ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 October ojú ìwé 7
  • Ohun Tí Pẹpẹ Àgọ́ Ìjọsìn Wà Fún

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tí Pẹpẹ Àgọ́ Ìjọsìn Wà Fún
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Bí Ọjọ́ Ètùtù Ṣe Kàn Ẹ́
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Tùràrí Sísun Ǹjẹ́ Ó Lóhun Tó Ń Ṣe Nínú Ìjọsìn Tòótọ́?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2003
  • Pẹpẹ—Kí Ni Ìlò Rẹ̀ Nínú Ìjọsìn?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2003
  • O Ha ‘Ń pèsè Àdúrà Rẹ Bí Tùràrí’ bí?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1999
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 October ojú ìwé 7
Bí inú Àgọ́ ìjọsìn ṣe rí tí wọ́n bá ṣí àwọn aṣọ tí wọ́n fi bò ó. Bàsíà bàbà àti pẹpẹ ẹbọ sísun wà nítòsí ẹ̀.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | Ẹ́KÍSÓDÙ 37-38

Ohun Tí Pẹpẹ Àgọ́ Ìjọsìn Wà Fún

37:​25, 29; 38:1

Jèhófà ló fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ní ìtọ́ni nípa bí wọ́n ṣe máa kọ́ àgọ́ ìjọsìn, ó sì nídìí pàtàkì tó fi ní kí wọ́n ṣe é bẹ́ẹ̀.

  • Pẹpẹ tùràrí.

    Bíi ti tùràrí olóòórùn dídùn táwọn ọmọ Ísírẹ́lì máa ń sun, inú Jèhófà máa ń dùn táwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ bá ń gbàdúrà sí i

  • Pẹpẹ ẹbọ sísun.

    Táwọn ọmọ Ísírẹ́lì bá rúbọ lórí pẹpẹ ẹbọ sísun, Jèhófà máa ń tẹ́wọ́ gbà á. Ìwájú ibi mímọ́ ni pẹpẹ yìí wà, èyí jẹ́ ká rí i pé a gbọ́dọ̀ nígbàgbọ́ nínú ẹbọ ìràpadà Jésù kínú Ọlọ́run tó lè dùn sí wa.​—Jo 3:​16-18; Heb 10:​5-10

Báwo la ṣe lè mú kí àdúrà wa dà bíi tùràrí olóòórùn dídùn sí Ọlọ́run?​—Sm 141:2

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́