ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Dáníẹ́lì 9
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Dáníẹ́lì

      • Dáníẹ́lì gbàdúrà ìjẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ (1-19)

        • Jerúsálẹ́mù máa dahoro fún 70 ọdún (2)

      • Gébúrẹ́lì wá bá Dáníẹ́lì (20-23)

      • Àsọtẹ́lẹ̀ nípa àádọ́rin ọ̀sẹ̀ (24-27)

        • Mèsáyà máa fara hàn lẹ́yìn ọ̀sẹ̀ 69 (25)

        • Wọ́n máa pa Mèsáyà (26)

        • Ìlú náà àti ibi mímọ́ máa pa run (26)

Dáníẹ́lì 9:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 6:28; 11:1
  • +Da 5:30, 31

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 6/2017,

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 181

Dáníẹ́lì 9:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, àwọn ìwé mímọ́.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹsr 1:1, 2; Sm 79:1; Ais 64:10; Ida 1:1
  • +2Kr 36:20, 21; Jer 25:11; 29:10; Sek 1:12; 7:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    10/2016, ojú ìwé 14

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2011, ojú ìwé 22

    6/1/2007, ojú ìwé 22

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 181, 309

    “Kí Ijọba Rẹ Dé,” ojú ìwé 56-57, 189

Dáníẹ́lì 9:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “aṣọ àpò ìdọ̀họ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹsr 8:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 182

Dáníẹ́lì 9:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 34:6
  • +Di 5:9, 10; Ne 1:5

Dáníẹ́lì 9:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹsr 9:6, 7; Ne 9:26, 33; Sm 106:6; Ida 3:42

Dáníẹ́lì 9:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 36:15, 16; Jer 7:13

Dáníẹ́lì 9:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 26:33; Di 28:41; 2Ọb 17:6; Ais 11:11

Dáníẹ́lì 9:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 34:6, 7; Ne 9:17; Sm 86:5
  • +Ne 9:26

Dáníẹ́lì 9:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 17:13, 14

Dáníẹ́lì 9:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 28:15; 31:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 182-183

Dáníẹ́lì 9:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “àwọn adájọ́ wa tí wọ́n dá ẹjọ́ wa.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ida 2:17
  • +Jer 39:8

Dáníẹ́lì 9:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “a ò tu Jèhófà Ọlọ́run wa lójú pé.”

  • *

    Tàbí “òdodo.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 26:16, 17; Di 28:15; Ida 1:1
  • +Ais 9:13; Jer 5:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 183

Dáníẹ́lì 9:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ne 9:33

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 183

Dáníẹ́lì 9:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 6:1
  • +Ẹk 9:16; Ne 9:10; Sm 106:7, 8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 183-184

Dáníẹ́lì 9:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 89:14; Ais 26:9
  • +Le 26:38, 39; 1Ọb 9:7-9; Sm 79:1, 4; Jer 24:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 183-184

Dáníẹ́lì 9:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 6:23, 25
  • +Ais 64:10, 11; Ida 5:18

Dáníẹ́lì 9:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 102:13; Ais 54:7, 8; Jer 14:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 184

Dáníẹ́lì 9:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 8:30
  • +Sm 79:8, 9; Ais 63:18, 19; Jer 14:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2007, ojú ìwé 20

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 184

Dáníẹ́lì 9:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 87:1, 2; Sek 8:3

Dáníẹ́lì 9:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 8:16; Lk 1:19
  • +Da 8:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2007, ojú ìwé 20

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 184-185

Dáníẹ́lì 9:23

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “fani mọ́ra gan-an; èèyàn pàtàkì ni ọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 10:11, 19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2007, ojú ìwé 20

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 7, 184-186

Dáníẹ́lì 9:24

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, ọ̀sẹ̀ tó dúró fún ọdún.

  • *

    Ní Héb., “wòlíì.”

  • *

    Tàbí “Ibi Mímọ́ Jù Lọ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ne 11:1; Ais 52:1
  • +Lk 1:76, 77; Heb 9:26
  • +Ro 3:25; 1Jo 2:1, 2; 4:10
  • +Ais 53:11; Ro 1:16, 17
  • +2Kọ 1:19, 20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    5/15/2001, ojú ìwé 27

    7/1/1996, ojú ìwé 15

    7/15/1994, ojú ìwé 29-30

    10/1/1992, ojú ìwé 13-14

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 186-187, 192, 194-195

    Ìmọ̀, ojú ìwé 36

    “Kí Ijọba Rẹ Dé,” ojú ìwé 58, 63-65

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 128-129

Dáníẹ́lì 9:25

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ẹni Àmì Òróró.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ne 2:5, 11; 6:15
  • +Sm 2:2; Jo 1:41
  • +Ais 55:4; Mt 23:10; Jo 1:45, 49
  • +Lk 3:1, 2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Bíbélì Fi Kọ́ni, ojú ìwé 197-199

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2002, ojú ìwé 4-5

    9/15/1998, ojú ìwé 13-14

    10/1/1992, ojú ìwé 11-12

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 186-192

    Ìmọ̀, ojú ìwé 36

    “Kí Ijọba Rẹ Dé,” ojú ìwé 58-61

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 128-129, 142-143

Dáníẹ́lì 9:26

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ké Mèsáyà kúrò.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 53:8, 12; Mt 26:2; Lk 24:26; 1Kọ 15:3
  • +Mk 9:12
  • +Mt 24:15; Lk 19:43, 44; 21:20
  • +Lk 21:22, 24

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 192-194, 195-196

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    10/1/1992, ojú ìwé 13-14

    “Kí Ijọba Rẹ Dé,” ojú ìwé 62-63

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 128, 142-143

Dáníẹ́lì 9:27

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 9:11, 12; 10:8-10
  • +Mk 13:14; Lk 21:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jíjẹ́rìí Kúnnákúnná, ojú ìwé 72

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2007, ojú ìwé 20

    5/15/2003, ojú ìwé 31

    5/1/1999, ojú ìwé 14-15

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 192-194, 195-196

    “Kí Ijọba Rẹ Dé,” ojú ìwé 65-66

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 128, 142-143, 161, 162-164

Àwọn míì

Dán. 9:1Da 6:28; 11:1
Dán. 9:1Da 5:30, 31
Dán. 9:2Ẹsr 1:1, 2; Sm 79:1; Ais 64:10; Ida 1:1
Dán. 9:22Kr 36:20, 21; Jer 25:11; 29:10; Sek 1:12; 7:5
Dán. 9:3Ẹsr 8:21
Dán. 9:4Ẹk 34:6
Dán. 9:4Di 5:9, 10; Ne 1:5
Dán. 9:5Ẹsr 9:6, 7; Ne 9:26, 33; Sm 106:6; Ida 3:42
Dán. 9:62Kr 36:15, 16; Jer 7:13
Dán. 9:7Le 26:33; Di 28:41; 2Ọb 17:6; Ais 11:11
Dán. 9:9Ẹk 34:6, 7; Ne 9:17; Sm 86:5
Dán. 9:9Ne 9:26
Dán. 9:102Ọb 17:13, 14
Dán. 9:11Di 28:15; 31:17
Dán. 9:12Ida 2:17
Dán. 9:12Jer 39:8
Dán. 9:13Le 26:16, 17; Di 28:15; Ida 1:1
Dán. 9:13Ais 9:13; Jer 5:3
Dán. 9:14Ne 9:33
Dán. 9:15Ẹk 6:1
Dán. 9:15Ẹk 9:16; Ne 9:10; Sm 106:7, 8
Dán. 9:16Sm 89:14; Ais 26:9
Dán. 9:16Le 26:38, 39; 1Ọb 9:7-9; Sm 79:1, 4; Jer 24:9
Dán. 9:17Nọ 6:23, 25
Dán. 9:17Ais 64:10, 11; Ida 5:18
Dán. 9:18Sm 102:13; Ais 54:7, 8; Jer 14:7
Dán. 9:191Ọb 8:30
Dán. 9:19Sm 79:8, 9; Ais 63:18, 19; Jer 14:9
Dán. 9:20Sm 87:1, 2; Sek 8:3
Dán. 9:21Da 8:16; Lk 1:19
Dán. 9:21Da 8:1
Dán. 9:23Da 10:11, 19
Dán. 9:24Ne 11:1; Ais 52:1
Dán. 9:24Lk 1:76, 77; Heb 9:26
Dán. 9:24Ro 3:25; 1Jo 2:1, 2; 4:10
Dán. 9:24Ais 53:11; Ro 1:16, 17
Dán. 9:242Kọ 1:19, 20
Dán. 9:25Ne 2:5, 11; 6:15
Dán. 9:25Sm 2:2; Jo 1:41
Dán. 9:25Ais 55:4; Mt 23:10; Jo 1:45, 49
Dán. 9:25Lk 3:1, 2
Dán. 9:26Ais 53:8, 12; Mt 26:2; Lk 24:26; 1Kọ 15:3
Dán. 9:26Mk 9:12
Dán. 9:26Mt 24:15; Lk 19:43, 44; 21:20
Dán. 9:26Lk 21:22, 24
Dán. 9:27Heb 9:11, 12; 10:8-10
Dán. 9:27Mk 13:14; Lk 21:20
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Dáníẹ́lì 9:1-27

Dáníẹ́lì

9 Ní ọdún kìíní Dáríúsì+ ọmọ Ahasuérúsì, àtọmọdọ́mọ àwọn ará Mídíà, ẹni tí wọ́n fi jọba lórí ìjọba àwọn ará Kálídíà,+ 2 ní ọdún kìíní ìjọba rẹ̀, èmi Dáníẹ́lì fi òye mọ̀ látinú ìwé,* iye ọdún tí Jèhófà sọ fún wòlíì Jeremáyà pé Jerúsálẹ́mù fi máa wà ní ahoro,+ ìyẹn àádọ́rin (70) ọdún.+ 3 Mo wá yíjú sí Jèhófà Ọlọ́run tòótọ́, mo bẹ̀ ẹ́ bí mo ṣe ń gbàdúrà sí i, pẹ̀lú ààwẹ̀,+ aṣọ ọ̀fọ̀* àti eérú. 4 Mo gbàdúrà sí Jèhófà Ọlọ́run mi, mo jẹ́wọ́, mo sì sọ pé:

“Jèhófà Ọlọ́run tòótọ́, Ẹni ńlá, tó yẹ lẹ́ni tí à ń bẹ̀rù, tó ń pa májẹ̀mú rẹ̀ mọ́, tó sì ń fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn sí àwọn tó nífẹ̀ẹ́ rẹ̀,+ tí wọ́n sì ń pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́,+ 5 a ti ṣẹ̀, a sì ti ṣe ohun tí kò dáa, a ti hùwà burúkú, a sì ti ṣọ̀tẹ̀;+ a ti kọ àwọn àṣẹ rẹ àti àwọn ìdájọ́ rẹ sílẹ̀. 6 A ò fetí sí àwọn wòlíì tí wọ́n jẹ́ ìránṣẹ́ rẹ,+ tí wọ́n bá àwọn ọba wa, àwọn ìjòyè wa, àwọn baba ńlá wa àti gbogbo èèyàn ilẹ̀ náà sọ̀rọ̀ ní orúkọ rẹ. 7 Jèhófà, tìrẹ ni òdodo, àmọ́ àwa ni ìtìjú bá, bó ṣe rí lónìí yìí, àwa èèyàn Júdà, àwọn tó ń gbé Jerúsálẹ́mù àti gbogbo Ísírẹ́lì, àwọn tó wà nítòsí àti lọ́nà jíjìn, ní gbogbo ilẹ̀ tí o fọ́n wọn ká sí torí pé wọn ò jẹ́ olóòótọ́ sí ọ.+

8 “Jèhófà, àwa ni ìtìjú bá, àwọn ọba wa, àwọn ìjòyè wa àti àwọn baba ńlá wa, torí pé a ti ṣẹ̀ ọ́. 9 Àánú àti ìdáríjì jẹ́ ti Jèhófà Ọlọ́run wa,+ torí a ti ṣọ̀tẹ̀ sí i.+ 10 A ò ṣègbọràn sí ohùn Jèhófà Ọlọ́run wa nípa títẹ̀ lé àwọn òfin rẹ̀ tó fún wa nípasẹ̀ àwọn wòlíì tó jẹ́ ìránṣẹ́ rẹ̀.+ 11 Gbogbo Ísírẹ́lì ti tẹ Òfin rẹ lójú, wọ́n sì ti yà kúrò nínú rẹ̀ torí pé wọn ò ṣègbọràn sí ohùn rẹ, tí o fi da ègún àti ìbúra lé wa lórí, èyí tí wọ́n kọ sínú Òfin Mósè ìránṣẹ́ Ọlọ́run tòótọ́,+ torí pé a ti ṣẹ̀ Ẹ́. 12 Ó ti ṣe ohun tó sọ lòdì sí àwa+ àti àwọn alákòóso wa tí wọ́n jọba lé wa lórí,* torí ó mú kí àjálù ńlá ṣẹlẹ̀ sí wa; ohunkóhun ò ṣẹlẹ̀ rí lábẹ́ gbogbo ọ̀run bí èyí tó ṣẹlẹ̀ ní Jerúsálẹ́mù.+ 13 Bí a ṣe kọ ọ́ sínú Òfin Mósè, gbogbo àjálù yìí ti dé bá wa,+ síbẹ̀ a kò bẹ Jèhófà Ọlọ́run wa pé* kó ṣojúure sí wa, nípa yíyí pa dà kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ wa,+ ká sì fi ìjìnlẹ̀ òye hàn nínú òótọ́* rẹ.

14 “Torí náà, Jèhófà wà lójúfò, ó sì mú àjálù bá wa, torí Jèhófà Ọlọ́run wa jẹ́ olódodo nínú gbogbo iṣẹ́ tó ti ṣe; síbẹ̀, a ò ṣègbọràn sí ohùn rẹ̀.+

15 “Ní báyìí, Jèhófà Ọlọ́run wa, Ìwọ tí o fi ọwọ́ agbára mú àwọn èèyàn rẹ kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì,+ tí o sì ṣe orúkọ fún ara rẹ títí di òní yìí,+ a ti ṣẹ̀, a sì ti hùwà burúkú. 16 Jèhófà, gẹ́gẹ́ bíi gbogbo ìṣe òdodo rẹ,+ jọ̀ọ́, dáwọ́ ìbínú àti ìrunú rẹ dúró lórí ìlú rẹ, Jerúsálẹ́mù, òkè mímọ́ rẹ; torí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa àti àṣìṣe àwọn baba ńlá wa, gbogbo àwọn tó yí wa ká ń gan Jerúsálẹ́mù àti àwọn èèyàn rẹ.+ 17 Ní báyìí, Ọlọ́run wa, fetí sílẹ̀ sí àdúrà ìránṣẹ́ rẹ àti ẹ̀bẹ̀ rẹ̀, kí o sì jẹ́ kí ojú rẹ tàn sára ibi mímọ́ rẹ+ tó ti di ahoro,+ torí tìẹ, Jèhófà. 18 Ọlọ́run mi, tẹ́tí sílẹ̀, kí o sì gbọ́! La ojú rẹ, kí o sì rí ìyà tó ń jẹ wá àti bí ìlú tí a fi orúkọ rẹ pè ṣe di ahoro; kì í ṣe torí àwọn ìṣe òdodo wa la ṣe ń bẹ̀ ọ́, torí àánú rẹ tó pọ̀ ni.+ 19 Jèhófà, jọ̀ọ́ tẹ́tí gbọ́. Jèhófà, jọ̀ọ́ dárí jì.+ Jèhófà, jọ̀ọ́ fiyè sí wa, kí o sì gbé ìgbésẹ̀! Má ṣe jẹ́ kó pẹ́, torí tìẹ, Ọlọ́run mi, torí orúkọ rẹ la fi pe ìlú rẹ àti àwọn èèyàn rẹ.”+

20 Bí mo ṣe ń sọ̀rọ̀ lọ́wọ́, tí mò ń gbàdúrà, tí mò ń jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ mi àti ẹ̀ṣẹ̀ àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì, tí mo sì ń bẹ̀bẹ̀ fún ojúure Jèhófà Ọlọ́run mi nítorí òkè mímọ́ Ọlọ́run mi,+ 21 àní, bí mo ṣe ń gbàdúrà lọ́wọ́, ọkùnrin náà Gébúrẹ́lì,+ ẹni tí mo ti rí nínú ìran tẹ́lẹ̀,+ wá sọ́dọ̀ mi nígbà tí okun ti tán nínú mi pátápátá, nígbà tí àkókò ọrẹ alẹ́ ti fẹ́rẹ̀ẹ́ tó. 22 Ó sì là mí lóye, ó sọ pé:

“Ìwọ Dáníẹ́lì, mo wá láti fún ọ ní ìjìnlẹ̀ òye àti ìmọ̀. 23 Nígbà tí o bẹ̀rẹ̀ sí í bẹ̀bẹ̀, ọ̀rọ̀ jáde lọ, mo sì wá ròyìn rẹ̀ fún ọ, torí o ṣeyebíye gan-an.*+ Torí náà, ro ọ̀rọ̀ náà, kí ìran náà sì yé ọ.

24 “A ti pinnu àádọ́rin (70) ọ̀sẹ̀* fún àwọn èèyàn rẹ àti ìlú mímọ́ rẹ,+ láti fòpin sí àṣìṣe, láti pa ẹ̀ṣẹ̀ rẹ́,+ láti ṣe ètùtù torí ìṣìnà,+ láti mú òdodo tó máa wà títí láé wá,+ láti gbé èdìdì lé ìran náà àti àsọtẹ́lẹ̀*+ àti láti fòróró yan Ibi Mímọ́ nínú Àwọn Ibi Mímọ́.* 25 Mọ èyí, kó sì yé ọ pé látìgbà tí a bá ti pàṣẹ pé ká dá Jerúsálẹ́mù pa dà sí bó ṣe wà,+ ká sì tún un kọ́, títí di ìgbà Mèsáyà*+ Aṣáájú,+ ọ̀sẹ̀ méje máa wà àti ọ̀sẹ̀ méjìlélọ́gọ́ta (62).+ Wọ́n máa mú kó pa dà sí bó ṣe wà, wọ́n sì máa tún un kọ́, ó máa ní ojúde ìlú, wọ́n sì máa gbẹ́ kòtò ńlá yí i ká, àmọ́ á jẹ́ ní àkókò wàhálà.

26 “Lẹ́yìn ọ̀sẹ̀ méjìlélọ́gọ́ta (62) náà, wọ́n máa pa Mèsáyà,*+ láìṣẹ́ ohunkóhun kù fún ara rẹ̀.+

“Àwọn èèyàn aṣáájú tó ń bọ̀ máa pa ìlú náà àti ibi mímọ́ náà run.+ Àkúnya omi ló sì máa fòpin sí i. Ogun á sì máa jà títí dé òpin; a ti pinnu pé ó máa di ahoro.+

27 “Ó máa mú kí májẹ̀mú náà wà lẹ́nu iṣẹ́ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀, fún ọ̀sẹ̀ kan; ní ìdajì ọ̀sẹ̀ náà, ó máa mú kí ẹbọ àti ọrẹ dópin.+

“Ẹni tó ń sọ nǹkan di ahoro máa wà lórí ìyẹ́ àwọn ohun ìríra;+ títí dìgbà ìparun, a máa da ohun tí a pinnu sórí ẹni tó ti di ahoro pẹ̀lú.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́