ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 January ojú ìwé 15
  • Báwo Lo Ṣe Lè Fìwà Jọ Àwọn Násírì?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Báwo Lo Ṣe Lè Fìwà Jọ Àwọn Násírì?
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ohun Tá A Kọ́ Lára Àwọn Násírì
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2024
  • Jèhófà Sọ Ègún Di Ìbùkún
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Iṣẹ́ Ìsìn Àwọn Ọmọ Léfì
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Ohun Tá A Rí Kọ́ Látinú Bí Jèhófà Ṣe Ṣètò Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 January ojú ìwé 15

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Báwo Lo Ṣe Lè Fìwà Jọ Àwọn Násírì?

Àwọn Násírì máa ń fi ọ̀pọ̀ nǹkan du ara wọn (Nọ 6:2-4; it-2 477)

Tọkàntọkàn làwọn Násírì fi máa ń ṣe ohun tí Jèhófà fẹ́ (Nọ 6:5)

Gbogbo ohun tí Jèhófà ní kí wọ́n ṣe ni wọ́n máa ń ṣe kí wọ́n lè jẹ́ mímọ́ (Nọ 6:6, 7)

Lónìí, àwọn òjíṣẹ́ alákòókò kíkún máa ń fi ọ̀pọ̀ nǹkan du ara wọn, wọ́n múra tán láti ṣe ohun tí Jèhófà fẹ́, wọ́n sì ń fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú ètò Ọlọ́run.

Àwòrán: Àwọn arákùnrin àti arábìnrin tó ń ṣe iṣẹ́ ìsìn alákòókò kíkún. 1. Àwọn arákùnrin méjì tó jẹ́ aṣáájú-ọ̀nà ń wàásù fún bàbá kan lórí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́. 2. Arákùnrin àti arábìnrin kan wà lẹ́nu iṣẹ́ ìkọ́lé.
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́