January 20-26
JẸ́NẸ́SÍSÌ 6-8
Orin 89 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ó Ṣe Bẹ́ẹ̀ Gẹ́lẹ́”: (10 min.)
Jẹ 6:9, 13—Àárín àwọn èèyàn burúkú ni Nóà ń gbé (w18.02 4 ¶4)
Jẹ 6:14-16—Ọlọ́run gbé iṣẹ́ ńlá kan fún Nóà (w13 4/1 14 ¶1)
Jẹ 6:22—Nóà fi hàn pé òun gba Jèhófà gbọ́ (w11 9/15 18 ¶13)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)
Jẹ 7:2—Kí ni wọ́n fi ń mọ àwọn ẹranko tó mọ́ yàtọ̀ sí àwọn tí kò mọ́? (w04 1/1 29 ¶7)
Jẹ 7:11—Ibo ni omi tó fa Ìkún Omi kárí ayé ti wá? (w04 1/1 30 ¶1)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jẹ 6:1-16 (th ẹ̀kọ́ 10)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́—Fídíò: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà, lẹ́yìn náà béèrè àwọn ìbéèrè yìí: Báwo ni akéde yẹn ṣe ṣàlàyé 1 Jòhánù 4:8 fún onílé? Báwo làwọn akéde yẹn ṣe fọwọ́ sowọ́ pọ̀ nígbà tí wọ́n ń bá onílé náà sọ̀rọ̀?
Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 12)
Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lẹ́yìn náà, fún un ní ọ̀kan lára àwọn ìtẹ̀jáde tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́. (th ẹ̀kọ́ 7)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ìjọsìn Ìdílé: Nóà—Ó Bá Ọlọ́run Rìn: (10 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, béèrè àwọn ìbéèrè yìí: Báwo làwọn òbí yẹn ṣe fi ìtàn Nóà kọ́ àwọn ọmọ wọn lẹ́kọ̀ọ́? Àwọn nǹkan wo lẹ rí kọ́ tẹ́yin náà lè ṣe nígbà ìjọsìn ìdílé yín?
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (5 min.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 15 ¶1-7
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
Orin 37 àti Àdúrà