ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 December ojú ìwé 8
  • Ilẹ̀ ‘Gbé Odò Náà Mì’

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ilẹ̀ ‘Gbé Odò Náà Mì’
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ìròyìn Nípa Àwọn Ẹjọ́
    Ìwé Ọdọọdún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—2014
  • Àwọn Akéde Ìjọba Ọlọ́run Gbé Ọ̀rọ̀ Lọ Sílé Ẹjọ́
    Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso!
  • Máa Rántí Gbàdúrà Fáwọn Kristẹni Tí Wọ́n Ń Ṣe Inúnibíni Sí
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
  • A Bí Ìjọba Ọlọ́run!
    Ìṣípayá—Ìparí Rẹ̀ Ológo Kù sí Dẹ̀dẹ̀!
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 December ojú ìwé 8
Ìwé òfin látọwọ́ Ìparapọ̀ Àwọn Orílẹ̀-èdè àtàwọn arákùnrin wa tó wà lẹ́wọ̀n lórílè-èdè Kòríà

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

‘Ilẹ̀ Gbé Odò Náà Mì’

Láyé àtijọ́, ọ̀pọ̀ ìgbà làwọn aláṣẹ ayé ti ran àwọn èèyàn Jèhófà lọ́wọ́. (Ẹsr 6:1-12; Ẹst 8:10-13) Bákan náà lónìí, a ti rí ìgbà tí “ilẹ̀” ìyẹn apá kan lára ètò ayé yìí ti gba tàwọn èèyàn Ọlọ́run rò, tí wọ́n sì “gbé odò” inúnibíni tí “dírágónì náà” ìyẹn Sátánì Èṣù pọ̀ látẹnu rẹ̀ mì. (Ifi 12:16) Nígbà míì, Jèhófà tó jẹ́ ‘Ọlọ́run tó ń gbani là’ lè lo àwọn aláṣẹ ayé yìí láti pèsè ìtura fáwọn èèyàn rẹ̀.​—Sm 68:20; Owe 21:1.

Ká wá sọ pé wọ́n jù ẹ́ sẹ́wọ̀n nítorí ohun tó o gbà gbọ́ ńkọ́? Má mikàn rárá, fi sọ́kàn pé Jèhófà ń rí ẹ níbi tó o wà. (Jẹ 39:21-23; Sm 105:17-20) Jẹ́ kó dá ẹ lójú pé Jèhófà máa san ẹ́ lẹ́san fún ìgbàgbọ́ tó o ní àti pé ìdúróṣinṣin rẹ máa fún àwọn ará kárí ayé níṣìírí.​—Flp 1:12-14; Ifi 2:10.

JẸ́ KÍ ÀWỌN ARÁ WO FÍDÍÒ NÁÀ WỌ́N DÁ ÀWỌN ARÁ WA SÍLẸ̀ LẸ́WỌ̀N NÍ KOREA, LẸ́YÌN NÁÀ, Ẹ DÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ YÌÍ:

  • Kí nìdí tí wọ́n fi ju ọ̀pọ̀ àwọn arákùnrin wa sẹ́wọ̀n lórílẹ̀-èdè South Korea láwọn ọdún yìí wá?

  • Ìdájọ́ wo ló mú kí wọ́n tètè dá àwọn arákùnrin wa sílẹ̀?

  • Báwo la ṣe lè ṣèrànwọ́ fáwọn ará wa tó wà lẹ́wọ̀n báyìí torí ìgbàgbọ́ wọn?

  • Báwo ló ṣe yẹ ká lo òmìnira tá a ní báyìí?

  • Ta ni ìyìn àti ògo yẹ fún àṣeyọrí èyíkéyìí tá a bá ṣe nílé ẹjọ́?

Ọgbà ẹ̀wọ̀n tí wọ́n fi àwọn ará wá sí nígbà kan lórílè-èdè Kòríà; lẹ́tà táwọn ará kọ sí ẹ̀ka ọ́fíìsì wa lórílẹ̀-èdè Kòríà, ẹ̀ka ọ́fíìsì fi àwọn lẹ́tà náà ránṣẹ́ sáwọn ará tó wà lẹ́wọ̀n; bàbá kan ń dì mọ́ ọmọ rẹ̀ lẹ́yìn tí wọ́n tún pa dà ríra wọn

Báwo ni mo ṣe ń lo òmìnira tí mo ní?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́