ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 3
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jẹ́nẹ́sísì

      • Bí èèyàn ṣe kọ́kọ́ dẹ́ṣẹ̀ (1-13)

        • Irọ́ àkọ́kọ́ (4, 5)

      • Jèhófà dá àwọn ọlọ̀tẹ̀ lẹ́jọ́ (14-24)

        • Àsọtẹ́lẹ̀ nípa ọmọ obìnrin náà (15)

        • Ọlọ́run lé Ádámù àti Éfà jáde ní Édẹ́nì (23, 24)

Jẹ́nẹ́sísì 3:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ló gbọ́n jù.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kọ 11:3; Ifi 12:9; 20:2
  • +Jẹ 2:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 26

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    6/2020, ojú ìwé 4

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    2/2017, ojú ìwé 5

    Ilé Ìṣọ́,

    5/15/2011, ojú ìwé 16-17

    1/1/2011, ojú ìwé 12

    9/1/2004, ojú ìwé 14-15

    11/15/2001, ojú ìwé 27

    7/1/2001, ojú ìwé 19

    2/1/1996, ojú ìwé 23

    4/1/1994, ojú ìwé 10

    Yiyan, ojú ìwé 150-151

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 50-51

Jẹ́nẹ́sísì 3:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 2:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 26

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 51

Jẹ́nẹ́sísì 3:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 2:8, 9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 26

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 51-52

Jẹ́nẹ́sísì 3:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 8:44; 1Jo 3:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 26

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    6/2020, ojú ìwé 4

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2019, ojú ìwé 15

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    10/2018, ojú ìwé 6-7

    Bíbélì Kọ́ Wa, ojú ìwé 65-66

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2014, ojú ìwé 9

    9/15/2007, ojú ìwé 5-6

    4/1/1994, ojú ìwé 10

    Bíbélì Fi Kọ́ni, ojú ìwé 61-63

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 120-121

    Ìmọ̀, ojú ìwé 73

    Yiyan, ojú ìwé 150-151

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 52

Jẹ́nẹ́sísì 3:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 3:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 26

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    4/2018, ojú ìwé 6

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    2/2017, ojú ìwé 5

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    8/2016, ojú ìwé 9

    Bíbélì Kọ́ Wa, ojú ìwé 65-66

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2014, ojú ìwé 9-10

    5/15/2011, ojú ìwé 16-17

    7/15/2009, ojú ìwé 9

    9/15/2007, ojú ìwé 5-7

    9/1/2004, ojú ìwé 14-15

    4/1/1994, ojú ìwé 11-13

    Bíbélì Fi Kọ́ni, ojú ìwé 61-63

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 120-121

    Jí!,

    7/2006, ojú ìwé 28-29

    Ìmọ̀, ojú ìwé 73

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 52

Jẹ́nẹ́sísì 3:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kọ 11:3; 1Ti 2:14; Jem 1:14, 15
  • +Ro 5:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 26

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2013, ojú ìwé 15

    5/15/2011, ojú ìwé 16-17

    11/15/2000, ojú ìwé 25-26

    Yiyan, ojú ìwé 150-151

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 52-53

Jẹ́nẹ́sísì 3:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 3:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    3/2019, ojú ìwé 5-6

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 53-54

Jẹ́nẹ́sísì 3:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “àkókò tí atẹ́gùn máa ń fẹ́ lóòjọ́.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2004, ojú ìwé 29

    7/1/2001, ojú ìwé 7

    8/1/1991, ojú ìwé 21

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 53-54

Jẹ́nẹ́sísì 3:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/1/2006, ojú ìwé 4-5

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 53-54

Jẹ́nẹ́sísì 3:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 2:25
  • +Jẹ 2:17

Jẹ́nẹ́sísì 3:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2014, ojú ìwé 7

    6/15/1997, ojú ìwé 15

    11/15/1992, ojú ìwé 15

    10/15/1992, ojú ìwé 6

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 54

Jẹ́nẹ́sísì 3:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kọ 11:3; 1Ti 2:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jí!,

    9/8/1998, ojú ìwé 24

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 54

Jẹ́nẹ́sísì 3:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 3:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2007, ojú ìwé 31

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 54-55

Jẹ́nẹ́sísì 3:15

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “kórìíra ara yín.”

  • *

    Ní Héb., “èso.”

  • *

    Ní Héb., “èso.”

  • *

    Tàbí “dọ́gbẹ́ sí ọ lórí; ṣe ọ́ lẹ́ṣe ní orí.”

  • *

    Tàbí “dọ́gbẹ́ sí i; fọ́ ọ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ifi 12:9
  • +Ifi 12:1
  • +Ifi 12:7, 17
  • +Jo 8:44; 1Jo 3:10
  • +Jẹ 22:18; 49:10; Ga 3:16, 29
  • +Ifi 20:2, 10
  • +Mt 27:50; Iṣe 3:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    9/2016, ojú ìwé 25-26

    8/2016, ojú ìwé 9

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2014, ojú ìwé 8-9, 13-14

    9/15/2012, ojú ìwé 7

    6/15/2012, ojú ìwé 7-11, 15, 19

    1/1/2011, ojú ìwé 10

    9/15/2009, ojú ìwé 26-27

    5/15/2009, ojú ìwé 22

    12/15/2008, ojú ìwé 14-15

    11/15/2008, ojú ìwé 27

    12/1/2007, ojú ìwé 23-25, 26-28

    1/1/2007, ojú ìwé 20

    6/1/2006, ojú ìwé 23-24

    2/15/2006, ojú ìwé 4, 17, 18-19

    5/1/2005, ojú ìwé 11-12

    11/15/2004, ojú ìwé 30

    8/15/2000, ojú ìwé 13

    7/15/2000, ojú ìwé 13

    5/15/2000, ojú ìwé 15-16

    4/15/1999, ojú ìwé 10-11

    2/1/1998, ojú ìwé 9-10, 13, 17-18

    6/1/1997, ojú ìwé 8-9

    6/1/1996, ojú ìwé 9-14

    2/1/1994, ojú ìwé 10-11

    10/1/1992, ojú ìwé 8

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 189-196

    Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso!, ojú ìwé 33-35

    Kí Ló Wà Nínú Bíbélì?, ojú ìwé 5, 28

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 10-14, 181, 286-295

    Jọ́sìn Ọlọ́run, ojú ìwé 33-35

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 54, 55-56, 79, 132, 134, 169, 185-186, 190-191

Jẹ́nẹ́sísì 3:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2012, ojú ìwé 4

    8/15/1998, ojú ìwé 6

    6/15/1997, ojú ìwé 15

    9/15/1995, ojú ìwé 20-21

    7/15/1995, ojú ìwé 11

    8/15/1993, ojú ìwé 5-6

    10/15/1992, ojú ìwé 6

    7/1/1991, ojú ìwé 11

    Jí!,

    11/8/2005, ojú ìwé 23

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 56-57

Jẹ́nẹ́sísì 3:17

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ó túmọ̀ sí “Ẹni Tí A Fi Erùpẹ̀ Mọ; Èèyàn; Aráyé.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 2:17
  • +Jẹ 5:29
  • +Ro 8:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2004, ojú ìwé 29

    11/1/1996, ojú ìwé 7-8

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 58-59, 67

Jẹ́nẹ́sísì 3:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 2:7
  • +Sm 104:29; Onw 3:20; 12:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde),

    No. 3 2019 ojú ìwé 8-9

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2015, ojú ìwé 5

    7/15/2001, ojú ìwé 5

    4/1/1999, ojú ìwé 16

    5/15/1995, ojú ìwé 4

    Bíbélì Kọ́ Wa, ojú ìwé 66

    Bíbélì Fi Kọ́ni, ojú ìwé 63

    Ẹmi Awọn Oku, ojú ìwé 4

    Ìmọ̀, ojú ìwé 58

    Ayọ, ojú ìwé 113

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 58

Jẹ́nẹ́sísì 3:20

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ó túmọ̀ sí “Ẹni Tó Wà Láàyè.”

  • *

    Ní Héb., “gbogbo èèyàn tó wà láàyè.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 17:26

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/1999, ojú ìwé 17

Jẹ́nẹ́sísì 3:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 3:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    11/2018, ojú ìwé 28

    Ilé Ìṣọ́,

    8/1/2006, ojú ìwé 5

    6/15/2005, ojú ìwé 9-10

Jẹ́nẹ́sísì 3:22

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “títí ayérayé.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 3:5
  • +Jẹ 2:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, ojú ìwé 1702

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2011, ojú ìwé 8

    10/15/2003, ojú ìwé 27

    11/15/2000, ojú ìwé 27

    4/15/1999, ojú ìwé 7-8

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 59

Jẹ́nẹ́sísì 3:23

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 2:8
  • +Jẹ 3:19

Jẹ́nẹ́sísì 3:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 80:1; Ais 37:16; Isk 10:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    4/2016, ojú ìwé 12-14

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2013, ojú ìwé 14

    1/1/2009, ojú ìwé 12

    Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ, ojú ìwé 13

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 306

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 59

Àwọn míì

Jẹ́n. 3:12Kọ 11:3; Ifi 12:9; 20:2
Jẹ́n. 3:1Jẹ 2:17
Jẹ́n. 3:2Jẹ 2:16
Jẹ́n. 3:3Jẹ 2:8, 9
Jẹ́n. 3:4Jo 8:44; 1Jo 3:8
Jẹ́n. 3:5Jẹ 3:22
Jẹ́n. 3:62Kọ 11:3; 1Ti 2:14; Jem 1:14, 15
Jẹ́n. 3:6Ro 5:12
Jẹ́n. 3:7Jẹ 3:21
Jẹ́n. 3:11Jẹ 2:25
Jẹ́n. 3:11Jẹ 2:17
Jẹ́n. 3:132Kọ 11:3; 1Ti 2:14
Jẹ́n. 3:14Jẹ 3:1
Jẹ́n. 3:15Ifi 12:9
Jẹ́n. 3:15Ifi 12:1
Jẹ́n. 3:15Ifi 12:7, 17
Jẹ́n. 3:15Jo 8:44; 1Jo 3:10
Jẹ́n. 3:15Jẹ 22:18; 49:10; Ga 3:16, 29
Jẹ́n. 3:15Ifi 20:2, 10
Jẹ́n. 3:15Mt 27:50; Iṣe 3:15
Jẹ́n. 3:17Jẹ 2:17
Jẹ́n. 3:17Jẹ 5:29
Jẹ́n. 3:17Ro 8:20
Jẹ́n. 3:19Jẹ 2:7
Jẹ́n. 3:19Sm 104:29; Onw 3:20; 12:7
Jẹ́n. 3:20Iṣe 17:26
Jẹ́n. 3:21Jẹ 3:7
Jẹ́n. 3:22Jẹ 3:5
Jẹ́n. 3:22Jẹ 2:9
Jẹ́n. 3:23Jẹ 2:8
Jẹ́n. 3:23Jẹ 3:19
Jẹ́n. 3:24Sm 80:1; Ais 37:16; Isk 10:4
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Jẹ́nẹ́sísì 3:1-24

Jẹ́nẹ́sísì

3 Nínú gbogbo ẹranko tí Jèhófà Ọlọ́run dá, ejò+ ló máa ń ṣọ́ra jù.* Ó sọ fún obìnrin náà pé: “Ṣé òótọ́ ni Ọlọ́run sọ pé ẹ kò gbọ́dọ̀ jẹ nínú èso gbogbo igi inú ọgbà?”+ 2 Ni obìnrin náà bá sọ fún ejò yẹn pé: “A lè jẹ lára àwọn èso igi inú ọgbà.+ 3 Àmọ́ Ọlọ́run sọ fún wa nípa èso igi tó wà láàárín ọgbà+ pé: ‘Ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ ẹ́, kódà, ẹ ò gbọ́dọ̀ fọwọ́ kàn án; kí ẹ má bàa kú.’” 4 Ejò yẹn wá sọ fún obìnrin náà pé: “Ó dájú pé ẹ ò ní kú.+ 5 Torí Ọlọ́run mọ̀ pé ọjọ́ tí ẹ bá jẹ ẹ́ ni ojú yín máa là, ẹ máa dà bí Ọlọ́run, ẹ sì máa mọ rere àti búburú.”+

6 Obìnrin náà wá rí i pé èso igi náà dára fún jíjẹ, ó dùn-ún wò, àní, igi náà wuni. Ló bá mú lára èso rẹ̀, ó sì jẹ ẹ́.+ Lẹ́yìn náà, ó fún ọkọ rẹ̀ lára èso náà nígbà tó wà lọ́dọ̀ rẹ̀, òun náà sì jẹ ẹ́.+ 7 Ni ojú àwọn méjèèjì bá là, wọ́n sì wá rí i pé ìhòòhò ni àwọn wà. Torí náà, wọ́n so ewé ọ̀pọ̀tọ́ pọ̀, wọ́n sì ṣe bàǹtẹ́ fún ara wọn.+

8 Lẹ́yìn náà, wọ́n gbọ́ ohùn Jèhófà Ọlọ́run nígbà tó ń rìn nínú ọgbà ní àkókò tí atẹ́gùn máa ń fẹ́ lọ́wọ́ ìrọ̀lẹ́,* ọkùnrin náà àti ìyàwó rẹ̀ sì lọ fara pa mọ́ sáàárín àwọn igi inú ọgbà, kí Jèhófà Ọlọ́run má bàa rí wọn. 9 Jèhófà Ọlọ́run sì ń pe ọkùnrin náà, ó ń sọ pé: “Ibo lo wà?” 10 Níkẹyìn, ọkùnrin náà fèsì pé: “Mo gbọ́ ohùn rẹ nínú ọgbà, àmọ́ ẹ̀rù bà mí torí pé mo wà ní ìhòòhò, mo wá lọ fara pa mọ́.” 11 Ó sọ fún un pé: “Ta ló sọ fún ọ pé o wà ní ìhòòhò?+ Ṣé o jẹ èso igi tí mo pàṣẹ fún ọ pé kí o má jẹ ni?”+ 12 Ọkùnrin náà sọ pé: “Obìnrin tí o fún mi pé kó wà pẹ̀lú mi ni, òun ló fún mi ní èso igi náà, mo sì jẹ ẹ́.” 13 Ni Jèhófà Ọlọ́run bá sọ fún obìnrin náà pé: “Kí lo ṣe yìí?” Obìnrin náà fèsì pé: “Ejò ló tàn mí, tí mo fi jẹ ẹ́.”+

14 Jèhófà Ọlọ́run wá sọ fún ejò+ náà pé: “Torí ohun tí o ṣe yìí, ègún ni fún ọ nínú gbogbo ẹran ọ̀sìn àti gbogbo ẹranko. Ikùn rẹ ni wàá máa fi wọ́, erùpẹ̀ ni wàá sì máa jẹ ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ. 15 Màá mú kí ìwọ+ àti obìnrin+ náà di ọ̀tá+ ara yín,* ọmọ* rẹ+ àti ọmọ* rẹ̀+ yóò sì di ọ̀tá. Òun yóò fọ́ orí rẹ,*+ ìwọ yóò sì ṣe é léṣe* ní gìgísẹ̀.”+

16 Ó sọ fún obìnrin náà pé: “Èmi yóò mú kí ìrora rẹ pọ̀ gan-an tí o bá lóyún; inú ìrora ni wàá ti máa bímọ, ọkàn rẹ á máa fà sí ọkọ rẹ, á sì máa jọba lé ọ lórí.”

17 Ó sọ fún Ádámù* pé: “Torí o fetí sí ìyàwó rẹ, tí o sì jẹ èso igi tí mo pàṣẹ+ fún ọ pé, ‘O ò gbọ́dọ̀ jẹ,’ ègún ni fún ilẹ̀ nítorí rẹ.+ Inú ìrora ni wàá ti máa jẹ èso rẹ̀ ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ.+ 18 Ẹ̀gún àti òṣùṣú ni yóò máa hù jáde fún ọ, ewéko ni wàá sì máa jẹ. 19 Inú òógùn ojú rẹ ni wàá ti máa jẹun títí wàá fi pa dà sí ilẹ̀, torí inú rẹ̀ lo ti wá.+ Erùpẹ̀ ni ọ́, ìwọ yóò sì pa dà sí erùpẹ̀.”+

20 Lẹ́yìn èyí, Ádámù sọ ìyàwó rẹ̀ ní Éfà,* torí òun ló máa di ìyá gbogbo èèyàn.*+ 21 Jèhófà Ọlọ́run sì fi awọ ṣe aṣọ gígùn fún Ádámù àti ìyàwó rẹ̀ tí wọ́n á máa wọ̀.+ 22 Jèhófà Ọlọ́run wá sọ pé: “Ọkùnrin náà ti dà bí ọ̀kan lára wa, ó ti mọ rere àti búburú.+ Ní báyìí, kó má bàa na ọwọ́ rẹ̀, kó sì tún mú èso igi ìyè,+ kó jẹ ẹ́, kó sì wà láàyè títí láé,*—” 23 Ni Jèhófà Ọlọ́run bá lé e kúrò nínú ọgbà Édẹ́nì  + kó lè máa ro ilẹ̀ tí a ti mú un jáde.+ 24 Torí náà, ó lé ọkùnrin náà jáde, ó sì fi àwọn kérúbù+ àti idà oníná tó ń yí láìdáwọ́ dúró sí ìlà oòrùn ọgbà Édẹ́nì, kí wọ́n lè máa ṣọ́ ọ̀nà tó lọ síbi igi ìyè náà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́