ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sekaráyà 14
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Sekaráyà

      • Ìjọsìn tòótọ́ borí, ó sì fìdí múlẹ̀ (1-21)

        • Òkè Ólífì yóò là sí méjì (4)

        • Jèhófà yóò jẹ́ ọ̀kan, orúkọ rẹ̀ yóò sì jẹ́ ọ̀kan (9)

        • Àjàkálẹ̀ àrùn yóò kọ lu àwọn tó ń gbéjà ko Jerúsálẹ́mù (12-15)

        • Wọn yóò ṣe Àjọyọ̀ Àtíbàbà (16-19)

        • Gbogbo ìkòkò yóò di mímọ́ fún Jèhófà (20, 21)

Sekaráyà 14:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, ìlú tó wà nínú ẹsẹ 2.

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2013, ojú ìwé 18

Sekaráyà 14:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2013, ojú ìwé 18-19

    7/1/1996, ojú ìwé 19-20, 22

Sekaráyà 14:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 38:23; Joẹ 3:2, 14; Ifi 16:14
  • +Ẹk 15:3; 2Kr 20:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2013, ojú ìwé 20

    7/1/1996, ojú ìwé 22

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 153-154

Sekaráyà 14:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “yíyọ oòrùn.”

  • *

    Ní Héb., “òkun.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Lk 19:29; Iṣe 1:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    12/2017, ojú ìwé 4

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2013, ojú ìwé 19

Sekaráyà 14:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Emọ 1:1
  • +Di 33:2; Joẹ 3:11; Jud 14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2013, ojú ìwé 19-20

Sekaráyà 14:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “dúró gbagidi,” bíi pé òtútù mú kó gan.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 13:9, 10; Emọ 5:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2013, ojú ìwé 20

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 158

Sekaráyà 14:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joẹ 2:31; 1Tẹ 5:2; 2Pe 3:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2006, ojú ìwé 29

Sekaráyà 14:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, Òkun Òkú.

  • *

    Ìyẹn, Òkun Mẹditaréníà.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ifi 21:6; 22:17
  • +Jer 17:13; Isk 47:1; Joẹ 3:18; Ifi 22:1
  • +Di 3:17
  • +Joṣ 1:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìjọsìn Mímọ́, ojú ìwé 204

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2013, ojú ìwé 21

    4/15/2006, ojú ìwé 29

Sekaráyà 14:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 97:1; Ifi 19:6
  • +Di 6:4
  • +Ais 42:8; 44:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2006, ojú ìwé 29

    7/1/1996, ojú ìwé 22

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 176

Sekaráyà 14:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “dé ẹkù ìfúntí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 15:22
  • +1Kr 4:24, 32
  • +Di 1:7
  • +Jer 30:18
  • +Jer 37:13
  • +Ne 3:1; Jer 31:38

Sekaráyà 14:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 60:18; Jer 31:40
  • +Jer 23:6; 33:16

Sekaráyà 14:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 19:34, 35; Joẹ 3:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    12/2017, ojú ìwé 4

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2013, ojú ìwé 20

    7/1/1996, ojú ìwé 22

    Ọjọ́ Jèhófà, ojú ìwé 32

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 157-158

Sekaráyà 14:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọwọ́ rẹ̀ yóò sì gbéjà ko ọwọ́ ẹnì kejì rẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ond 7:22; Isk 38:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    7/1/1996, ojú ìwé 22

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 158-159

    “Kí Ijọba Rẹ Dé,” ojú ìwé 172

Sekaráyà 14:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 14:13; 20:25; Sek 2:8, 9

Sekaráyà 14:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    12/2017, ojú ìwé 4

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2013, ojú ìwé 20

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 158

Sekaráyà 14:16

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “jọ́sìn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 66:23
  • +Sm 86:9
  • +Le 23:34; Ne 8:14, 15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    7/1/1996, ojú ìwé 22-23

Sekaráyà 14:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 60:12

Sekaráyà 14:20

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìkòkò ìsebẹ̀ ẹlẹ́nu fífẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 28:36; 39:30
  • +1Sa 2:13, 14
  • +Ẹk 25:29; Nọ 4:7

Sekaráyà 14:21

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìkòkò ìsebẹ̀ ẹlẹ́nu fífẹ̀.”

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “oníṣòwò.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 44:9

Àwọn míì

Sek. 14:3Isk 38:23; Joẹ 3:2, 14; Ifi 16:14
Sek. 14:3Ẹk 15:3; 2Kr 20:15
Sek. 14:4Lk 19:29; Iṣe 1:12
Sek. 14:5Emọ 1:1
Sek. 14:5Di 33:2; Joẹ 3:11; Jud 14
Sek. 14:6Ais 13:9, 10; Emọ 5:18
Sek. 14:7Joẹ 2:31; 1Tẹ 5:2; 2Pe 3:10
Sek. 14:8Ifi 21:6; 22:17
Sek. 14:8Jer 17:13; Isk 47:1; Joẹ 3:18; Ifi 22:1
Sek. 14:8Di 3:17
Sek. 14:8Joṣ 1:4
Sek. 14:9Sm 97:1; Ifi 19:6
Sek. 14:9Di 6:4
Sek. 14:9Ais 42:8; 44:6
Sek. 14:101Ọb 15:22
Sek. 14:101Kr 4:24, 32
Sek. 14:10Di 1:7
Sek. 14:10Jer 30:18
Sek. 14:10Jer 37:13
Sek. 14:10Ne 3:1; Jer 31:38
Sek. 14:11Ais 60:18; Jer 31:40
Sek. 14:11Jer 23:6; 33:16
Sek. 14:122Ọb 19:34, 35; Joẹ 3:2
Sek. 14:13Ond 7:22; Isk 38:21
Sek. 14:142Kr 14:13; 20:25; Sek 2:8, 9
Sek. 14:16Ais 66:23
Sek. 14:16Sm 86:9
Sek. 14:16Le 23:34; Ne 8:14, 15
Sek. 14:17Ais 60:12
Sek. 14:20Ẹk 28:36; 39:30
Sek. 14:201Sa 2:13, 14
Sek. 14:20Ẹk 25:29; Nọ 4:7
Sek. 14:21Isk 44:9
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Sekaráyà 14:1-21

Sekaráyà

14 “Wò ó! Ọjọ́ náà ń bọ̀. Ti Jèhófà ni ọjọ́ náà, àárín yín ni wọn yóò ti pín ẹrù yín* tí wọ́n kó ní ọjọ́ náà. 2 Màá kó gbogbo orílẹ̀-èdè jọ láti gbógun ti Jerúsálẹ́mù; wọ́n á gba ìlú náà, wọ́n á kó ẹrù nínú àwọn ilé, wọ́n á sì fipá bá àwọn obìnrin lò pọ̀. Ìdajì ìlú náà á sì lọ sí ìgbèkùn, àmọ́ wọn ò ní kó àwọn tó ṣẹ́ kù lára àwọn èèyàn náà kúrò ní ìlú náà.

3 “Jèhófà yóò jáde lọ gbéjà ko àwọn orílẹ̀-èdè+ yẹn bí ìgbà tó ń jà ní ọjọ́ ogun.+ 4 Ní ọjọ́ yẹn, ẹsẹ̀ rẹ̀ yóò dúró sórí Òkè Ólífì,+ tó dojú kọ Jerúsálẹ́mù ní ìlà oòrùn; Òkè Ólífì yóò là sí méjì láti ìlà oòrùn* dé ìwọ̀ oòrùn,* àfonífojì ńlá kan yóò sì wà láàárín rẹ̀; ìdajì òkè náà yóò sún sí àríwá àti ìdajì sí gúúsù. 5 Ẹ máa sá lọ sí àfonífojì àárín àwọn òkè mi; torí àfonífojì àárín àwọn òkè náà yóò dé Ásélì lọ́hùn-ún lọ́hùn-ún. Ẹ máa sá lọ, bí ẹ ṣe sá lọ torí ìmìtìtì ilẹ̀ láyé ìgbà Ùsáyà ọba Júdà.+ Jèhófà Ọlọ́run mi yóò wá, gbogbo àwọn ẹni mímọ́ yóò sì wà pẹ̀lú rẹ̀.+

6 “Ní ọjọ́ yẹn, kò ní sí ìmọ́lẹ̀ tó tàn yòò;+ àwọn nǹkan yóò dì.* 7 Yóò sì di ọjọ́ kan tí a mọ̀ sí ti Jèhófà.+ Kò ní jẹ́ ọ̀sán, bẹ́ẹ̀ ni kò ní jẹ́ òru; ìmọ́lẹ̀ yóò sì wà ní ìrọ̀lẹ́. 8 Ní ọjọ́ yẹn, omi ìyè+ yóò ṣàn jáde láti Jerúsálẹ́mù,+ ìdajì rẹ̀ sí ọ̀nà òkun ìlà oòrùn*+ àti ìdajì rẹ̀ sí ọ̀nà òkun ìwọ̀ oòrùn.*+ Yóò ṣẹlẹ̀ ní ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn àti ní ìgbà òtútù. 9 Jèhófà yóò sì jẹ́ Ọba lórí gbogbo ayé.+ Jèhófà yóò jẹ́ ọ̀kan ní ọjọ́ yẹn,+ orúkọ rẹ̀ yóò sì jẹ́ ọ̀kan.+

10 “Gbogbo ilẹ̀ náà láti Gébà+ dé Rímónì+ ní gúúsù Jerúsálẹ́mù yóò dà bí Árábà;+ yóò dìde, yóò sì máa gbé àyè rẹ̀,+ láti Ẹnubodè Bẹ́ńjámínì+ títí lọ dé ibi Ẹnubodè Àkọ́kọ́, títí lọ dé Ẹnubodè Igun àti láti Ilé Gogoro Hánánélì+ títí lọ dé àwọn ibi tí wọ́n ti ń fún wáìnì* tó jẹ́ ti ọba. 11 Àwọn èèyàn yóò gbé inú rẹ̀; kò tún ní sí ìparun tí ègún fà mọ́,+ wọn yóò sì máa gbé Jerúsálẹ́mù ní àlàáfíà.+

12 “Èyí ni àjàkálẹ̀ àrùn tí Jèhófà yóò fi kọ lu gbogbo èèyàn tó bá gbéjà ko Jerúsálẹ́mù:+ Ẹran ara wọn yóò jẹrà lórí ìdúró, ojú wọn yóò jẹrà ní agbárí wọn, ahọ́n wọn yóò sì jẹrà ní ẹnu wọn.

13 “Ní ọjọ́ yẹn, Jèhófà yóò da àárín wọn rú; kálukú wọn yóò gbá ọwọ́ ẹnì kejì rẹ̀ mú, wọn yóò sì gbéjà ko ara wọn.*+ 14 Júdà pẹ̀lú yóò jagun ní Jerúsálẹ́mù; ọrọ̀ gbogbo orílẹ̀-èdè tó yí wọn ká ni wọ́n á sì kó jọ, ọ̀pọ̀lọpọ̀ wúrà àti fàdákà àti aṣọ.+

15 “Irú àjàkálẹ̀ àrùn yẹn yóò tún kọ lu àwọn ẹṣin, ìbaaka, ràkúnmí, kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ àti gbogbo ẹran ọ̀sìn tó wà nínú àwọn àgọ́ yẹn.

16 “Gbogbo ẹni tó ṣẹ́ kù nínú gbogbo orílẹ̀-èdè tó wá gbéjà ko Jerúsálẹ́mù yóò máa lọ láti ọdún dé ọdún+ kí wọ́n lè tẹrí ba fún* Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun tó jẹ́ Ọba,+ kí wọ́n sì lè ṣe Àjọyọ̀ Àtíbàbà.+ 17 Àmọ́ tí ẹnì kankan nínú àwọn ìdílé tó wà ní ayé kò bá lọ sí Jerúsálẹ́mù láti tẹrí ba fún Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun tó jẹ́ Ọba, òjò kò ní rọ̀ sórí wọn.+ 18 Tí ìdílé àwọn ará Íjíbítì kò bá wá, tí wọn ò sì wọlé wá, òjò kò ní rọ̀ sórí wọn. Dípò ìyẹn, àjàkálẹ̀ àrùn tí Jèhófà fi kọ lu àwọn orílẹ̀-èdè tí kò wá ṣe Àjọyọ̀ Àtíbàbà ni yóò kọ lù wọ́n. 19 Èyí ni yóò jẹ́ ìyà ẹ̀ṣẹ̀ Íjíbítì àti ìyà ẹ̀ṣẹ̀ gbogbo orílẹ̀-èdè tí kò wá ṣe Àjọyọ̀ Àtíbàbà.

20 “Ní ọjọ́ yẹn, wọn yóò kọ ọ̀rọ̀ náà, ‘Ìjẹ́mímọ́ jẹ́ ti Jèhófà!’+ sára àwọn agogo tí wọ́n so mọ́ àwọn ẹṣin. Àwọn ìkòkò oúnjẹ*+ inú ilé Jèhófà yóò sì dà bí àwọn abọ́+ níwájú pẹpẹ. 21 Gbogbo ìkòkò oúnjẹ* ní Jerúsálẹ́mù àti Júdà yóò di mímọ́, yóò sì jẹ́ ti Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, gbogbo àwọn tó ń rúbọ yóò wọlé wá, wọn yóò sì lò lára rẹ̀ láti fi se nǹkan. Ní ọjọ́ yẹn, kò ní sí ọmọ Kénáánì* kankan mọ́ nínú ilé Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́