Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
October–December 2011
Bí Àwọn Òbí Ṣe Lè Tọ́ Àwọn Ọmọ Yanjú
ÌGBÀ ÌKÓKÓ OJÚ ÌWÉ 4-9
4 “ Ohun Àgbàyanu Tó Ń Yára Kẹ́kọ̀ọ́ Jù Lọ Lágbàáyé”
ÌGBÀ ỌMỌDÉ OJÚ ÌWÉ 10-15
10 Bó O Ṣe Lè Tọ́ Ọmọ Láti Ìgbà Ọmọdé Títí Dìgbà Ìbàlágà
ÌGBÀ ÌBÀLÁGÀ OJÚ ÌWÉ 16-23
16 Bí Àwọn Òbí Ṣe Lè Ṣèrànwọ́ fún Àwọn Ọmọ Wọn Tó Ti Bàlágà
26 Bó O Ṣe Lè Dènà Ìjàǹbá Ọkọ̀
28 Ojú Ìwòye Bíbélì Ǹjẹ́ Bíbélì Fọwọ́ sí Fífi Èèyàn Ṣe Ẹrú?
30 Ojú Ìwòye Bíbélì Ǹjẹ́ Ọlọ́run Fọwọ́ sí Ogun Jíjà Lóde Òní?