ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • km 6/11 ojú ìwé 3
  • “Wákàtí Mélòó Ni Kí N Ròyìn?”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Wákàtí Mélòó Ni Kí N Ròyìn?”
  • Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2011
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Àwọn Òjíṣẹ́ Tó Ń Wàásù Ìhìn Rere
    A Ṣètò Wa Láti Ṣe Ìfẹ́ Jèhófà
  • Lo Àkókò Rẹ Lọ́nà Gbígbéṣẹ́
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—1999
  • Ǹjẹ́ Ò Ń Ṣe Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Láṣeyanjú?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2019
  • Máa Ra Àkókò Tí Ó Rọgbọ Pa Dà Lẹ́nu Iṣẹ́ Òjíṣẹ́
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2015
Àwọn Míì
Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2011
km 6/11 ojú ìwé 3

“Wákàtí Mélòó Ni Kí N Ròyìn?”

Ǹjẹ́ o ti béèrè irú ìbéèrè yìí rí? A lè rí ìtọ́sọ́nà lórí kókó yìí nínú ìwé A Ṣètò Wa, ojú ìwé 86 sí 87. A tún máa ń pèsè àfikún ìsọfúnni lóòrèkóòrè, irú èyí tó wà nínú Àpótí Ìbéèrè nínú Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa ti oṣù September ọdún 2008. Níwọ̀n bó ti jẹ́ pé ipò nǹkan kò dọ́gba, a kò ṣe òfin jànràn-janran lórí kókó yìí. Torí náà, kò ní bẹ́tọ̀ọ́ mu fún àwọn alàgbà tàbí àwọn míì láti wá gbé àwọn ìlànà kan kalẹ̀.

Bí ìbéèrè bá jẹ yọ lórí iye àkókò tá a lò lóde ẹ̀rí, tí kò sì sí ìtọ́ni pàtó kan tá a tẹ̀ jáde nípa rẹ̀, akéde kọ̀ọ̀kan lè ronú nípa àwọn kókó yìí: Ṣé iṣẹ́ òjíṣẹ́ la lo gbogbo àkókò náà fún? Àbí nǹkan míì tí kò fi bẹ́ẹ̀ jẹ mọ́ iṣẹ́ òjíṣẹ́ la fi àkókò náà ṣe? Ńṣe ló yẹ kí ohun tá a kọ sínú ìròyìn iṣẹ́ ìsìn pápá níparí oṣù fún wa láyọ̀, kò yẹ kó jẹ́ èyí táá máa da ẹ̀rí ọkàn wa láàmú. (Ìṣe 23:1) Lóòótọ́, kì í ṣe ríròyìn àkókò ni ohun tó jẹ wá lógún jù lọ, bí kò ṣe pé kí a máa lo àkókò náà lọ́nà tó dára, nípa jíjẹ́ aláápọn lẹ́nu iṣẹ́ òjíṣẹ́ náà.—Héb. 6:11.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́