ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 34
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Diutarónómì

      • Jèhófà fi ilẹ̀ náà han Mósè (1-4)

      • Ikú Mósè (5-12)

Diutarónómì 34:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 32:49
  • +Di 3:27
  • +Nọ 36:13
  • +Ond 18:29

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    “Ilẹ̀ Dáradára,” ojú ìwé 8-9

Diutarónómì 34:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, Òkun Ńlá, Òkun Mẹditaréníà.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 23:31; Nọ 34:2, 6; Di 11:24

Diutarónómì 34:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 15:1
  • +Jẹ 13:10
  • +Jẹ 19:22, 23

Diutarónómì 34:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “Èso.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 12:7; 26:3; 28:13
  • +Nọ 20:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 2/2020, ojú ìwé 1

Diutarónómì 34:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 32:50; Joṣ 1:2

Diutarónómì 34:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jud 9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 9/2021,

Diutarónómì 34:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 31:1, 2; Iṣe 7:23, 30, 36

Diutarónómì 34:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 20:29

Diutarónómì 34:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 31:14; 1Ti 4:14
  • +Nọ 27:18, 21; Joṣ 1:16

Diutarónómì 34:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 18:15; Iṣe 3:22; 7:37
  • +Ẹk 33:11; Nọ 12:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/1997, ojú ìwé 4-5

Diutarónómì 34:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 4:34

Diutarónómì 34:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 26:8; Lk 24:19

Àwọn míì

Diu. 34:1Di 32:49
Diu. 34:1Di 3:27
Diu. 34:1Nọ 36:13
Diu. 34:1Ond 18:29
Diu. 34:2Ẹk 23:31; Nọ 34:2, 6; Di 11:24
Diu. 34:3Joṣ 15:1
Diu. 34:3Jẹ 13:10
Diu. 34:3Jẹ 19:22, 23
Diu. 34:4Jẹ 12:7; 26:3; 28:13
Diu. 34:4Nọ 20:12
Diu. 34:5Di 32:50; Joṣ 1:2
Diu. 34:6Jud 9
Diu. 34:7Di 31:1, 2; Iṣe 7:23, 30, 36
Diu. 34:8Nọ 20:29
Diu. 34:9Di 31:14; 1Ti 4:14
Diu. 34:9Nọ 27:18, 21; Joṣ 1:16
Diu. 34:10Di 18:15; Iṣe 3:22; 7:37
Diu. 34:10Ẹk 33:11; Nọ 12:8
Diu. 34:11Di 4:34
Diu. 34:12Di 26:8; Lk 24:19
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Diutarónómì 34:1-12

Diutarónómì

34 Mósè wá kúrò ní aṣálẹ̀ tó tẹ́jú ní Móábù lọ sí Òkè Nébò,+ sí orí Písígà,+ tó dojú kọ Jẹ́ríkò.+ Jèhófà sì fi gbogbo ilẹ̀ náà hàn án, láti Gílíádì títí dé Dánì+ 2 àti gbogbo Náfútálì àti ilẹ̀ Éfúrémù àti Mánásè àti gbogbo ilẹ̀ Júdà títí lọ dé òkun ìwọ̀ oòrùn*+ 3 àti Négébù+ àti Agbègbè,+ pẹ̀tẹ́lẹ̀ Jẹ́ríkò, ìlú tí àwọn igi ọ̀pẹ wà, títí lọ dé Sóárì.+

4 Jèhófà sọ fún un pé: “Ilẹ̀ tí mo búra nípa rẹ̀ fún Ábúráhámù, Ísákì àti Jékọ́bù nìyí pé, ‘Ọmọ* rẹ ni èmi yóò fún.’+ Mo ti jẹ́ kí o fi ojú ara rẹ rí i, àmọ́ o ò ní sọdá sí ibẹ̀.”+

5 Lẹ́yìn náà, Mósè ìránṣẹ́ Jèhófà kú síbẹ̀ ní ilẹ̀ Móábù bí Jèhófà ṣe sọ gẹ́lẹ́.+ 6 Ó sin ín sí àfonífojì ní ilẹ̀ Móábù ní òdìkejì Bẹti-péórì, kò sì sí ẹni tó mọ sàréè rẹ̀ títí di òní yìí.+ 7 Ẹni ọgọ́fà (120) ọdún ni Mósè nígbà tó kú.+ Ojú rẹ̀ ò di bàìbàì, agbára rẹ̀ ò sì dín kù. 8 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì fi ọgbọ̀n (30) ọjọ́+ sunkún torí Mósè ní aṣálẹ̀ tó tẹ́jú ní Móábù. Nígbà tó yá, ọjọ́ tí wọ́n fi ń sunkún, tí wọ́n sì fi ń ṣọ̀fọ̀ torí Mósè dópin.

9 Ẹ̀mí ọgbọ́n sì kún inú Jóṣúà ọmọ Núnì torí Mósè ti gbé ọwọ́ lé e;+ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì wá ń fetí sí i, wọ́n sì ṣe ohun tí Jèhófà pa láṣẹ fún Mósè gẹ́lẹ́.+ 10 Àmọ́ látìgbà náà, kò tíì sí wòlíì kankan ní Ísírẹ́lì bíi Mósè,+ ẹni tí Jèhófà mọ̀ lójúkojú.+ 11 Ó ṣe gbogbo iṣẹ́ àmì àti iṣẹ́ ìyanu tí Jèhófà ní kó lọ ṣe ní ilẹ̀ Íjíbítì sí Fáráò àti gbogbo àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ àti gbogbo ilẹ̀ rẹ̀,+ 12 pẹ̀lú ọwọ́ agbára àti agbára tó kàmàmà tí Mósè fi hàn lójú gbogbo Ísírẹ́lì.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́