ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 18:15, 16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Mósè sọ fún bàbá ìyàwó rẹ̀ pé: “Torí pé àwọn èèyàn ń wá sọ́dọ̀ mi kí n lè bá wọn wádìí ọ̀rọ̀ lọ́wọ́ Ọlọ́run ni. 16 Tí ẹjọ́ kan bá délẹ̀, wọ́n á gbé e wá sọ́dọ̀ mi, màá sì ṣèdájọ́ ẹnì kìíní àti ẹnì kejì, màá jẹ́ kí wọ́n mọ àwọn ìpinnu Ọlọ́run tòótọ́ àti àwọn òfin rẹ̀.”+

  • Ẹ́kísódù 33:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Jèhófà bá Mósè sọ̀rọ̀ ní ojúkojú,+ bí ìgbà téèyàn méjì ń bá ara wọn sọ̀rọ̀. Nígbà tó pa dà sọ́dọ̀ àwọn èèyàn náà, Jóṣúà+ ọmọ Núnì, òjíṣẹ́ rẹ̀ àti ìránṣẹ́ rẹ̀+ ò kúrò níbi àgọ́ náà.

  • Léfítíkù 24:11, 12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Ọmọkùnrin tí ìyá rẹ̀ jẹ́ ọmọ Ísírẹ́lì náà wá bẹ̀rẹ̀ sí í tàbùkù sí Orúkọ náà,* ó sì ń sọ̀rọ̀ òdì sí i.*+ Torí náà, wọ́n mú un wá sọ́dọ̀ Mósè.+ Ó ṣẹlẹ̀ pé, Ṣẹ́lómítì ni orúkọ ìyá rẹ̀, ọmọ Díbírì látinú ẹ̀yà Dánì. 12 Wọ́n fi ọmọkùnrin náà sínú àhámọ́ títí ìpinnu Jèhófà fi ṣe kedere sí wọn.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́