ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb17 February ojú ìwé 1
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • JÍ!
  • MÁA FI ÒTÍTỌ́ KỌ́NI
  • TẸ́TÍ SÍ ỌLỌ́RUN KÓ O LÈ WÀ LÁÀYÈ TÍTÍ LÁÉ (ll )
  • KỌ Ọ̀NÀ ÌGBỌ́RỌ̀KALẸ̀ RẸ
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
mwb17 February ojú ìwé 1
Arábìnrin kan ń sọ̀rọ̀ nípa ìṣẹ̀dá nínú kíláàsì

Arábìnrin kan ń ṣàlàyé ọ̀rọ̀ ní kíláàsì

Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò

JÍ!

Jí! No. 1 2017 | Ìrànlọ́wọ́ fún Àwọn Ọ̀dọ́ Tó Ní Ìdààmú Ọkàn

Béèrè ìbéèrè: Ìròyìn nípa àwọn ọ̀dọ́ tó ń ní ìdààmú ọkàn ti wá pọ̀ ju ti tẹ́lẹ̀ lọ báyìí. Kí lẹrò pá a lè ṣe nípa ìṣòro yìí?

Fi ìwé lọni: Ìwé ìròyìn yìí sọ ohun táwọn ọ̀dọ́ lè ṣe tí wọ́n bá ní ìdààmú ọkàn àti báwọn òbí wọn ṣe lè ràn wọ́n lọ́wọ́.

MÁA FI ÒTÍTỌ́ KỌ́NI

Wọ́n ṣí Bíbélì sílẹ̀

Béèrè ìbéèrè: Kí ló ń mú kí ìdílé láyọ̀?

Ka Bíbélì: Ef 5:33

Òtítọ́: Ìgbéyàwó máa ń yọrí sí rere tí tọkọ tìyàwó bá ń fìfẹ́ bára wọn lò, tí wọ́n sì ń bọ̀wọ̀ fúnra wọn.

TẸ́TÍ SÍ ỌLỌ́RUN KÓ O LÈ WÀ LÁÀYÈ TÍTÍ LÁÉ (ll )

Tẹ́tí Sí Ọlọ́run Kó O Lè Wà Láàyè Títí Láé

Béèrè ìbéèrè: Táwọn kan bá rí onírúurú ìṣẹ̀dá àgbàyanu, ó máa ń yà wọ́n lẹ́nu, wọ́n sì máa ń sọ bó ṣe rẹwà tó. Àmọ́ ta ló yẹ kí wọ́n fi ògo fún?

Ka Bíbélì: Iṣi 4:11

Fi ìwé lọni: Bí ẹsẹ Bíbélì yìí ṣe sọ, Ọlọ́run ló yẹ kó gba ògo àti ọlá fún àwọn nǹkan tó dá. Ohun tó wà ní ojú ìwé keje [7] ìwé yìí nìyẹn.

KỌ Ọ̀NÀ ÌGBỌ́RỌ̀KALẸ̀ RẸ

Wo àwọn ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ tá a fi ṣe àpẹẹrẹ yìí, kó o sì kọ ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ tìrẹ

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́