ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | AÍSÁYÀ 47-51
Jèhófà Máa Bù Kún Wa Tá A Bá Ṣègbọràn Sí I
Jèhófà nífẹ̀ẹ́ wa, torí náà ó ń mú ká máa tọ ‘ọ̀nà tí ó yẹ kí a máa rìn,’ ká báa lè gbádùn ìgbésí ayé wa. Tá a bá ṣègbọràn sí i, àwa la máa jàǹfààní ẹ̀
“Àlàáfíà . . . dà bí odò”
Jèhófà ṣèlérí pé òun máa fún wa ní àlááfíà lọ́pọ̀ yanturu, tí kò sì ní lópin bí odò
“Òdodo . . . bí ìgbì òkun”
Ìwa òdodo wa yóò pọ̀ lọ súà, kò sì ní lóǹkà bí ìgbì òkun