ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 November ojú ìwé 10
  • Sùúrù Jèhófà Níbi Tó Mọ

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Sùúrù Jèhófà Níbi Tó Mọ
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Jèhófà Ṣe Ohun Tó Dà Bíi Pé Kò Ṣeé Ṣe
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Jèhófà Fìyà Jẹ Obìnrin Burúkú Kan
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Máa Fi Ọjọ́ Jèhófà Sọ́kàn
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àwọn Tó Wà Pẹ̀lú Wa Pọ̀ Ju Àwọn Tó Wà Pẹ̀lú Wọn
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 November ojú ìwé 10
Jésù àtàwọn ọmọ ogun ọ̀run gun ẹṣin funfun, wọ́n sì pa àwọn ọ̀tá Ọlọ́run tó wà láyé.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Sùúrù Jèhófà Níbi Tó Mọ

Jèhófà jẹ́ kí àwọn ará Ásíríà ṣẹ́gun àwọn ọmọ Ísírẹ́lì (2Ọb 17:5, 6; it-2 908 ¶5)

Jèhófà bá àwọn èèyàn rẹ̀ wí torí pé wọn ò jáwọ́ nínú ìwà burúkú wọn (2Ọb 17:9-12; it-1 414-415)

Jèhófà mú sùúrù fáwọn ọmọ Ísírẹ́lì, léraléra ló sì ń kìlọ̀ fún wọn (2Ọb 17:13, 14)

Baba wa ọ̀run nífẹ̀ẹ́ wa, ó sì ń mú sùúrù fáwa èèyàn aláìpé. (2Pe 3:9) Síbẹ̀, ó máa pa àwọn èèyàn burúkú run láìpẹ́ kí ohun tó ní lọ́kàn lè ṣẹ. Ó yẹ kí èyí mú ká túbọ̀ jára mọ́ iṣẹ́ ìwàásù, ká sì ṣe àwọn àyípadà tó yẹ tí wọ́n bá bá wa wí?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́