ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • km 2/15 ojú ìwé 4
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
  • Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2015
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2014
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2013
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2014
Àwọn Míì
Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2015
km 2/15 ojú ìwé 4

Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò

Tí A Bá Ń Pín Ìwé Ìkésíni Síbi Ìrántí Ikú Kristi

“À ń fún àwọn èèyàn ní ìwé ìkésíni síbi ìṣẹ̀lẹ̀ pàtàkì kan. Ní April 3, ọ̀kẹ́ àìmọye èèyàn kárí ayé ló máa pàdé láti ṣe Ìrántí Ikú Kristi, wọ́n sì máa gbọ́ ìjíròrò Bíbélì kan lọ́fẹ̀ẹ́ tó dá lórí bí ikú Jésù Kristi ṣe ṣe wá láǹfààní. Ìwé ìkésíni yìí máa jẹ́ kó o mọ ibi tá a ti máa ṣe é ládùúgbò wa àti àkókò tá a máa ṣe é.”

Ilé Ìṣọ́ March 1

“Ní April 3, a ó ṣe ìrántí ikú Jésù Kristi ti ọdún yìí. Àwọn kan ládùúgbò wa máa pà dé láti ṣe ìrántí yìí, àmọ́ àwọn kan wà tí wọ́n rò pé ikú Jésù kò ṣe pàtàkì. Kí lèrò yín nípa rẹ̀? Ǹjẹ́ ẹ rò pé ikú àti àjíǹde Jésù ṣe wá láǹfààní kankan? [Jẹ́ kó fèsì.] Ẹ gbọ́ ohun tí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run sọ nípa rẹ̀. [Ka 1 Kọ́ríńtì 15:22, 26.] Ìwé ìròyìn yìí sọ ọ̀kan lára àwọn ìbùkún ọjọ́ iwájú tí ìràpadà Jésù máa ṣe fún wa, ìyẹn ni pé ikú kò ní sí mọ́ lọ́jọ́ kan.”

Ji! March–April

“À ń ṣèbẹ̀wò ráńpẹ́ sọ́dọ̀ yín ká lè fún yín ní ìwé ìròyìn Jí! tó ṣẹ̀ṣẹ̀ dé. Ìwé ìròyìn yìí dáhùn ìbéèrè tó wà níbí. [Fi iwájú ìwé ìròyìn náà hàn án.] Kí lẹ rò nípa àpẹẹrẹ tó wà nínú ìwé ìròyìn yìí. [Ka Òwe 29:11.] Ǹjẹ́ ẹ rò pé ìlànà Bíbélì yìí wúlò lóde òní. Jẹ́ kó fèsì. Ìwé ìròyìn yìí sọ àwọn ìlànà Bíbélì mẹ́rin, ó sì ṣàlàyé bí àwọn ìlànà yìí ṣe lè ṣe wá láǹfààní.”

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́