:12; 143:5
Sm 111:3Sm 103:17
Sm 111:4Di 31:19; Joṣ 4:5-7
Sm 111:4Ẹk 34:6; Jem 5:11
Sm 111:5Sm 37:25; Mt 6:33
Sm 111:5Sm 89:34; 105:8
Sm 111:6Sm 44:2; 105:44
Sm 111:7Di 32:4
Sm 111:7Sm 19:8; Ais 55:10, 11
Sm 111:8Sm 19:9
Sm 111:9Ẹk 15:13; Lk 1:68; Ifi 7:10
Sm 111:9Sm 89:7; Ais 6:2, 3; Lk 1:49; Ifi 4:8
Sm 111:10Job 28:28; Owe 1:7; Onw 12:13
Sm 111:10Di 4:6; Joṣ 1:7, 8; 1Ọb 2:3; Sm 119:100; 2Ti 3:14, 15
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Sáàmù 111:1-10

Sáàmù

111 Ẹ yin Jáà!*+

א [Áléfì]

Màá fi gbogbo ọkàn mi yin Jèhófà+

ב [Bétì]

Nínú àwùjọ àwọn adúróṣinṣin àti nínú ìjọ.

ג [Gímélì]

 2 Àwọn iṣẹ́ Jèhófà tóbi;+

ד [Dálétì]

Gbogbo àwọn tó fẹ́ràn wọn máa ń kẹ́kọ̀ọ́ nípa wọn.+

ה [Híì]

 3 Àwọn iṣẹ́ rẹ̀ ní ògo àti ọlá ńlá,

ו [Wọ́ọ̀]

Òdodo rẹ̀ sì wà títí láé.+

ז [Sáyìn]

 4 Ó ń mú ká rántí àwọn iṣẹ́ àgbàyanu rẹ̀.+

ח [Hétì]

Jèhófà jẹ́ agbatẹnirò* àti aláàánú.+

ט [Tétì]

 5 Ó ń fún àwọn tó bẹ̀rù rẹ̀ ní oúnjẹ.+

י [Yódì]

Ó rántí májẹ̀mú rẹ̀ títí láé.+

כ [Káfì]

 6 Ó ti fi àwọn iṣẹ́ agbára rẹ̀ han àwọn èèyàn rẹ̀

ל [Lámédì]

Bó ṣe fún wọn ní ogún àwọn orílẹ̀-èdè.+

מ [Mémì]

 7 Àwọn iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀ jẹ́ òtítọ́ àti ìdájọ́ òdodo;+

נ [Núnì]

Gbogbo àṣẹ rẹ̀ ṣeé gbẹ́kẹ̀ lé.+

ס [Sámékì]

 8 Wọ́n ṣeé gbára lé ní gbogbo ìgbà, ní báyìí àti títí láé;

ע [Áyìn]

Inú òtítọ́ àti òdodo ni wọ́n ti wá.+

פ [Péè]

 9 Ó ti ra àwọn èèyàn rẹ̀ pa dà,+

צ [Sádì]

Ó pàṣẹ pé kí májẹ̀mú rẹ̀ wà títí láé.

ק [Kófì]

Orúkọ rẹ̀ jẹ́ mímọ́, ó sì yẹ fún ọ̀wọ̀.+

ר [Réṣì]

10 Ìbẹ̀rù Jèhófà ni ìbẹ̀rẹ̀ ọgbọ́n.+

ש [Sínì]

Gbogbo àwọn tó ń pa àwọn àṣẹ rẹ̀* mọ́ ní òye tó jinlẹ̀ gan-an.+

ת [Tọ́ọ̀]

Ìyìn rẹ̀ wà títí láé.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́