ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb17 May ojú ìwé 6
  • Má Ṣe “Wá Àwọn Ohun Ńláńlá fún Ara Rẹ”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Má Ṣe “Wá Àwọn Ohun Ńláńlá fún Ara Rẹ”
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Bárúkù Akọ̀wé Jeremáyà Tó Dúró Tì Í Gbágbáágbá
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2006
  • Má Ṣe “Wá Àwọn Ohun Ńláńlá fún Ara Rẹ”
    Ọ̀rọ̀ Tí Ọlọ́run Bá Wa Sọ Nípasẹ̀ Jeremáyà
  • Ní Àjọṣe Tó Dáa Pẹ̀lú Àwọn Ará Kí Òpin Tó Dé
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2019
  • “Mo Wà Pẹ̀lú Rẹ Láti Dá Ọ Nídè”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
mwb17 May ojú ìwé 6

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JEREMÁYÀ 44-48

Má Ṣe “Wá Àwọn Ohun Ńláńlá fún Ara Rẹ”

45:2-5

Ó ṣeé ṣe kó jẹ́ pé ìjòyè kan tó jẹ́ ọ̀mọ̀wé ni Bárúkù, ìdílé ọba ló sì ti wá. Bó tilẹ̀ jẹ́ pé tọkàntọkàn ló fi ń sin Jèhófà, tó sì ń ti Jeremáyà lẹ́yìn, ìgbà kan wà tí kò fọkàn sí àwọn nǹkan tẹ̀mí mọ́. Ó bẹ̀rẹ̀ sí í “wá àwọn ohun ńláńlá.” Ó ṣeé ṣe kó jẹ́ pé ó fẹ́ túbọ̀ di olókìkí láàfin ọba tàbí kó jẹ́ pé ó fẹ́ di olówó rẹpẹtẹ. Àmọ́, tó bá máa la ìparun tó rọ̀ dẹ̀dẹ̀ sórí Jerúsálẹ́mù já, ó yẹ kó tún èrò rẹ̀ ṣe.

Lákòókò tí Bárúkù fi jẹ́ akọ̀wé Jeremáyà, ńṣe ló ń ronú ṣáá nípa bó ṣe máa di ọlọ́rọ̀ àti olókìkí
Àtẹ tó ṣàfihàn ìgbà tí Jeremáyà bẹ̀rẹ̀ sí sàsọtẹ́lẹ̀, ìgbà tí Bárúkù bẹ̀rẹ̀ sí ràn án lọ́wọ́ àti ìgbà tí Jerúsálẹ̀mu pa run
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́