ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 112
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Sáàmù

      • Olódodo máa ń bẹ̀rù Jèhófà

        • Ẹni tó bá ń yáni ní nǹkan tọkàntọkàn yóò láásìkí (5)

        • “A ó máa rántí àwọn olódodo títí láé” (6)

        • Ọ̀làwọ́ máa ń fún àwọn aláìní (9)

Sáàmù 112:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Halelúyà!” “Jáà” ni ìkékúrú Jèhófà.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 15:2; Ifi 19:1
  • +Sm 111:10
  • +Sm 1:1, 2; 40:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2009, ojú ìwé 25-26

    7/15/2000, ojú ìwé 5

Sáàmù 112:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 25:12, 13; 37:25, 26

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2009, ojú ìwé 25-26

Sáàmù 112:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2009, ojú ìwé 26-27

Sáàmù 112:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “olóore ọ̀fẹ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 97:11; 1Pe 2:9
  • +Lk 6:36; Ef 4:32

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2009, ojú ìwé 26-27

Sáàmù 112:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “pẹ̀lú oore ọ̀fẹ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 15:7, 8; Sm 41:1; Owe 19:17; Lk 6:34, 35; Iṣe 20:35; Heb 13:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2009, ojú ìwé 27

Sáàmù 112:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 15:5; 125:1
  • +Ne 5:19; Owe 10:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2009, ojú ìwé 28

Sáàmù 112:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 27:1; Owe 3:25
  • +Sm 62:8; Ais 26:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2009, ojú ìwé 28

Sáàmù 112:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “kò ṣe ségesège.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 28:1
  • +Sm 59:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2009, ojú ìwé 28

Sáàmù 112:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “fàlàlà.”

  • *

    Ní Héb., “ìwo.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 15:11; Owe 11:24; 19:17
  • +Di 24:12, 13; 2Kọ 9:9; Heb 6:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2009, ojú ìwé 27-28

Sáàmù 112:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 11:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2009, ojú ìwé 28

Àwọn míì

Sm 112:1Ẹk 15:2; Ifi 19:1
Sm 112:1Sm 111:10
Sm 112:1Sm 1:1, 2; 40:8
Sm 112:2Sm 25:12, 13; 37:25, 26
Sm 112:4Sm 97:11; 1Pe 2:9
Sm 112:4Lk 6:36; Ef 4:32
Sm 112:5Di 15:7, 8; Sm 41:1; Owe 19:17; Lk 6:34, 35; Iṣe 20:35; Heb 13:16
Sm 112:6Sm 15:5; 125:1
Sm 112:6Ne 5:19; Owe 10:7
Sm 112:7Sm 27:1; Owe 3:25
Sm 112:7Sm 62:8; Ais 26:3
Sm 112:8Owe 28:1
Sm 112:8Sm 59:10
Sm 112:9Di 15:11; Owe 11:24; 19:17
Sm 112:9Di 24:12, 13; 2Kọ 9:9; Heb 6:10
Sm 112:10Owe 11:7
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Sáàmù 112:1-10

Sáàmù

112 Ẹ yin Jáà!*+

א [Áléfì]

Aláyọ̀ ni ẹni tó bẹ̀rù Jèhófà,+

ב [Bétì]

Tó sì fẹ́ràn àwọn àṣẹ rẹ̀ gan-an.+

ג [Gímélì]

 2 Àtọmọdọ́mọ rẹ̀ yóò di alágbára ní ayé,

ד [Dálétì]

Ìran àwọn adúróṣinṣin yóò sì rí ìbùkún.+

ה [Híì]

 3 Ọlá àti ọrọ̀ wà nínú ilé rẹ̀,

ו [Wọ́ọ̀]

Òdodo rẹ̀ sì wà títí láé.

ז [Sáyìn]

 4 Nínú òkùnkùn, ó ń tàn yanran bí ìmọ́lẹ̀ sí àwọn adúróṣinṣin.+

ח [Hétì]

Ó jẹ́ agbatẹnirò* àti aláàánú+ àti olódodo.

ט [Tétì]

 5 Nǹkan máa ń lọ dáadáa fún ẹni tó bá ń yáni ní nǹkan tọkàntọkàn.*+

י [Yódì]

Ìdájọ́ òdodo ló fi ń ṣe nǹkan.

כ [Káfì]

 6 Mìmì kan ò ní mì í láé.+

ל [Lámédì]

A ó máa rántí àwọn olódodo títí láé.+

מ [Mémì]

 7 Kò ní bẹ̀rù ìròyìn burúkú.+

נ [Núnì]

Ọkàn rẹ̀ dúró ṣinṣin, ó gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà.+

ס [Sámékì]

 8 Ọkàn rẹ̀ kò mì;* kò bẹ̀rù;+

ע [Áyìn]

Níkẹyìn, yóò rí ìṣubú àwọn ọ̀tá rẹ̀.+

פ [Péè]

 9 Ó ti pín nǹkan fún àwọn èèyàn káàkiri;* ó ti fún àwọn aláìní.+

צ [Sádì]

Òdodo rẹ̀ wà títí láé.+

ק [Kófì]

A ó gbé agbára* rẹ̀ ga nínú ògo.

ר [Réṣì]

10 Ẹni burúkú á rí i, inú á sì bí i.

ש [Ṣínì]

Á wa eyín pọ̀, á sì pa rẹ́.

ת [Tọ́ọ̀]

Ìfẹ́ ọkàn àwọn ẹni burúkú yóò ṣègbé.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́