ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 10
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jẹ́nẹ́sísì

      • Àwọn orílẹ̀-èdè (1-32)

        • Àtọmọdọ́mọ Jáfẹ́tì (2-5)

        • Àtọmọdọ́mọ Hámù (6-20)

          • Nímírọ́dù ta ko Jèhófà (8-12)

        • Àtọmọdọ́mọ Ṣémù (21-31)

Jẹ́nẹ́sísì 10:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Lk 3:23, 36
  • +Jẹ 9:18, 19

Jẹ́nẹ́sísì 10:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 38:6
  • +Isk 38:2
  • +Ais 66:19; Isk 27:13
  • +Sm 120:5; Isk 32:26
  • +1Kr 1:5-7

Jẹ́nẹ́sísì 10:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 51:27
  • +Isk 27:14; 38:6

Jẹ́nẹ́sísì 10:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 27:7
  • +Jon 1:3
  • +Ais 23:1

Jẹ́nẹ́sísì 10:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 50:11
  • +Jer 46:9; Na 3:9
  • +Nọ 34:2; 1Kr 1:8-10

Jẹ́nẹ́sísì 10:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 72:10
  • +Isk 27:22

Jẹ́nẹ́sísì 10:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Àwọn ìlú tó kọ́kọ́ wà lábẹ́ ìjọba rẹ̀ ni.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 11:9
  • +Ẹsr 4:9
  • +Da 1:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 1/2020, ojú ìwé 6

Jẹ́nẹ́sísì 10:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mik 5:6
  • +Jon 3:3; Mt 12:41

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    6/1/1993, ojú ìwé 5-7

Jẹ́nẹ́sísì 10:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “Wọ́n para pọ̀ di ìlú ńlá náà.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    6/1/1993, ojú ìwé 5

Jẹ́nẹ́sísì 10:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 46:9
  • +1Kr 1:11, 12

Jẹ́nẹ́sísì 10:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 29:14
  • +Joṣ 13:2, 3; Jer 47:4
  • +Di 2:23

Jẹ́nẹ́sísì 10:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 13:6; Mk 7:24
  • +Jẹ 25:10; 27:46; 1Kr 1:13-16

Jẹ́nẹ́sísì 10:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ond 1:21
  • +Jẹ 15:16; Di 3:8

Jẹ́nẹ́sísì 10:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 11:3

Jẹ́nẹ́sísì 10:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 27:11
  • +1Ọb 8:65

Jẹ́nẹ́sísì 10:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 20:1
  • +Joṣ 15:20, 47; Iṣe 8:26
  • +Jẹ 13:10; 19:24; Jud 7
  • +Di 29:23

Jẹ́nẹ́sísì 10:21

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “òun sì ni ẹ̀gbọ́n Jáfẹ́tì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 11:17

Jẹ́nẹ́sísì 10:22

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹsr 4:9; Iṣe 2:8, 9
  • +Isk 27:23
  • +Jẹ 11:10
  • +1Kr 1:17

Jẹ́nẹ́sísì 10:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 11:12; Lk 3:23, 35

Jẹ́nẹ́sísì 10:25

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ó túmọ̀ sí “Pín Sọ́tọ̀.”

  • *

    Tàbí “aráyé.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 11:16
  • +1Kr 1:19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2004, ojú ìwé 31

Jẹ́nẹ́sísì 10:26

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kr 1:20-23

Jẹ́nẹ́sísì 10:29

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 9:28; 10:11

Jẹ́nẹ́sísì 10:31

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 10:5

Jẹ́nẹ́sísì 10:32

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 9:7, 19; Iṣe 17:26

Àwọn míì

Jẹ́n. 10:1Lk 3:23, 36
Jẹ́n. 10:1Jẹ 9:18, 19
Jẹ́n. 10:2Isk 38:6
Jẹ́n. 10:2Isk 38:2
Jẹ́n. 10:2Ais 66:19; Isk 27:13
Jẹ́n. 10:2Sm 120:5; Isk 32:26
Jẹ́n. 10:21Kr 1:5-7
Jẹ́n. 10:3Jer 51:27
Jẹ́n. 10:3Isk 27:14; 38:6
Jẹ́n. 10:4Isk 27:7
Jẹ́n. 10:4Jon 1:3
Jẹ́n. 10:4Ais 23:1
Jẹ́n. 10:6Jẹ 50:11
Jẹ́n. 10:6Jer 46:9; Na 3:9
Jẹ́n. 10:6Nọ 34:2; 1Kr 1:8-10
Jẹ́n. 10:7Sm 72:10
Jẹ́n. 10:7Isk 27:22
Jẹ́n. 10:10Jẹ 11:9
Jẹ́n. 10:10Ẹsr 4:9
Jẹ́n. 10:10Da 1:2
Jẹ́n. 10:11Mik 5:6
Jẹ́n. 10:11Jon 3:3; Mt 12:41
Jẹ́n. 10:13Jer 46:9
Jẹ́n. 10:131Kr 1:11, 12
Jẹ́n. 10:14Isk 29:14
Jẹ́n. 10:14Joṣ 13:2, 3; Jer 47:4
Jẹ́n. 10:14Di 2:23
Jẹ́n. 10:15Joṣ 13:6; Mk 7:24
Jẹ́n. 10:15Jẹ 25:10; 27:46; 1Kr 1:13-16
Jẹ́n. 10:16Ond 1:21
Jẹ́n. 10:16Jẹ 15:16; Di 3:8
Jẹ́n. 10:17Joṣ 11:3
Jẹ́n. 10:18Isk 27:11
Jẹ́n. 10:181Ọb 8:65
Jẹ́n. 10:19Jẹ 20:1
Jẹ́n. 10:19Joṣ 15:20, 47; Iṣe 8:26
Jẹ́n. 10:19Jẹ 13:10; 19:24; Jud 7
Jẹ́n. 10:19Di 29:23
Jẹ́n. 10:21Jẹ 11:17
Jẹ́n. 10:22Ẹsr 4:9; Iṣe 2:8, 9
Jẹ́n. 10:22Isk 27:23
Jẹ́n. 10:22Jẹ 11:10
Jẹ́n. 10:221Kr 1:17
Jẹ́n. 10:24Jẹ 11:12; Lk 3:23, 35
Jẹ́n. 10:25Jẹ 11:16
Jẹ́n. 10:251Kr 1:19
Jẹ́n. 10:261Kr 1:20-23
Jẹ́n. 10:291Ọb 9:28; 10:11
Jẹ́n. 10:31Jẹ 10:5
Jẹ́n. 10:32Jẹ 9:7, 19; Iṣe 17:26
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
  • 28
  • 29
  • 30
  • 31
  • 32
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Jẹ́nẹ́sísì 10:1-32

Jẹ́nẹ́sísì

10 Ìtàn àwọn ọmọ Nóà nìyí, Ṣémù,+ Hámù àti Jáfẹ́tì.

Wọ́n bí àwọn ọmọ lẹ́yìn Ìkún Omi.+ 2 Àwọn ọmọ Jáfẹ́tì ni Gómérì,+ Mágọ́gù,+ Mádáì, Jáfánì, Túbálì,+ Méṣékì+ àti Tírásì.+

3 Àwọn ọmọ Gómérì ni Áṣíkénásì,+ Rífátì àti Tógámà.+

4 Àwọn ọmọ Jáfánì ni Élíṣáhì,+ Táṣíṣì,+ Kítímù+ àti Dódánímù.

5 Ọ̀dọ̀ wọn ni àwọn tó ń gbé àwọn erékùṣù ti tàn ká àwọn ilẹ̀ wọn, gẹ́gẹ́ bí èdè wọn, ìdílé wọn àti orílẹ̀-èdè wọn.

6 Àwọn ọmọ Hámù ni Kúṣì, Mísíráímù,+ Pútì+ àti Kénáánì.+

7 Àwọn ọmọ Kúṣì ni Sébà,+ Háfílà, Sábítà, Ráámà+ àti Sábítékà.

Àwọn ọmọ Ráámà sì ni Ṣébà àti Dédánì.

8 Kúṣì bí Nímírọ́dù. Òun ló kọ́kọ́ di alágbára ní ayé. 9 Ó di ọdẹ alágbára tó ń ta ko Jèhófà. Ìdí nìyẹn tí wọ́n fi máa ń sọ pé: “Bíi Nímírọ́dù ọdẹ alágbára tó ta ko Jèhófà.” 10 Ibi tí ìjọba rẹ̀ ti bẹ̀rẹ̀ ni* Bábélì,+ Érékì,+ Ákádì àti Kálínè, ní ilẹ̀ Ṣínárì.+ 11 Láti ibẹ̀, ó lọ sí Ásíríà,+ ó sì kọ́ Nínéfè,+ Rehoboti-Írì, Kálà 12 àti Résénì, láàárín Nínéfè àti Kálà: Èyí ni ìlú ńlá náà.*

13 Mísíráímù bí Lúdímù,+ Ánámímù, Léhábímù, Náfítúhímù,+ 14 Pátírúsímù,+ Kásílúhímù (ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni àwọn Filísínì+ ti wá) àti Káfítórímù.+

15 Kénáánì bí Sídónì+ àkọ́bí rẹ̀ àti Hétì+ 16 àti àwọn ará Jébúsì,+ àwọn Ámórì,+ àwọn Gẹ́gáṣì, 17 àwọn Hífì,+ àwọn Ákì, àwọn Sáínì, 18 àwọn Áfádì,+ àwọn Sémárì àti àwọn Hámátì.+ Lẹ́yìn náà, àwọn ìdílé àwọn ọmọ Kénáánì tàn káàkiri. 19 Ààlà àwọn ọmọ Kénáánì bẹ̀rẹ̀ láti Sídónì títí lọ dé Gérárì,+ nítòsí Gásà,+ títí lọ dé Sódómù, Gòmórà,+ Ádímà àti Sébóíímù,+ nítòsí Láṣà. 20 Àwọn ọmọ Hámù nìyí, bí wọ́n ṣe wà nínú ìdílé wọn, èdè wọn, ilẹ̀ wọn àti orílẹ̀-èdè wọn.

21 Ṣémù náà bímọ, òun ni baba ńlá gbogbo àwọn ọmọ Ébérì,+ òun sì ni arákùnrin Jáfẹ́tì tó jẹ́ ẹ̀gbọ́n pátápátá.* 22 Àwọn ọmọ Ṣémù ni Élámù,+ Áṣúrì,+ Ápákíṣádì,+ Lúdì àti Árámù.+

23 Àwọn ọmọ Árámù ni Úsì, Húlì, Gétérì àti Máṣì.

24 Ápákíṣádì bí Ṣélà,+ Ṣélà sì bí Ébérì.

25 Ọmọ méjì ni Ébérì bí. Ọ̀kan ń jẹ́ Pélégì,*+ torí pé ìgbà ayé rẹ̀ ni ayé* pín sọ́tọ̀ọ̀tọ̀. Orúkọ arákùnrin rẹ̀ ni Jókítánì.+

26 Jókítánì bí Álímódádì, Ṣéléfì, Hásámáfétì, Jérà,+ 27 Hádórámù, Úsálì, Díkílà, 28 Óbálì, Ábímáélì, Ṣébà, 29 Ófírì,+ Háfílà àti Jóbábù; gbogbo wọn jẹ́ ọmọ Jókítánì.

30 Ibi tí wọ́n ń gbé bẹ̀rẹ̀ láti Méṣà títí lọ dé Séfárì, agbègbè olókè Ìlà Oòrùn.

31 Àwọn ọmọ Ṣémù nìyí bí wọ́n ṣe wà nínú ìdílé wọn, èdè wọn, ilẹ̀ wọn àti orílẹ̀-èdè wọn.+

32 Ìwọ̀nyí ni ìdílé àwọn ọmọ Nóà, bí wọ́n ṣe wà nínú ìdílé kálukú wọn àti orílẹ̀-èdè wọn. Ọ̀dọ̀ wọn ni àwọn orílẹ̀-èdè ti tàn káàkiri ayé lẹ́yìn Ìkún Omi.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́