ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • g19 No. 1 ojú ìwé 16
  • Kí Lèrò Rẹ?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Kí Lèrò Rẹ?
  • Jí!—2019
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Máa Lo Abala Ìbẹ̀rẹ̀ Orí Ìkànnì JW.ORG Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Bí A Ṣe Lè Lo Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Gbohùn Wọn Sílẹ̀
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2015
  • Kẹ́kọ̀ọ́ SíI
    Jí!—2018
  • Ibo La Ti Lè Rí Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Pàtàkì Nípa Ìgbésí Ayé?
    Ibo La Ti Lè Rí Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Pàtàkì Nípa Ìgbésí Ayé?
Àwọn Míì
Jí!—2019
g19 No. 1 ojú ìwé 16

KÍ LÈRÒ RẸ?

Bàbá kan àti ọmọ rẹ̀ jọ ń wo ìkànnì jw.org
  • Tí Ọlọ́run bá nífẹ̀ẹ́ wa lóòótọ́, kí nìdí tó fi jẹ́ kí ìwà ibi àti ìyà máa bá a lọ?

  • Kí nìdí tó fi dá wa lójú pé àwọn ọjọ́ ìkẹyìn ayé là ń gbé yìí?

  • Báwo la ṣe mọ̀ pé àwọn nǹkan tí Bíbélì sọ nípa Ìjọba Ọlọ́run máa ṣẹ?

  • Ṣé Bíbélì lè ràn wá lọ́wọ́ láti ṣe àwọn ìpinnu tó bọ́gbọ́n mu lóde òní?

Torí pé Ẹlẹ́dàá wa nífẹ̀ẹ́ wa, ó pèsè ìdáhùn sí àwọn ìbéèrè yìí àtàwọn míì. Lọ sí ìkànnì wa, www.jw.org/yo, tá a fi ń kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì, kó o ba lè rí àwọn ìdáhùn náà.

Tó o bá lọ sórí ìkànnì wa, wàá rí eré ìkẹ́kọ̀ọ́, àwọn àpilẹ̀kọ, ohùn tá a gbà sílẹ̀ àti fídíò, àwọn ìfòrọ̀wánilẹ́nuwò, àti ọ̀pọ̀ àwọn ìwé lóríṣiríṣi, títí kan Bíbélì. Ọ̀fẹ́ sì ni gbogbo wọn.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́