Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
June 8, 2000
Àìsàn Bára Kú—Kíkojú Rẹ̀ Gẹ́gẹ́ Bí Ìdílé
Mọ̀ nípa bí àwọn ìdílé kan ṣe ń kojú ìṣòro àìsàn bára kú tó ń ṣe mẹ́ńbà ìdílé wọn tí wọ́n fẹ́ràn.
3 Nígbà Tí Àìsàn Bára Kú Bá Kọ Lu Ìdílé Kan
4 Àìsàn Bára Kú—Àníyàn Ló Jẹ́ fún Ìdílé
8 Bí Àwọn Ìdílé Ṣe Lè Kojú Ìṣòro Àìsàn Bára Kú
16 Ìfẹ́ Kristẹni—Nígbà Tí Òkè Ayọnáyèéfín Bú Gbàù
20 Ǹjẹ́ o Mọ̀?
26 Àwọn Olùgbé Inú Hòrò Lóde Òní
28 Wíwo Ayé
30 Ǹjẹ́ Ẹ̀kọ́ Ẹfolúṣọ̀n Bọ́gbọ́n mu?
31 Lílo Tẹlifíṣọ̀n Tìṣọ́ratìṣọ́ra
Àwọn Ìsáǹsá Bàbá Ọmọ—Ṣé Lóòótọ́ Ni Wọ́n Lè Bọ́? 13
Ṣé ọ̀dọ́mọkùnrin kan lè bọ́ pátápátá nínú gbígbé ẹrù ọmọ tó bí láìṣègbéyàwó?
Báwo ni Bíbélì ṣe dáhùn ìbéèrè yìí?