Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
November 8, 2000
Àwọn Nọ́ọ̀sì—Kí La Lè Ṣe Láìsí Wọn?
Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ọ̀pọ̀ ìgbà la máa ń fojú kéré àwọn nọ́ọ̀sì, ipa tí wọ́n ń kó nínú ìtọ́jú aláìsàn kò kéré rárá. Ayọ̀ àti àwọn ìpèníjà wo ló wà nínú iṣẹ́ àtàtà yìí?
3 Àwọn Nọ́ọ̀sì—Èé Ṣe Tí Wọ́n Fi Jẹ́ Kòṣeémánìí?
5 Ipa Pàtàkì Tí Àwọn Nọ́ọ̀sì Ń Kó
12 Àbẹ̀wò sí Ilé Elégbòogi Kan ní China
19 Ìlera Tó Sunwọ̀n—Ṣe Ìtọ́sọ́nà Tuntun Ni?
20 Àwọn Ìtọ́jú Àfirọ́pò—Ìdí Tó Fi Jẹ́ Pé Òun Lọ̀pọ̀ Èèyàn Ń Yíjú Sí
22 Ṣíṣàyẹ̀wò Àwọn Ìlànà Ìtọ́jú Àfirọ́pò
29 Wíwo Ayé
31 Ìgbìyànjú Láti Yọ Ìjọba Póòpù Kúrò Nínú Àjọ Ìparapọ̀ Àwọn Orílẹ̀-Èdè
32 Ìdí Táwọn Èèyàn Fi Ń hùwàkiwà
Ṣé Kí N Sọ fún Ẹnì Kan Pé Mo Níṣòro Ìsoríkọ́? 16
Ọ̀pọ̀ ọ̀dọ́ ló ń ṣiyèméjì nípa ẹni tó yẹ kí wọ́n finú hàn.
Láti Rí Ìlera Pípé—Irú Ìlànà Ìtọ́jú Wo Ló Yẹ Ká Yàn? 19-28
Àwọn èèyàn mọyì oògùn òyìnbó àti ìtọ́jú àfirọ́pò lóde òní. Kí ni díẹ̀ lára àwọn ọ̀nà tí ìtọ́jú àfirọ́pò gbà gbéṣẹ́? Àti pé, èé ṣe tó fi jẹ́ pé òun lọ̀pọ̀ èèyàn ń yíjú sí?