ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Kọ́ríńtì 4
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 2 Kọ́ríńtì

      • Ìmọ́lẹ̀ ìhìn rere (1-6)

        • Ojú inú àwọn aláìgbàgbọ́ fọ́ (4)

      • Ìṣúra nínú àwọn ohun èlò tí a fi amọ̀ ṣe (7-18)

2 Kọ́ríńtì 4:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2005, ojú ìwé 14-15

2 Kọ́ríńtì 4:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kọ 2:17; Ga 1:9
  • +2Kọ 6:3, 4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2005, ojú ìwé 14-15

    10/1/1997, ojú ìwé 18-20

    5/1/1997, ojú ìwé 6-7

    Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run, ojú ìwé 153

2 Kọ́ríńtì 4:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2005, ojú ìwé 20-22

2 Kọ́ríńtì 4:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àsìkò yìí.” Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

  • *

    Tàbí “iná.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 14:30; Ef 2:2; 1Jo 5:19
  • +2Kọ 11:14
  • +Kol 1:15; Heb 1:3
  • +Ais 60:2; Jo 8:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jí!,

    5/8/2005, ojú ìwé 21

    Ayọ, ojú ìwé 127-128

2 Kọ́ríńtì 4:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 1:3
  • +1Pe 2:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2004, ojú ìwé 16-17

    3/1/2002, ojú ìwé 8

2 Kọ́ríńtì 4:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìṣà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kọ 4:1
  • +Ais 64:8; Iṣe 9:15; 1Kọ 15:47
  • +2Kọ 12:9, 10; Flp 4:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    6/2017, ojú ìwé 10-11

    Jọ̀wọ́ Pa Dà Sọ́dọ̀ Jèhófà, ojú ìwé 6

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2012, ojú ìwé 28-29

    7/1/2000, ojú ìwé 18

    3/15/1999, ojú ìwé 11

    2/1/1999, ojú ìwé 14

    2/1/1992, ojú ìwé 32

    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba,

    2/2007, ojú ìwé 1

    1/1998, ojú ìwé 1

2 Kọ́ríńtì 4:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “kì í ṣe pé ó tojú sú wa.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 10:13

2 Kọ́ríńtì 4:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 13:5
  • +Ifi 2:10

2 Kọ́ríńtì 4:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Flp 3:10; 1Pe 4:13

2 Kọ́ríńtì 4:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 8:36; 1Kọ 4:9; 15:31

2 Kọ́ríńtì 4:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 116:10

2 Kọ́ríńtì 4:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 6:14

2 Kọ́ríńtì 4:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ti 2:10

2 Kọ́ríńtì 4:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    5/2019, ojú ìwé 2

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2008, ojú ìwé 28

    8/15/2004, ojú ìwé 25

    5/15/1996, ojú ìwé 32

2 Kọ́ríńtì 4:17

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àdánwò.”

  • *

    Ní Grk., “tẹ̀wọ̀n.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 5:12; Ro 8:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 5/2019, ojú ìwé 1

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    2/15/1996, ojú ìwé 27-28

2 Kọ́ríńtì 4:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kọ 5:7; Heb 11:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    5/2020, ojú ìwé 26-31

    Ìjọsìn Mímọ́, ojú ìwé 36

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    2/15/1996, ojú ìwé 27-29

Àwọn míì

2 Kọ́r. 4:22Kọ 2:17; Ga 1:9
2 Kọ́r. 4:22Kọ 6:3, 4
2 Kọ́r. 4:4Jo 14:30; Ef 2:2; 1Jo 5:19
2 Kọ́r. 4:42Kọ 11:14
2 Kọ́r. 4:4Kol 1:15; Heb 1:3
2 Kọ́r. 4:4Ais 60:2; Jo 8:12
2 Kọ́r. 4:6Jẹ 1:3
2 Kọ́r. 4:61Pe 2:9
2 Kọ́r. 4:72Kọ 4:1
2 Kọ́r. 4:7Ais 64:8; Iṣe 9:15; 1Kọ 15:47
2 Kọ́r. 4:72Kọ 12:9, 10; Flp 4:13
2 Kọ́r. 4:81Kọ 10:13
2 Kọ́r. 4:9Heb 13:5
2 Kọ́r. 4:9Ifi 2:10
2 Kọ́r. 4:10Flp 3:10; 1Pe 4:13
2 Kọ́r. 4:11Ro 8:36; 1Kọ 4:9; 15:31
2 Kọ́r. 4:13Sm 116:10
2 Kọ́r. 4:141Kọ 6:14
2 Kọ́r. 4:152Ti 2:10
2 Kọ́r. 4:17Mt 5:12; Ro 8:18
2 Kọ́r. 4:182Kọ 5:7; Heb 11:1
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
2 Kọ́ríńtì 4:1-18

Ìwé Kejì sí Àwọn Ará Kọ́ríńtì

4 Nígbà náà, torí pé ipasẹ̀ àánú tí a fi hàn sí wa la fi rí iṣẹ́ òjíṣẹ́ yìí gbà, a kò juwọ́ sílẹ̀. 2 Àmọ́ a ti kọ àwọn ohun ìtìjú tí kò ṣeé gbọ́ sétí sílẹ̀ pátápátá, a kò rin ìrìn ẹ̀tàn, bẹ́ẹ̀ ni a kò ṣe àbùlà ọ̀rọ̀ Ọlọ́run;+ àmọ́ bí a ṣe ń fi òtítọ́ hàn kedere, à ń dámọ̀ràn ara wa fún ẹ̀rí ọkàn gbogbo èèyàn níwájú Ọlọ́run.+ 3 Tí ìhìn rere tí à ń kéde bá wà lábẹ́ ìbòjú lóòótọ́, á jẹ́ pé ó wà lábẹ́ ìbòjú láàárín àwọn tó ń ṣègbé, 4 láàárín àwọn tí ọlọ́run ètò àwọn nǹkan yìí*+ ti fọ́ ojú inú àwọn aláìgbàgbọ́,+ kí ìmọ́lẹ̀* ìhìn rere ológo nípa Kristi, ẹni tó jẹ́ àwòrán Ọlọ́run,+ má bàa mọ́lẹ̀ wọlé.+ 5 Nítorí kì í ṣe ara wa là ń wàásù rẹ̀, Jésù Kristi là ń wàásù gẹ́gẹ́ bí Olúwa, a sì ń sọ pé a jẹ́ ẹrú yín nítorí Jésù. 6 Torí Ọlọ́run ni ẹni tó sọ pé: “Kí ìmọ́lẹ̀ tàn láti inú òkùnkùn,”+ ó sì ti tan ìmọ́lẹ̀ sí ọkàn wa+ láti mú kí ìmọ̀ ológo nípa Ọlọ́run mọ́lẹ̀ nípasẹ̀ ojú Kristi.

7 Àmọ́ ṣá o, a ní ìṣúra yìí+ nínú àwọn ohun èlò* tí a fi amọ̀ ṣe,+ kí agbára tó kọjá ti ẹ̀dá lè jẹ́ ti Ọlọ́run, kó má sì jẹ́ látọ̀dọ̀ wa.+ 8 Wọ́n há wa gádígádí ní gbogbo ọ̀nà, àmọ́ kò le débi tí a ò fi lè yíra; ọkàn wa dà rú, àmọ́ kì í ṣe láìsí ọ̀nà àbáyọ rárá;*+ 9 wọ́n ṣe inúnibíni sí wa, àmọ́ a ò pa wá tì;+ wọ́n gbé wa ṣánlẹ̀, àmọ́ a ò pa run.+ 10 Nínú ara wa, ìgbà gbogbo là ń fara da ìyà àti ewu ikú tí Jésù dojú kọ,+ kí ìgbésí ayé Jésù lè hàn kedere lára wa. 11 Nítorí ìgbà gbogbo ni wọ́n ń mú kí àwa tí a wà láàyè fojú kojú pẹ̀lú ikú+ nítorí Jésù, kí ìgbésí ayé Jésù lè hàn kedere nínú ara kíkú wa. 12 Torí náà, ikú wà lẹ́nu iṣẹ́ nínú wa, àmọ́ ìyè wà lẹ́nu iṣẹ́ nínú yín.

13 Ní báyìí, torí a ní ẹ̀mí ìgbàgbọ́ kan náà, irú èyí tí a kọ nípa rẹ̀ pé: “Mo ní ìgbàgbọ́, torí náà mo sọ̀rọ̀”;+ àwa náà ní ìgbàgbọ́, torí náà a sọ̀rọ̀, 14 bí a ṣe mọ̀ pé Ẹni tó gbé Jésù dìde máa gbé àwa náà dìde pẹ̀lú Jésù, ó sì máa mú àwa pẹ̀lú yín wá síwájú rẹ̀.+ 15 Gbogbo èyí jẹ́ nítorí yín, kí inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí tó ń pọ̀ sí i lè túbọ̀ pọ̀ gidigidi, nítorí àwọn púpọ̀ sí i tó ń dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run ń fi ògo fún un.+

16 Nítorí náà, a kò juwọ́ sílẹ̀, kódà bí ẹni tí a jẹ́ ní òde bá tilẹ̀ ń joro, ó dájú pé ẹni tí a jẹ́ ní inú ń di ọ̀tun láti ọjọ́ dé ọjọ́. 17 Bó tiẹ̀ jẹ́ pé ìpọ́njú* náà jẹ́ fún ìgbà díẹ̀, kò sì lágbára, ó ń yọrí sí ògo fún wa, ògo tí ó tóbi* gan-an, tí ó sì jẹ́ ti ayérayé;+ 18 bí a ṣe ń tẹ ojú wa mọ́ àwọn ohun tí a kò rí dípò àwọn ohun tí à ń rí.+ Nítorí àwọn ohun tí à ń rí wà fún ìgbà díẹ̀, àmọ́ àwọn ohun tí a kò rí máa wà títí ayérayé.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́