Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
April 8, 2004
Ṣé Mósè Ti Gbáyé Rí àbí Ẹni Ìtàn Àròsọ Ni?
Kò sẹ́ni tó kóyán Mósè kéré láàárín àwọn Júù, Kristẹni àtàwọn Mùsùlùmí. Síbẹ̀, lẹ́nu àwọn ọdún àìpẹ́ yìí, àwọn akẹ́kọ̀ọ́jinlẹ̀ àtàwọn ẹlẹ́kọ̀ọ́ ìsìn kan ti bẹ̀rẹ̀ sí ṣiyèméjì pé bóyá lẹnì kan tó ń jẹ́ Mósè tiẹ̀ wà rí. Kí ni ẹ̀rí fi hàn? Báwo sì ni ohun tí Mósè gbélé ayé ṣe ṣe kàn wá lónìí?
4 Ṣé Mósè Ti Gbáyé Rí àbí Ẹni Ìtàn Àròsọ Ni?
10 Bí Ohun Tí Mósè Gbélé Ayé Ṣe Ṣe Kàn Ọ́
16 Wọ́n Bọ́ Lọ́wọ́ Ewu Omíyalé!
17 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
23 Ṣé Àwọn Alátùn-úntò Ló Máa Tún Ayé Ṣe?
32 Àṣálẹ́ Tó Yẹ Ká Máa Rántí—Sunday, April 4, 2004
Bí A Ṣe Kọ́ Kristi Láti Nífẹ̀ẹ́ Ọlọ́run 14
Ka ìtàn amọ́kànyọ̀ nípa bí tọkọtaya kan ṣe ran ọmọ wọn obìnrin tó yadi lọ́wọ́.
Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Ń Jẹ́ Ká Jìyà? 18
Ṣé ó yẹ ká máa bínú sí Ọlọ́run nítorí pé ó fàyè gba ìjìyà? Kọ́ nípa ìdáhùn atura tó wà nínú Bíbélì.