ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • km 2/13 ojú ìwé 3
  • O Ò Ṣe Ṣiṣẹ́ Díẹ̀ Sí I?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • O Ò Ṣe Ṣiṣẹ́ Díẹ̀ Sí I?
  • Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2013
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ìjẹ́rìí Òpópónà Tó Gbéṣẹ́
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2011
  • Wàásù Ìhìn Rere Náà Níbi Gbogbo
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—1997
  • Máa Ra Àkókò Tí Ó Rọgbọ Pa Dà Lẹ́nu Iṣẹ́ Òjíṣẹ́
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2015
  • Ọ̀nà Tuntun Tá A Fẹ́ Máa Gbà Wàásù Láwọn Ibi Tí Èrò Pọ̀ Sí
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2013
Àwọn Míì
Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2013
km 2/13 ojú ìwé 3

O Ò Ṣe Ṣiṣẹ́ Díẹ̀ Sí I?

Àwọn akéde kan sábà máa ń ṣíwọ́ lóde ẹ̀rí ní àkókò kan pàtó, ó lè jẹ́ ní aago méjìlà ọ̀sán. Òótọ́ ni pé àwọn nǹkan kan lè mú kó pọn dandan fún àwọn kan láti tètè ṣíwọ́ lóde ẹ̀rí. Àmọ́, ṣé torí pé àwọn tẹ́ ẹ jọ jáde òde ẹ̀rí ṣíwọ́ ni ìwọ náà ṣe máa ń ṣíwọ́? Ó lè ti di àṣà àwọn kan pé kí wọ́n máa ṣíwọ́ ní àkókò kan pàtó. O ò ṣe máa gbìyànjú láti ṣiṣẹ́ díẹ̀ sí i lóde ẹ̀rí? Kó o fi àǹfààní yẹn wàásù fún àwọn èèyàn ní òpópónà tàbí láwọn ibòmíì. O tiẹ̀ lè ṣe ìpadàbẹ̀wò kan tàbí méjì bó o ṣe ń darí lọ sílé. Ronú nípa àṣeyọrí tó o máa ṣe tó o bá tún rí ẹnì kan tó nífẹ̀ẹ́ sí ọ̀rọ̀ wa tàbí tó o bá tún fún ẹnì kan tó ń kọjá lọ ní àwọn ìwé ìròyìn wa. Tí a kò bá tètè ṣíwọ́ lóde ẹ̀rí, tá a sì gbìyànjú láti ṣiṣẹ́ díẹ̀ sí i, ọ̀nà kan tó rọrùn nìyẹn tá a lè gbà fi kún “ẹbọ iyìn” wa sí Jèhófà.”—Héb. 13:15.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́