ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 25
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Ọlọ́run máa bù kún àwọn èèyàn rẹ̀ lọ́pọ̀ yanturu (1-12)

        • Àkànṣe àsè Jèhófà tó ní wáìnì tó dáa (6)

        • Kò ní sí ikú mọ́ (8)

Àìsáyà 25:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Àwọn ìmọ̀ràn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 40:5; 98:1; 107:8; 145:1, 4
  • +Sm 33:11
  • +Di 32:4; Ne 9:33

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2001, ojú ìwé 14

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 271

Àìsáyà 25:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2001, ojú ìwé 12

    3/1/2001, ojú ìwé 14

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 271

Àìsáyà 25:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 46:10; 66:3; Isk 38:23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2001, ojú ìwé 14-15

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 272

Àìsáyà 25:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 46:1; Na 1:7; Sef 3:12
  • +Sm 91:1; 121:5-7; Ais 49:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2019, ojú ìwé 6-7

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2001, ojú ìwé 15-16

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 272-273

Àìsáyà 25:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àwọsánmà.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2001, ojú ìwé 15-16

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 272-273

Àìsáyà 25:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “wáìnì tó wà lórí gẹ̀dẹ̀gẹ́dẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 11:9; 65:25
  • +Sm 72:16; 85:11, 12; Jer 31:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    1/2017, ojú ìwé 2

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2001, ojú ìwé 16

    1/15/1995, ojú ìwé 20

    7/1/1994, ojú ìwé 11

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 273-275

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 175

Àìsáyà 25:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “gbé ohun tó ń bo gbogbo èèyàn mì.”

  • *

    Tàbí “ìbòjú.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/15/2014, ojú ìwé 25, 26-27

    8/15/2009, ojú ìwé 6

    12/1/2006, ojú ìwé 11

    4/15/2001, ojú ìwé 13

    3/1/2001, ojú ìwé 16

    1/15/1995, ojú ìwé 20

    1/15/1993, ojú ìwé 9-10

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 273-274

Àìsáyà 25:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “mú ikú kúrò.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ho 13:14; 1Kọ 15:54; 2Ti 1:10; Ifi 20:14
  • +Ais 35:10; Ifi 7:17; 21:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/15/2014, ojú ìwé 25-27

    8/15/2009, ojú ìwé 6

    4/15/2001, ojú ìwé 13

    3/1/2001, ojú ìwé 17

    1/15/1995, ojú ìwé 20

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 303

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 273-274

Àìsáyà 25:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 25:1
  • +Sm 37:34; 146:5
  • +Mik 7:7
  • +Sm 20:5; Sef 3:14, 15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 15

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2003, ojú ìwé 10

Àìsáyà 25:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 132:13, 14; Ais 12:6
  • +Ais 15:1; Sef 2:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 274-276

Àìsáyà 25:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 48:29; Jem 4:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 274-276

Àìsáyà 25:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 274-276

Àwọn míì

Àìsá. 25:1Sm 40:5; 98:1; 107:8; 145:1, 4
Àìsá. 25:1Sm 33:11
Àìsá. 25:1Di 32:4; Ne 9:33
Àìsá. 25:3Sm 46:10; 66:3; Isk 38:23
Àìsá. 25:4Sm 46:1; Na 1:7; Sef 3:12
Àìsá. 25:4Sm 91:1; 121:5-7; Ais 49:10
Àìsá. 25:6Ais 11:9; 65:25
Àìsá. 25:6Sm 72:16; 85:11, 12; Jer 31:12
Àìsá. 25:8Ho 13:14; 1Kọ 15:54; 2Ti 1:10; Ifi 20:14
Àìsá. 25:8Ais 35:10; Ifi 7:17; 21:4
Àìsá. 25:9Ais 25:1
Àìsá. 25:9Sm 37:34; 146:5
Àìsá. 25:9Mik 7:7
Àìsá. 25:9Sm 20:5; Sef 3:14, 15
Àìsá. 25:10Sm 132:13, 14; Ais 12:6
Àìsá. 25:10Ais 15:1; Sef 2:9
Àìsá. 25:11Jer 48:29; Jem 4:6
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 25:1-12

Àìsáyà

25 Jèhófà, ìwọ ni Ọlọ́run mi.

Mo gbé ọ ga, mo yin orúkọ rẹ,

Torí o ti ṣe àwọn ohun àgbàyanu,+

Àwọn ohun tí o pinnu* láti ìgbà àtijọ́,+

Nínú òtítọ́,+ nínú ìfọkàntán.

 2 Torí o ti sọ ìlú kan di òkúta tí a tò jọ pelemọ,

O ti sọ ìlú olódi di ibi tí a rún wómúwómú.

Ilé gogoro àjèjì kì í ṣe ìlú mọ́;

Wọn ò ní tún un kọ́ láé.

 3 Ìdí nìyẹn tí àwọn èèyàn tó lágbára fi máa yìn ọ́ lógo;

Àwọn orílẹ̀-èdè oníkà máa bẹ̀rù rẹ.+

 4 Torí o ti di ibi ààbò fún ẹni rírẹlẹ̀,

Ibi ààbò fún aláìní nínú ìdààmú rẹ̀,+

Ibi ààbò kúrò lọ́wọ́ ìjì òjò,

Àti ibòji kúrò lọ́wọ́ ooru.+

Nígbà tí atẹ́gùn líle àwọn ìkà bá dà bí ìjì òjò tó kọ lu ògiri,

 5 Bí ooru ní ilẹ̀ tí kò lómi,

O dáwọ́ ariwo àwọn àjèjì dúró.

Bí òjìji ìkùukùu* ṣe ń lé ooru lọ,

Bẹ́ẹ̀ ni a máa mú kí orin àwọn ìkà dáwọ́ dúró.

 6 Lórí òkè yìí,+ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun máa se àkànṣe àsè tó dọ́ṣọ̀+

Fún gbogbo èèyàn,

Àkànṣe àsè tó ní wáìnì tó dáa,*

Àsè tó dọ́ṣọ̀ tí mùdùnmúdùn kún inú rẹ̀,

Àsè tó ní wáìnì tó dáa tí wọ́n sẹ́.

 7 Lórí òkè yìí, ó máa mú ohun tó ń bo gbogbo èèyàn kúrò*

Àti aṣọ* tí wọ́n hun bo gbogbo orílẹ̀-èdè.

 8 Ó máa gbé ikú mì* títí láé,+

Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sì máa nu omijé kúrò ní ojú gbogbo èèyàn.+

Ó máa mú ẹ̀gàn àwọn èèyàn rẹ̀ kúrò ní gbogbo ayé,

Torí Jèhófà fúnra rẹ̀ ti sọ ọ́.

 9 Ní ọjọ́ yẹn, wọ́n máa sọ pé:

“Wò ó! Ọlọ́run wa nìyí!+

A ti gbẹ́kẹ̀ lé e,+

Ó sì máa gbà wá là.+

Jèhófà nìyí!

A ti gbẹ́kẹ̀ lé e.

Ẹ jẹ́ ká máa yọ̀, kí inú wa sì dùn torí ìgbàlà rẹ̀.”+

10 Torí ọwọ́ Jèhófà máa wà lórí òkè yìí,+

A sì máa tẹ Móábù mọ́lẹ̀ ní àyè rẹ̀+

Bíi pòròpórò tí wọ́n tẹ̀ mọ́ inú ajílẹ̀ tí wọ́n kó jọ.

11 Ó máa na ọwọ́ rẹ̀ jáde sínú rẹ̀

Bí ìgbà tí òmùwẹ̀ bá na ọwọ́ rẹ̀ jáde láti lúwẹ̀ẹ́,

Ó sì máa rẹ ìgbéraga rẹ̀ wálẹ̀,+

Pẹ̀lú bó ṣe ń gbé ọwọ́ rẹ̀ lọ́nà tó já fáfá.

12 Ó sì máa wó ìlú olódi rẹ lulẹ̀,

Pẹ̀lú àwọn ògiri gíga tí o fi ṣe ààbò;

Ó máa wó o palẹ̀, ó máa wó o lulẹ̀ pátápátá.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́