Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
October 8, 2000
Ṣé Gbogbo Ohun Tóo Bá Gbọ́ Ló Yẹ Kóo Gbà Gbọ́?
Èyí tó pọ̀ jù lára wa ló ń rí ìsọfúnni púpọ̀ gbà lójoojúmọ́. Irú èwo ló máa ń jẹ́? Báwo lo ṣe lè mọ èyí tó jẹ́ òtítọ́ yàtọ̀ sí èyí tó jẹ́ irọ́?
9 Má Ṣe Jẹ́ Kí Wọ́n Fi Bojúbojú Ìpolongo Èké Bò Ọ́ Lójú!
15 Ibo Lọ̀ràn “Iṣẹ́ Àfìgbésí Ayé Ẹni Ṣe” Ń Lọ Báyìí?
20 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
22 Àwọn Òkè Aboríṣóńṣó-bìdírẹ̀kẹ̀tẹ̀ ní Mẹ́síkò
24 Jíjẹ́ Adúróṣinṣin—Lolórí Àníyàn Mi
29 Wíwo Ayé
Èé Ṣe Tí Mo Fi Rí Tẹ́ẹ́rẹ́ Báyìí? 12
Àwọn ọ̀dọ́ kan ń rò pé àwọn ò jojú ní gbèsè nítorí pé àwọn rí tẹ́ẹ́rẹ́. Gbé àwọn àbá tó gbéṣẹ́ díẹ̀ yẹ̀ wò tó lè ran àwọn ọ̀dọ́ lọ́wọ́ láti kojú rẹ̀.
“Eré Ìdárayá Àṣejù”—Ǹjẹ́ Ó Yẹ Kí O Fara Rẹ Wewu? 18
Kí ni Bíbélì sọ nípa èyí?