ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 January ojú ìwé 3
  • Máa Fi Ọjọ́ Jèhófà Sọ́kàn

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Máa Fi Ọjọ́ Jèhófà Sọ́kàn
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Sùúrù Jèhófà Níbi Tó Mọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Jèhófà Ṣe Ohun Tó Dà Bíi Pé Kò Ṣeé Ṣe
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀?
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • “Gbé Ọmọ Rẹ”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 January ojú ìwé 3

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Máa Fi Ọjọ́ Jèhófà Sọ́kàn

Ọ̀pọ̀ ọdún ni Jèhófà fi kìlọ̀ fún àwọn èèyàn Júdà pé òun máa kọ̀ wọ́n tí wọn ò bá jáwọ́ nínú ìwà búburú wọn (2Ọb 24:2, 3; w01 2/15 12 ¶2)

Jèhófà lo àwọn ará Bábílónì láti pa Jerúsálẹ́mù run lọ́dún 607 Ṣ.S.K. (2Ọb 25:8-10; w07 3/15 11 ¶10)

Jèhófà dáàbò bo àwọn tó fetí sí ìkìlọ̀ rẹ̀ (2Ọb 25:11)

Arákùnrin kan ń wàásù fún ẹni tí wọ́n jọ ń ṣiṣẹ́ nígbà ìsinmi ọ̀sán.

Ọjọ́ pẹ́ tí Jèhófà ti ń kìlọ̀ fáwọn èèyàn pé òun máa mú ìdájọ́ wá sórí “àwọn èèyàn tí kò ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run.”​—2Pe 3:7.

BI ARA RẸ PÉ, ‘Ṣé mò ń lo gbogbo àǹfààní tó bá yọ láti ran àwọn èèyàn lọ́wọ́ kí wọ́n lè gbọ́ ìkìlọ̀ Jèhófà?’​—2Ti 4:2.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́