ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Kọ́ríńtì 6
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Kọ́ríńtì

      • Àwọn ará ń gbéra wọn lọ sílé ẹjọ́ (1-8)

      • Àwọn tí kò ní jogún Ìjọba Ọlọ́run (9-11)

      • Ẹ máa yin Ọlọ́run lógo nínú ara yín (12-20)

        • “Ẹ máa sá fún ìṣekúṣe!” (18)

1 Kọ́ríńtì 6:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 18:15-17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    5/1/1995, ojú ìwé 30

1 Kọ́ríńtì 6:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ifi 2:26, 27; 20:4

1 Kọ́ríńtì 6:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 16:20

1 Kọ́ríńtì 6:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 18:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    10/15/1995, ojú ìwé 20

1 Kọ́ríńtì 6:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 5:39, 40

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/1/2002, ojú ìwé 6

    3/15/1997, ojú ìwé 21-22

    3/15/1996, ojú ìwé 15

    5/1/1995, ojú ìwé 30

1 Kọ́ríńtì 6:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tàn yín jẹ.”

  • *

    Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀, “Ìṣekúṣe.”

  • *

    Tàbí “àwọn ọkùnrin tó ń bá ọkùnrin lò pọ̀.” Ní Grk., “àwọn ọkùnrin tó ń bá ọkùnrin sùn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ef 5:5; Ifi 22:15
  • +Ifi 21:8
  • +Kol 3:5
  • +Heb 13:4
  • +Ro 1:27
  • +1Ti 1:9, 10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 31

    Ilé Ìṣọ́,

    5/1/2008, ojú ìwé 21-22

1 Kọ́ríńtì 6:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ẹlẹ́rẹ̀kẹ́ èébú.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 5:11
  • +Di 21:20, 21; Owe 23:20; 1Pe 4:3
  • +Heb 12:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 31

    Ilé Ìṣọ́,

    5/1/2008, ojú ìwé 21-22

1 Kọ́ríńtì 6:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 22:16; Heb 10:22
  • +Ef 5:25, 26; 2Tẹ 2:13
  • +Ro 5:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 31

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2010, ojú ìwé 9-10

    4/15/2010, ojú ìwé 9

1 Kọ́ríńtì 6:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “làyè gbà.”

  • *

    Tàbí “mú mi wá sábẹ́ àṣẹ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 10:23

1 Kọ́ríńtì 6:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Lédè Gíríìkì, por·neiʹa. Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 14:17
  • +1Tẹ 4:3

1 Kọ́ríńtì 6:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 2:24
  • +2Kọ 4:14
  • +Ro 8:11; Ef 1:19, 20

1 Kọ́ríńtì 6:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 12:4, 5; 1Kọ 12:18, 27; Ef 4:15; 5:29, 30

1 Kọ́ríńtì 6:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 2:24; Mt 19:4, 5

1 Kọ́ríńtì 6:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 17:20, 21

1 Kọ́ríńtì 6:18

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Lédè Gíríìkì, por·neiʹa. Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 39:10-12; 1Tẹ 4:3
  • +Ro 1:24, 27

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 41

    Jí!,

    11/2013, ojú ìwé 7

    1/2010, ojú ìwé 23

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2008, ojú ìwé 27

    6/15/2008, ojú ìwé 10

    2/15/2004, ojú ìwé 12-14

    9/1/1999, ojú ìwé 12-13

    4/15/1993, ojú ìwé 16-17

1 Kọ́ríńtì 6:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kọ 6:16
  • +1Kọ 3:16
  • +Ro 14:8

1 Kọ́ríńtì 6:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 7:23; Heb 9:12; 1Pe 1:18, 19
  • +Mt 5:16
  • +Ro 12:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2005, ojú ìwé 15-20

    2/15/1991, ojú ìwé 15-20

Àwọn míì

1 Kọ́r. 6:1Mt 18:15-17
1 Kọ́r. 6:2Ifi 2:26, 27; 20:4
1 Kọ́r. 6:3Ro 16:20
1 Kọ́r. 6:4Mt 18:17
1 Kọ́r. 6:7Mt 5:39, 40
1 Kọ́r. 6:9Ef 5:5; Ifi 22:15
1 Kọ́r. 6:9Ifi 21:8
1 Kọ́r. 6:9Kol 3:5
1 Kọ́r. 6:9Heb 13:4
1 Kọ́r. 6:9Ro 1:27
1 Kọ́r. 6:91Ti 1:9, 10
1 Kọ́r. 6:101Kọ 5:11
1 Kọ́r. 6:10Di 21:20, 21; Owe 23:20; 1Pe 4:3
1 Kọ́r. 6:10Heb 12:14
1 Kọ́r. 6:11Iṣe 22:16; Heb 10:22
1 Kọ́r. 6:11Ef 5:25, 26; 2Tẹ 2:13
1 Kọ́r. 6:11Ro 5:18
1 Kọ́r. 6:121Kọ 10:23
1 Kọ́r. 6:13Ro 14:17
1 Kọ́r. 6:131Tẹ 4:3
1 Kọ́r. 6:14Iṣe 2:24
1 Kọ́r. 6:142Kọ 4:14
1 Kọ́r. 6:14Ro 8:11; Ef 1:19, 20
1 Kọ́r. 6:15Ro 12:4, 5; 1Kọ 12:18, 27; Ef 4:15; 5:29, 30
1 Kọ́r. 6:16Jẹ 2:24; Mt 19:4, 5
1 Kọ́r. 6:17Jo 17:20, 21
1 Kọ́r. 6:18Jẹ 39:10-12; 1Tẹ 4:3
1 Kọ́r. 6:18Ro 1:24, 27
1 Kọ́r. 6:192Kọ 6:16
1 Kọ́r. 6:191Kọ 3:16
1 Kọ́r. 6:19Ro 14:8
1 Kọ́r. 6:201Kọ 7:23; Heb 9:12; 1Pe 1:18, 19
1 Kọ́r. 6:20Mt 5:16
1 Kọ́r. 6:20Ro 12:1
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
1 Kọ́ríńtì 6:1-20

Ìwé Kìíní sí Àwọn Ará Kọ́ríńtì

6 Ṣé ó yẹ kí ẹnikẹ́ni nínú yín tó ní èdèkòyédè pẹ̀lú ẹnì kan+ gbójúgbóyà lọ sí ilé ẹjọ́ níwájú àwọn aláìṣòdodo, tí kì í sì í ṣe níwájú àwọn ẹni mímọ́? 2 Àbí ẹ ò mọ̀ pé àwọn ẹni mímọ́ ló máa ṣèdájọ́ ayé?+ Tó bá sì jẹ́ pé ẹ̀yin lẹ máa ṣèdájọ́ ayé, ṣé ẹ ò mọ bí ẹ ṣe máa gbọ́ ẹjọ́ lórí àwọn ọ̀ràn tí kò tó nǹkan ni? 3 Ṣé ẹ ò mọ̀ pé àwa la máa ṣèdájọ́ àwọn áńgẹ́lì ni?+ Kí ló wá dé tí a ò lè yanjú àwọn ọ̀ràn ti ayé yìí? 4 Tí ẹ bá wá ní àwọn ọ̀ràn ayé yìí tí ẹ fẹ́ gbọ́ ẹjọ́ rẹ̀,+ ṣé àwọn ọkùnrin tí ìjọ ń fojú àbùkù wò ló yẹ kí ẹ yàn ṣe onídàájọ́? 5 Mò ń sọ̀rọ̀ kí ojú lè tì yín. Ṣé kò sí ọlọ́gbọ́n kankan láàárín yín tó lè ṣèdájọ́ láàárín àwọn arákùnrin rẹ̀ ni? 6 Arákùnrin wá ń gbé arákùnrin lọ sí ilé ẹjọ́, ó tún wá jẹ́ níwájú àwọn aláìgbàgbọ́!

7 Ní tòótọ́, ẹ ti pa ara yín láyò bí ẹ ṣe ń pe ara yín lẹ́jọ́. Ẹ ò ṣe kúkú gbà kí wọ́n ṣe àìtọ́ sí yín?+ Ẹ ò ṣe kúkú jẹ́ kí wọ́n lù yín ní jìbìtì? 8 Kàkà bẹ́ẹ̀, ẹ̀ ń ṣe àìtọ́, ẹ sì ń lu jìbìtì, ó tún wá jẹ́ sí àwọn arákùnrin yín!

9 Àbí ẹ ò mọ̀ pé àwọn aláìṣòdodo kò ní jogún Ìjọba Ọlọ́run ni?+ Ẹ má ṣe jẹ́ kí wọ́n ṣì yín lọ́nà.* Àwọn oníṣekúṣe,*+ àwọn abọ̀rìṣà,+ àwọn alágbèrè,+ àwọn ọkùnrin tó ń jẹ́ kí ọkùnrin bá wọn lò pọ̀,+ àwọn abẹ́yà-kan-náà-lòpọ̀,*+ 10 àwọn olè, àwọn olójúkòkòrò,+ àwọn ọ̀mùtípara,+ àwọn pẹ̀gànpẹ̀gàn* àti àwọn alọ́nilọ́wọ́gbà kò ní jogún Ìjọba Ọlọ́run.+ 11 Síbẹ̀, ohun tí àwọn kan lára yín jẹ́ tẹ́lẹ̀ nìyẹn. Àmọ́ a ti wẹ̀ yín mọ́;+ a ti yà yín sí mímọ́;+ a ti pè yín ní olódodo+ ní orúkọ Olúwa wa Jésù Kristi àti nípasẹ̀ ẹ̀mí Ọlọ́run wa.

12 Ohun gbogbo ló bófin mu* lójú mi, àmọ́ kì í ṣe ohun gbogbo ló ṣàǹfààní.+ Ohun gbogbo ló bófin mu lójú mi, àmọ́ mi ò ní jẹ́ kí ohunkóhun máa darí mi.* 13 Oúnjẹ wà fún ikùn, ikùn sì wà fún oúnjẹ, àmọ́ Ọlọ́run máa sọ àwọn méjèèjì di asán.+ Ara kò wà fún ìṣekúṣe,* Olúwa ló wà fún,+ Olúwa sì wà fún ara. 14 Àmọ́ Ọlọ́run gbé Olúwa dìde,+ yóò sì gbé àwa náà dìde kúrò nínú ikú+ nípasẹ̀ agbára rẹ̀.+

15 Ṣé ẹ ò mọ̀ pé ẹ̀yà ara Kristi ni ara yín ni?+ Ṣé ó wá yẹ kí n mú ẹ̀yà ara Kristi kúrò, kí n sì dà á pọ̀ mọ́ ti aṣẹ́wó? Ká má ri! 16 Ṣé ẹ ò mọ̀ pé ẹni tó bá ní àṣepọ̀ pẹ̀lú aṣẹ́wó á di ara kan pẹ̀lú rẹ̀ ni? Nítorí Ọlọ́run sọ pé “àwọn méjèèjì á sì di ara kan.”+ 17 Àmọ́ ẹni tó bá dara pọ̀ mọ́ Olúwa jẹ́ ọ̀kan pẹ̀lú rẹ̀ nínú ẹ̀mí.+ 18 Ẹ máa sá fún ìṣekúṣe!*+ Gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ míì tí èèyàn lè dá wà lóde ara rẹ̀, àmọ́ ẹni tó bá ń ṣe ìṣekúṣe ń ṣẹ̀ sí ara òun fúnra rẹ̀.+ 19 Ṣé ẹ ò mọ̀ pé ara yín ni tẹ́ńpìlì+ ẹ̀mí mímọ́ tó wà nínú yín, èyí tí ẹ gbà lọ́wọ́ Ọlọ́run?+ Bákan náà, ẹ kì í ṣe ti ara yín,+ 20 nítorí a ti rà yín ní iye kan.+ Nítorí náà, ẹ máa yin Ọlọ́run lógo+ nínú ara yín.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́