ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 19
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Ọ̀rọ̀ ìkéde sí Íjíbítì (1-15)

      • Íjíbítì máa mọ Jèhófà (16-25)

        • Pẹpẹ kan máa wà fún Jèhófà ní Íjíbítì (19)

Àìsáyà 19:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 25:17, 19; Isk 29:2; Joẹ 3:19
  • +Ẹk 12:12; Jer 43:12; 46:25; Isk 30:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 201

Àìsáyà 19:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 200-202

Àìsáyà 19:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 19:11, 13
  • +Ais 8:19; Iṣe 16:16; Ifi 18:23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 200-202

Àìsáyà 19:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 20:3, 4; Jer 46:25, 26; Isk 29:19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 200-202

Àìsáyà 19:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 30:12; Sek 10:11

Àìsáyà 19:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, koríko etí omi.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 2:3

Àìsáyà 19:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 11:10
  • +Isk 29:10

Àìsáyà 19:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 9:25, 31; Owe 7:16

Àìsáyà 19:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ni ọkàn wọn máa gbọgbẹ́.”

Àìsáyà 19:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 78:12; Isk 30:14
  • +Ais 44:25

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 202-203

Àìsáyà 19:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 41:8; 1Ọb 4:30; Iṣe 7:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 202-203

Àìsáyà 19:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Mémúfísì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 46:14; Isk 30:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 202-203

Àìsáyà 19:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Job 12:20, 24; Ais 19:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 202-203

Àìsáyà 19:15

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “imọ̀ ọ̀pẹ tàbí koríko etí omi.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 202-203

Àìsáyà 19:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 11:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 203-204

Àìsáyà 19:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 20:3, 4; Jer 25:17, 19; 43:10, 11; Isk 29:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 203-204

Àìsáyà 19:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 43:4, 7; 44:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 204

Àìsáyà 19:19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2000, ojú ìwé 9-10

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 204-205

Àìsáyà 19:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2000, ojú ìwé 9-10

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 205

Àìsáyà 19:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 205-206

Àìsáyà 19:22

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 19:1; Jer 46:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 205-206

Àìsáyà 19:23

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 11:16; 35:8; 40:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 206-207

Àìsáyà 19:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sek 2:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 206-207

Àìsáyà 19:25

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 32:9; Sm 115:12; Ais 61:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 206-207

Àwọn míì

Àìsá. 19:1Jer 25:17, 19; Isk 29:2; Joẹ 3:19
Àìsá. 19:1Ẹk 12:12; Jer 43:12; 46:25; Isk 30:13
Àìsá. 19:3Ais 19:11, 13
Àìsá. 19:3Ais 8:19; Iṣe 16:16; Ifi 18:23
Àìsá. 19:4Ais 20:3, 4; Jer 46:25, 26; Isk 29:19
Àìsá. 19:5Isk 30:12; Sek 10:11
Àìsá. 19:6Ẹk 2:3
Àìsá. 19:7Di 11:10
Àìsá. 19:7Isk 29:10
Àìsá. 19:9Ẹk 9:25, 31; Owe 7:16
Àìsá. 19:11Sm 78:12; Isk 30:14
Àìsá. 19:11Ais 44:25
Àìsá. 19:12Jẹ 41:8; 1Ọb 4:30; Iṣe 7:22
Àìsá. 19:13Jer 46:14; Isk 30:13
Àìsá. 19:14Job 12:20, 24; Ais 19:3
Àìsá. 19:16Ais 11:15
Àìsá. 19:17Ais 20:3, 4; Jer 25:17, 19; 43:10, 11; Isk 29:6
Àìsá. 19:18Jer 43:4, 7; 44:1
Àìsá. 19:22Ais 19:1; Jer 46:13
Àìsá. 19:23Ais 11:16; 35:8; 40:3
Àìsá. 19:24Sek 2:11
Àìsá. 19:25Di 32:9; Sm 115:12; Ais 61:9
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 19:1-25

Àìsáyà

19 Ọ̀rọ̀ ìkéde sí Íjíbítì:+

Wò ó! Jèhófà gun àwọsánmà tó ń yára kánkán, ó sì ń bọ̀ wá sí Íjíbítì.

Àwọn ọlọ́run Íjíbítì tí kò ní láárí máa gbọ̀n rìrì níwájú rẹ̀,+

Ọkàn Íjíbítì sì máa domi nínú rẹ̀.

 2 “Màá mú kí àwọn ọmọ Íjíbítì dojú kọ ara wọn,

Wọ́n á sì bá ara wọn jà,

Kálukú máa bá arákùnrin rẹ̀ àti ọmọnìkejì rẹ̀ jà,

Ìlú máa bá ìlú jà, ìjọba sì máa bá ìjọba jà.

 3 Ìdààmú sì máa bá Íjíbítì láàárín rẹ̀,

Màá sì da àwọn ohun tó ń gbèrò rú.+

Wọ́n máa yíjú sí àwọn ọlọ́run tí kò ní láárí,

Àwọn atujú, àwọn abẹ́mìílò àti àwọn woṣẹ́woṣẹ́.+

 4 Màá fa Íjíbítì lé ọ̀gá tó le lọ́wọ́,

Ọba tó sì burú máa jẹ lé wọn lórí,”+ ni Olúwa tòótọ́, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí.

 5 Omi òkun máa gbẹ,

Kò ní sí omi nínú odò, ó sì máa gbẹ táútáú.+

 6 Àwọn odò á máa rùn;

Àwọn ipa odò Náílì nílẹ̀ Íjíbítì máa fà, ó sì máa gbẹ táútáú.

Àwọn esùsú* àti koríko etídò máa jẹrà.+

 7 Àwọn ewéko tó wà létí odò Náílì, ní bèbè Náílì,

Àti gbogbo ilẹ̀ tí wọ́n fúnrúgbìn sí létí odò Náílì+ máa gbẹ.+

Ó máa fẹ́ lọ, kò sì ní sí mọ́.

 8 Àwọn apẹja máa ṣọ̀fọ̀,

Àwọn tó ń ju ìwọ̀ ẹja sínú odò Náílì máa dárò,

Àwọn tó sì ń na àwọ̀n ìpẹja wọn sí ojú omi máa dín kù.

 9 Ojú máa ti àwọn tó ń ya ọ̀gbọ̀+

Àti àwọn tó ń hun aṣọ funfun.

10 Wọ́n máa tẹ àwọn ahunṣọ rẹ̀ rẹ́;

Gbogbo alágbàṣe rẹ̀ máa kẹ́dùn.*

11 Òmùgọ̀ ni àwọn olórí Sóánì.+

Ìmọ̀ràn tí kò bọ́gbọ́n mu làwọn tó gbọ́n jù nínú àwọn agbani-nímọ̀ràn Fáráò ń mú wá.+

Báwo lẹ ṣe máa sọ fún Fáráò pé:

“Àtọmọdọ́mọ àwọn ọlọ́gbọ́n ni mí,

Àtọmọdọ́mọ àwọn ọba àtijọ́”?

12 Àwọn ọlọ́gbọ́n rẹ wá dà?+

Jẹ́ kí wọ́n sọ fún ọ, tí wọ́n bá mọ ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ti pinnu nípa Íjíbítì.

13 Àwọn olórí Sóánì ti hùwà òpònú;

Wọ́n ti tan àwọn olórí Nófì*+ jẹ;

Àwọn ìjòyè àwọn ẹ̀ya rẹ̀ ti kó Íjíbítì ṣìnà.

14 Jèhófà ti fi ẹ̀mí ìdàrúdàpọ̀ kọ lù ú;+

Wọ́n sì ti kó Íjíbítì ṣìnà nínú gbogbo ohun tó ń ṣe,

Bí ọ̀mùtí tó ń ta gọ̀ọ́gọ̀ọ́ nínú èébì rẹ̀.

15 Íjíbítì ò sì ní rí iṣẹ́ kankan ṣe,

Ì báà jẹ́ orí tàbí ìrù, ọ̀mùnú tàbí koríko etídò.*

16 Ní ọjọ́ yẹn, Íjíbítì máa dà bí obìnrin, ó máa gbọ̀n rìrì, ẹ̀rù á sì máa bà á torí ọwọ́ ìhàlẹ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun gbé sókè sí i.+ 17 Ilẹ̀ Júdà sì máa di ohun ìbẹ̀rù fún Íjíbítì. Tí wọ́n bá gbọ́ orúkọ rẹ̀, ẹ̀rù máa bà wọ́n torí ìpinnu tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ti ṣe lòdì sí wọn.+

18 Ní ọjọ́ yẹn, ìlú márùn-ún máa wà nílẹ̀ Íjíbítì tí wọ́n ń sọ èdè Kénáánì,+ tí wọ́n á sì búra pé àwọn máa dúró ti Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun. Ìlú kan á máa jẹ́ Ìlú Ìyalulẹ̀.

19 Ní ọjọ́ yẹn, pẹpẹ kan máa wà fún Jèhófà ní àárín ilẹ̀ Íjíbítì, òpó kan sì máa wà fún Jèhófà níbi ààlà rẹ̀. 20 Ó máa jẹ́ àmì àti ẹ̀rí sí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun nílẹ̀ Íjíbítì; torí wọ́n máa ké pe Jèhófà nítorí àwọn aninilára, ó sì máa rán olùgbàlà kan sí wọn, ẹni tó tóbi lọ́lá, tó máa gbà wọ́n là. 21 Jèhófà máa jẹ́ kí àwọn ọmọ Íjíbítì mọ òun, àwọn ọmọ Íjíbítì sì máa mọ Jèhófà ní ọjọ́ yẹn, wọ́n máa rúbọ, wọ́n á mú ẹ̀bùn wá, wọ́n á jẹ́jẹ̀ẹ́ fún Jèhófà, wọ́n á sì san án. 22 Jèhófà máa kọ lu Íjíbítì,+ á kọ lù ú, á sì wò ó sàn; wọ́n á pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà, á gbọ́ ẹ̀bẹ̀ wọn, á sì wò wọ́n sàn.

23 Ní ọjọ́ yẹn, ọ̀nà kan máa jáde+ láti Íjíbítì lọ sí Ásíríà. Ásíríà máa wá sí Íjíbítì, Íjíbítì sì máa lọ sí Ásíríà, Íjíbítì àti Ásíríà sì jọ máa sin Ọlọ́run. 24 Ní ọjọ́ yẹn, Ísírẹ́lì máa ṣe ìkẹta Íjíbítì àti Ásíríà,+ àwọn tí a bù kún ní àárín ayé, 25 torí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ti máa súre fún un pé: “Ìbùkún ni fún àwọn èèyàn mi, Íjíbítì, àti iṣẹ́ ọwọ́ mi, Ásíríà, àti ogún mi, Ísírẹ́lì.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́