ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 March ojú ìwé 5
  • Jékọ́bù Gba Ìbùkún Tó Tọ́ Sí I

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jékọ́bù Gba Ìbùkún Tó Tọ́ Sí I
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Jékọ́bù àti Ísọ̀ Parí Ìjà Wọn
    Àwọn Ẹ̀kọ́ Tó O Lè Kọ́ Látinú Bíbélì
  • Àwọn Ìbejì Tí Wọn Ò Jọra
    Ìwé Ìtàn Bíbélì
  • Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2007
  • Jékọ́bù Rí Ogún Gbà
    Àwọn Ẹ̀kọ́ Tó O Lè Kọ́ Látinú Bíbélì
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 March ojú ìwé 5
Jékọ́bù wọ aṣọ Ísọ̀ ó fi irun ewúrẹ́ bo ọwọ́ àti ọrùn rẹ̀, Ísákì sì dí ọwọ́ Jékọ́bù mú.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JẸ́NẸ́SÍSÌ 27-28

Jékọ́bù Gba Ìbùkún Tó Tọ́ Sí I

27:6-10, 18, 19, 27-29

Àsọtẹ́lẹ̀ kan ti wà pé Jékọ́bù máa gba ìbùkún tó jẹ́ ti àkọ́bí.

  • Àwòrán Ilẹ̀ Ìlérí tó fi bí ilẹ̀ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tó lọ́ràá ṣe dáa ju ilẹ̀ àwọn ọmọ Édómù tó gbẹ táútáú.

    27:28​—Jèhófà fún àwọn àtọmọdọ́mọ Jékọ́bù ní ilẹ̀ ọlọ́ràá “tí wàrà àti oyin ti ń ṣàn.”​—Di 26:15

  • 27:29​—Nígbà tó yá, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tó jẹ́ àtọmọdọ́mọ Jékọ́bù lágbára ju àwọn ọmọ Édómù tó jẹ́ àtọmọdọ́mọ Ísọ̀ lọ.​—Jẹ 25:23; 2Sa 8:14

  • 27:29​—Jèhófà gégùn-ún fún àwọn ọmọ Édómù torí pé wọ́n kórìíra àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, orílẹ̀-èdè wọn sì pa run pátápátá.​—Isk 25:12-14

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́