ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 April ojú ìwé 8
  • A Máa Pín Ìwé Ìkésíni sí Àpéjọ Àgbègbè

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • A Máa Pín Ìwé Ìkésíni sí Àpéjọ Àgbègbè
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • ÀWỌN OHUN TÓ YẸ KÍ N FI SỌ́KÀN
  • KÍ LO MÁA SỌ?
  • PA DÀ LỌ BẸ̀ WỌ́N WÒ
  • Ìkésíni Tààràtà
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2015
  • Ìwé Ìkésíni Pàtàkì
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2014
  • Ìpolongo Tó Méso Rere Jáde
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2013
  • A Máa Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Pín Ìwé Ìkésíni Síbi Ìrántí Ikú Kristi Ní March 17
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2012
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 April ojú ìwé 8

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

A Máa Pín Ìwé Ìkésíni sí Àpéjọ Àgbègbè

Ọ̀kan lára àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà dúró lẹ́gbẹ̀ẹ́ kẹ̀kẹ́ tó ṣeé tì kiri tí wọ́n pàtẹ ìwé sí, ó wá ń wàásù fún ọkùnrin kan

Lọ́dọọdún, a máa ń hára gàgà láti gbádùn àsè tẹ̀mí ní àwọn àpéjọ àgbègbè wa. A máa pe àwọn èèyàn wá sí àpéjọ yìí bó bá ti lè ṣeé ṣe tó kí àwọn náà lè tọ́ oore Jèhófà wò. (Sm 34:8) Ìgbìmọ̀ àwọn alàgbà ìjọ kọ̀ọ̀kan ló máa pinnu ọ̀nà tó dára jù láti pín ìwé ìkésíni yìí.

ÀWỌN OHUN TÓ YẸ KÍ N FI SỌ́KÀN

  • Ìgbà wo ni àpéjọ àgbègbè wa bọ́ sí?

  • Ìgbà wo ni ìjọ wa máa bẹ̀rẹ̀ sí í pín ìwé ìkésíni?

  • Ìgbà wo ni ìjọ wa á máa ṣe ìpàdé iṣẹ́ ìsìn pápá?

  • Kí làwọn àfojúsùn mi nígbà ìpolongo yìí?

  • Àwọn wo ni mo fẹ́ pè?

KÍ LO MÁA SỌ?

Ìwé ìkésíni sí Àpéjọ Àgbègbè ọdún 2016

Lẹ́yìn tó o bá ti kí onílé dáadáa, o lè sọ pé:

“À ń pín ìwé ìkésíni yìí kárí ayé láti pe àwọn èèyàn sí àpéjọ pàtàkì kan. Ọjọ́ tá a máa ṣe é, aago tá a máa bẹ̀rẹ̀ àti ibi tá a ti máa ṣe é wà nínú ìwé ìkésíni yìí. A ó máa retí yín.”

PA DÀ LỌ BẸ̀ WỌ́N WÒ

Ìwé ìròyìn Ji! No. 2 2016 | Ṣé Ìwé Dáradára Kan Lásán Ni Bíbélì?

Bó tilẹ̀ jẹ́ pé a fẹ́ pe àwọn èèyàn wá sí àpéjọ àgbègbè bó bá ti lè ṣeé ṣe tó, ó yẹ ká ṣe ìpadàbẹ̀wò sọ́dọ̀ àwọn tó nífẹ̀ẹ́ sí ọ̀rọ̀ wa.

Fi ìwé ìròyìn àti ìwé ìkésíni lọni pa pọ̀ ní òpin ọ̀sẹ̀.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́