ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 18
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Léfítíkù

      • Ìbálòpọ̀ tí kò tọ́ (1-30)

        • Ẹ má fara wé àwọn ọmọ Kénáánì (3)

        • Ìbálòpọ̀ láàárín mọ̀lẹ́bí (6-18)

        • Tí obìnrin bá ń ṣe nǹkan oṣù (19)

        • Bíbá ẹ̀yà kan náà lò pọ̀ (22)

        • Bíbá ẹranko lò pọ̀ (23)

        • ‘Ẹ jẹ́ mímọ́, kí ilẹ̀ náà má bàa pọ̀ yín jáde’ (24-30)

Léfítíkù 18:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 17:7; Ẹk 6:7

Léfítíkù 18:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 23:24; Le 20:23

Léfítíkù 18:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 20:22; Di 4:1

Léfítíkù 18:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Lk 10:27, 28; Ro 10:5; Ga 3:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2009, ojú ìwé 6

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 114

Léfítíkù 18:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “láti ṣí i sí ìhòòhò,” ní ẹsẹ yìí àtàwọn ẹsẹ tó tẹ̀ lé e.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 20:17

Léfítíkù 18:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “Ìhòòhò bàbá rẹ̀ ni.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 35:22; 49:4; Le 20:11; Di 27:20; 2Sa 16:21; 1Kọ 5:1

Léfítíkù 18:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 20:17; Di 27:22; 2Sa 13:10-12

Léfítíkù 18:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 20:19

Léfítíkù 18:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ṣí ìhòòhò.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 20:20

Léfítíkù 18:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 20:12

Léfítíkù 18:16

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ìhòòhò arákùnrin rẹ ni.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 20:21; Di 25:5; Mk 6:17, 18

Léfítíkù 18:17

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìwà tó ń dójú tini; ìwà ìbàjẹ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 20:14; Di 27:23

Léfítíkù 18:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 30:15

Léfítíkù 18:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 15:19, 24; 20:18

Léfítíkù 18:20

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọmọnìkejì rẹ; ọ̀rẹ́ rẹ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 20:14; Le 20:10; Di 22:22; Owe 6:29; Mt 5:27, 28; 1Kọ 6:9, 10; Heb 13:4

Léfítíkù 18:21

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ya ọmọ rẹ kankan sọ́tọ̀ fún.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 20:2; Di 18:10; 1Ọb 11:7; 2Ọb 23:10
  • +Le 20:3

Léfítíkù 18:22

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 19:5; Le 20:13; Ond 19:22; Ro 1:26, 27; 1Kọ 6:9, 10; Jud 7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jí!,

    4/2012, ojú ìwé 30

Léfítíkù 18:23

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 22:19; Le 20:15, 16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2003, ojú ìwé 27

Léfítíkù 18:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 20:23; Di 18:12

Léfítíkù 18:25

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 15:16

Léfítíkù 18:26

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 20:22; Di 4:1, 40
  • +Ẹk 12:49

Léfítíkù 18:27

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 20:17, 18; 2Ọb 16:2, 3; 21:1, 2

Léfítíkù 18:29

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọkàn.”

Léfítíkù 18:30

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 18:3; 20:23; Di 18:9

Àwọn míì

Léf. 18:2Jẹ 17:7; Ẹk 6:7
Léf. 18:3Ẹk 23:24; Le 20:23
Léf. 18:4Le 20:22; Di 4:1
Léf. 18:5Lk 10:27, 28; Ro 10:5; Ga 3:12
Léf. 18:6Le 20:17
Léf. 18:8Jẹ 35:22; 49:4; Le 20:11; Di 27:20; 2Sa 16:21; 1Kọ 5:1
Léf. 18:9Le 20:17; Di 27:22; 2Sa 13:10-12
Léf. 18:12Le 20:19
Léf. 18:14Le 20:20
Léf. 18:15Le 20:12
Léf. 18:16Le 20:21; Di 25:5; Mk 6:17, 18
Léf. 18:17Le 20:14; Di 27:23
Léf. 18:18Jẹ 30:15
Léf. 18:19Le 15:19, 24; 20:18
Léf. 18:20Ẹk 20:14; Le 20:10; Di 22:22; Owe 6:29; Mt 5:27, 28; 1Kọ 6:9, 10; Heb 13:4
Léf. 18:21Le 20:2; Di 18:10; 1Ọb 11:7; 2Ọb 23:10
Léf. 18:21Le 20:3
Léf. 18:22Jẹ 19:5; Le 20:13; Ond 19:22; Ro 1:26, 27; 1Kọ 6:9, 10; Jud 7
Léf. 18:23Ẹk 22:19; Le 20:15, 16
Léf. 18:24Le 20:23; Di 18:12
Léf. 18:25Jẹ 15:16
Léf. 18:26Le 20:22; Di 4:1, 40
Léf. 18:26Ẹk 12:49
Léf. 18:27Di 20:17, 18; 2Ọb 16:2, 3; 21:1, 2
Léf. 18:30Le 18:3; 20:23; Di 18:9
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
  • 28
  • 29
  • 30
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Léfítíkù 18:1-30

Léfítíkù

18 Jèhófà ń bá ọ̀rọ̀ tó ń sọ fún Mósè lọ pé: 2 “Sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín.+ 3 Ẹ ò gbọ́dọ̀ ṣe bí wọ́n ṣe ń ṣe nílẹ̀ Íjíbítì tí ẹ gbé rí, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ ṣe bí wọ́n ṣe ń ṣe nílẹ̀ Kénáánì tí mò ń mú yín lọ.+ Ẹ ò gbọ́dọ̀ tẹ̀ lé àṣẹ wọn. 4 Kí ẹ máa tẹ̀ lé àwọn ìdájọ́ mi, kí ẹ máa pa àwọn àṣẹ mi mọ́, kí ẹ sì máa rìn nínú wọn.+ Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín. 5 Kí ẹ máa pa àwọn àṣẹ mi àti àwọn ìdájọ́ mi mọ́; yóò mú kí ẹnikẹ́ni tó bá ń pa á mọ́ wà láàyè.+ Èmi ni Jèhófà.

6 “‘Ẹnikẹ́ni nínú yín ò gbọ́dọ̀ sún mọ́ ìkankan nínú àwọn mọ̀lẹ́bí rẹ̀ tó sún mọ́ ọn láti bá a lò pọ̀.*+ Èmi ni Jèhófà. 7 O ò gbọ́dọ̀ bá bàbá rẹ lò pọ̀, o ò gbọ́dọ̀ bá ìyá rẹ lò pọ̀. Ìyá rẹ ni, o ò sì gbọ́dọ̀ bá a lò pọ̀.

8 “‘O ò gbọ́dọ̀ bá ìyàwó bàbá rẹ lò pọ̀.+ Ìyẹn máa dójú ti bàbá rẹ.*

9 “‘O ò gbọ́dọ̀ bá arábìnrin rẹ lò pọ̀, ì báà jẹ́ ọmọ bàbá rẹ tàbí ọmọ ìyá rẹ, ì báà jẹ́ agbo ilé kan náà ni wọ́n bí yín sí tàbí bẹ́ẹ̀ kọ́.+

10 “‘O ò gbọ́dọ̀ bá ọmọbìnrin tí ọmọ rẹ ọkùnrin bí lò pọ̀ tàbí kí o bá ọmọbìnrin tí ọmọ rẹ obìnrin bí lò pọ̀, torí ìhòòhò rẹ ni wọ́n.

11 “‘O ò gbọ́dọ̀ bá ọmọbìnrin tí ìyàwó bàbá rẹ bí lò pọ̀, torí ọmọ bàbá kan náà lẹ jẹ́, arábìnrin rẹ ni.

12 “‘O ò gbọ́dọ̀ bá arábìnrin bàbá rẹ lò pọ̀. Mọ̀lẹ́bí bàbá rẹ tímọ́tímọ́ ni.+

13 “‘O ò gbọ́dọ̀ bá arábìnrin ìyá rẹ lò pọ̀, torí mọ̀lẹ́bí ìyá rẹ tímọ́tímọ́ ni.

14 “‘O ò gbọ́dọ̀ bá ìyàwó arákùnrin bàbá rẹ lò pọ̀, kí o má bàa dójú ti* arákùnrin bàbá rẹ. Ìyàwó arákùnrin bàbá rẹ ni.+

15 “‘O ò gbọ́dọ̀ bá ìyàwó ọmọ rẹ lò pọ̀.+ Ìyàwó ọmọ rẹ ni, o ò gbọ́dọ̀ bá a lò pọ̀.

16 “‘O ò gbọ́dọ̀ bá ìyàwó arákùnrin rẹ lò pọ̀,+ torí ìyẹn máa dójú ti arákùnrin rẹ.*

17 “‘O ò gbọ́dọ̀ bá ìyá àti ọmọbìnrin rẹ̀ lò pọ̀.+ O ò gbọ́dọ̀ mú ọmọbìnrin tí ọmọ rẹ̀ ọkùnrin bí tàbí ọmọbìnrin tí ọmọ rẹ̀ obìnrin bí kí o lè bá a lò pọ̀. Mọ̀lẹ́bí rẹ̀ tímọ́tímọ́ ni wọ́n, ìwà àìnítìjú* ni.

18 “‘O ò gbọ́dọ̀ fẹ́ arábìnrin ìyàwó rẹ láti fi ṣe orogún rẹ̀,+ o ò sì gbọ́dọ̀ bá a lò pọ̀ nígbà tí arábìnrin rẹ̀ ṣì wà láàyè.

19 “‘O ò gbọ́dọ̀ sún mọ́ obìnrin nígbà tó bá ń ṣe nǹkan oṣù rẹ̀ láti bá a lò pọ̀.+

20 “‘O ò gbọ́dọ̀ bá ìyàwó ẹnì kejì rẹ* lò pọ̀ kí o wá tipa bẹ́ẹ̀ sọ ara rẹ di aláìmọ́.+

21 “‘O ò gbọ́dọ̀ jẹ́ kí wọ́n fi ìkankan nínú àwọn ọmọ rẹ rúbọ sí* Mólékì.+ O ò gbọ́dọ̀ tipa bẹ́ẹ̀ sọ orúkọ Ọlọ́run rẹ di aláìmọ́.+ Èmi ni Jèhófà.

22 “‘O ò gbọ́dọ̀ bá ọkùnrin sùn bí ìgbà tí ò ń bá obìnrin sùn.+ Ohun ìríra ni.

23 “‘Ọkùnrin ò gbọ́dọ̀ bá ẹranko lò pọ̀, kó má bàa di aláìmọ̀; obìnrin ò sì gbọ́dọ̀ jẹ́ kí ẹranko bá òun lò pọ̀.+ Kì í ṣe ìwà tó tọ́.

24 “‘Ẹ má fi èyíkéyìí nínú àwọn nǹkan yìí sọ ara yín di aláìmọ́, torí gbogbo àwọn nǹkan yìí ni àwọn orílẹ̀-èdè tí mo fẹ́ lé kúrò níwájú yín fi sọ ara wọn di aláìmọ́.+ 25 Torí náà, ilẹ̀ náà jẹ́ aláìmọ́, màá fìyà ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ jẹ ẹ́, ilẹ̀ náà yóò sì pọ àwọn tó ń gbé ibẹ̀ jáde.+ 26 Àmọ́ kí ẹ̀yin fúnra yín máa pa àwọn àṣẹ mi àti àwọn ìlànà mi mọ́,+ ẹ ò sì gbọ́dọ̀ ṣe ìkankan nínú àwọn ohun ìríra yìí, ì báà jẹ́ ọmọ ìbílẹ̀ tàbí àjèjì tó ń gbé láàárín yín.+ 27 Torí gbogbo ohun ìríra wọ̀nyí ni àwọn tó gbé ilẹ̀ náà ṣáájú yín+ ti ṣe, ilẹ̀ náà sì ti wá di aláìmọ́. 28 Kí ilẹ̀ náà má bàa pọ̀ yín jáde torí pé ẹ sọ ọ́ di ẹlẹ́gbin, bó ṣe máa pọ àwọn orílẹ̀-èdè tó wà ṣáájú yín jáde. 29 Tí ẹnikẹ́ni bá ṣe èyíkéyìí nínú àwọn ohun ìríra yìí, kí ẹ pa gbogbo àwọn* tó bá ń ṣe é, kí ẹ lè mú wọn kúrò láàárín àwọn èèyàn wọn. 30 Kí ẹ máa ṣe ohun tí mo pa láṣẹ fún yín, ẹ ò gbọ́dọ̀ lọ́wọ́ sí àṣà èyíkéyìí tó ń ríni lára tí wọ́n ṣe ṣáájú yín,+ kí ẹ má bàa fi wọ́n sọ ara yín di aláìmọ́. Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín.’”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́