ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb17 March ojú ìwé 6
  • Ran Ìdílé Rẹ Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Máa Rántí Jèhófà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ran Ìdílé Rẹ Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Máa Rántí Jèhófà
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ìrànlọ́wọ́ fún Àwọn Ìdílé
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2011
  • Ìjọsìn Ìdílé—Ǹjẹ́ O Lè Mú Kó Túbọ̀ Gbádùn Mọ́ni?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2014
  • ‘Kí Ọ̀rọ̀ Wọ̀nyí Wà ní Ọkàn Rẹ’
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2015
  • Ẹ Jọ Máa Sin Jèhófà Nínú Ìdílé Yín
    Ìdílé Rẹ Lè Jẹ́ Aláyọ̀
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
mwb17 March ojú ìwé 6

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Ran Ìdílé Rẹ Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Máa Rántí Jèhófà

Torí pé àwọn Júù ti pa Jèhófà Ọlọ́run wọn tì, Jèhófà rán Jeremáyà pé kó lọ kìlọ̀ nípa ìparun tó rọ̀ dẹ̀dẹ̀ sórí wọn. (Jer 13:25) Báwo ni orílẹ̀-èdè náà ṣe dénú ipò yìí? Àwọn ìdílé lórílẹ̀-èdè Ísírẹ́lì ti pàdánù àjọṣe wọn pẹ̀lú Jèhófà. Ohun tó sì fà á ni pé àwọn olórí ìdílé ò tẹ̀lé ìtọ́ni Jèhófà tó wà nínú Diutarónómì 6:​5-7.

Ìdílé olóbìí kan ń gbádùn Ìjọsìn Ìdílé wọn; Ìdílé kan ń lo àwòrán ilẹ̀ inú Bíbélì nígbà Ìjọsìn Ìdílé wọn

Lóde òní, tí ìdílé kọ̀ọ̀kan bá jiná dénú nípa tẹ̀mí, ó máa ń jẹ́ kí ìjọ dúró sán-ún. Àwọn olórí ìdílé lè ran ìdílé wọn lọ́wọ́ kí wọ́n lè máa rántí Jèhófà nípa ṣíṣe Ìjọsìn Ìdílé déédéé, kó sì nítumọ̀. (Sm 22:27) Lẹ́yìn tẹ́ ẹ bá ti wo fídíò ‘Kí Ọ̀rọ̀ Wọ̀nyí Wà ní Ọkàn Rẹ ​—Ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò, kí ẹ béèrè àwọn ìbéèrè yìí:

  • Báwo làwọn ìdílé kan ṣe yanjú ìṣòro tí kì í jẹ́ kí Ìjọsìn Ìdílé wọn lọ déédéé?

  • Àwọn àǹfààní wo ló wà nínú ká máa ṣe Ìjọsìn Ìdílé déédéé, tó sì nítumọ̀?

  • Tó bá dọ̀rọ̀ Ìjọsìn Ìdílé, kí làwọn ìpènijà tí mo ní, kí ni mo lè ṣe láti yanjú ẹ̀?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́