Àwọn Ìgbà Tá A Lè Lo Ìwé Àṣàrò Kúkúrú:
• Bí onílé ò bá fẹ́ gba ìwé tá a fi lọ̀ ọ́
• Tọ́wọ́ onílé bá dí
• Nígbà míì tẹ́ ò bá bá èèyàn nílé
• Fún ìjẹ́rìí àìjẹ́-bí-àṣà
• Láti bẹ̀rẹ̀ ìjíròrò
• Tẹ́ ẹ bá ń kọ́ àwọn ọmọ bí wọ́n ṣe máa wàásù
• Tẹ́ ẹ bá ń kọ́ ẹni tẹ́ ẹ̀ ń kọ́ lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì bó ṣe máa wàásù fáwọn ọ̀rẹ́ ẹ̀
• Láti bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì