Nínú Ìtẹ̀jáde Yìí
March–April 2015
© 2015 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Ǹjẹ́ Bíbélì Wúlò fún Wa Lónìí?
OJÚ ÌWÉ 3-7
8 Ìrànlọ́wọ́ Fún Ìdílé Bí O Ṣe Lè Ṣàkóso Ìbínú Rẹ
12 Ìrànlọ́wọ́ Fún Ìdílé Bí O Ṣe Lè Ṣàlàyé Ohun Tí Ikú Jẹ́ fún Ọmọ Rẹ
TÚN LỌ WO ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ÀPILẸ̀KỌ
Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé Ìdí Tí Kò Fi Yẹ Kó O Wo Àwòrán Oníhòòhò
Ìjọra wo ló wà láàárín àwòrán oníhòòhò àti sìgá mímu?
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀWỌN Ọ̀DỌ́)
FÍDÍÒ
Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà Jẹ́ Onínúure Àti Ọ̀làwọ́
Nínú fídíò yìí tó wà fún àwọn ọmọdé, wo bí Kọ́lá àti Tósìn ṣe gbádùn eré wọn nígbà tí wọn lawọ́ síra wọn.
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀWỌN ỌMỌDÉ)