ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 63
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Jèhófà máa gbẹ̀san lára àwọn orílẹ̀-èdè (1-6)

      • Bí Jèhófà ṣe fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn nígbà àtijọ́ (7-14)

      • Àdúrà ìrònúpìwàdà (15-19)

Àìsáyà 63:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “aṣọ rẹ̀ pọ́n yòò.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 137:7; Ais 34:5, 6
  • +Emọ 1:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 349-351

Àìsáyà 63:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joẹ 3:13; Ifi 14:19, 20; 19:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 352-353

Àìsáyà 63:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 34:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 352-353

Àìsáyà 63:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 34:8; 35:4; 61:1, 2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 353

Àìsáyà 63:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìṣẹ́gun.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 51:9; 52:10; 59:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2007, ojú ìwé 11

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 353-354

Àìsáyà 63:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 25:15, 16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 353-354

Àìsáyà 63:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 78:12; 105:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 354-355

Àìsáyà 63:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “já sí èké.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 24:7
  • +Ẹk 14:30

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 354, 355-356

Àìsáyà 63:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Áńgẹ́lì iwájú rẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 3:7
  • +Ẹk 14:19; 23:20
  • +Di 7:8
  • +Ẹk 19:4; Di 1:31

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde),

    No. 3 2018 ojú ìwé 8

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 354, 356

Àìsáyà 63:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 9:7
  • +Iṣe 7:51; Ef 4:30
  • +Le 26:14, 17; Di 28:63
  • +Jer 21:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 356-357

Àìsáyà 63:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 14:30; Ais 51:10
  • +Sm 77:20
  • +Nọ 11:16, 17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 357-358

Àìsáyà 63:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 6:1, 6; 15:16
  • +Ẹk 14:21, 22
  • +Ẹk 9:15, 16; 14:17; Ro 9:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 357-358

Àìsáyà 63:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ibú omi.”

  • *

    Tàbí “nínú aginjù?”

Àìsáyà 63:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tó lẹ́wà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 22:4
  • +2Sa 7:23; Ne 9:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 357-359

Àìsáyà 63:15

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ẹlẹ́wà.”

  • *

    Ní Héb., “Inú rẹ lọ́hùn-ún tó ń ru sókè.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 31:20
  • +Di 4:31; Ne 9:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 361

Àìsáyà 63:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 4:22
  • +Ais 41:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 361

Àìsáyà 63:17

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “mú ká.”

  • *

    Ní Héb., “mú kí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 6:10
  • +Sm 74:2; 80:14, 15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 361-363

Àìsáyà 63:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 36:19; Ais 64:11; Ida 1:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 363-364

Àìsáyà 63:19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 363-364

Àwọn míì

Àìsá. 63:1Sm 137:7; Ais 34:5, 6
Àìsá. 63:1Emọ 1:12
Àìsá. 63:2Joẹ 3:13; Ifi 14:19, 20; 19:15
Àìsá. 63:3Ais 34:2
Àìsá. 63:4Ais 34:8; 35:4; 61:1, 2
Àìsá. 63:5Ais 51:9; 52:10; 59:16
Àìsá. 63:6Jer 25:15, 16
Àìsá. 63:7Sm 78:12; 105:5
Àìsá. 63:8Ẹk 24:7
Àìsá. 63:8Ẹk 14:30
Àìsá. 63:9Ẹk 3:7
Àìsá. 63:9Ẹk 14:19; 23:20
Àìsá. 63:9Di 7:8
Àìsá. 63:9Ẹk 19:4; Di 1:31
Àìsá. 63:10Di 9:7
Àìsá. 63:10Iṣe 7:51; Ef 4:30
Àìsá. 63:10Le 26:14, 17; Di 28:63
Àìsá. 63:10Jer 21:5
Àìsá. 63:11Ẹk 14:30; Ais 51:10
Àìsá. 63:11Sm 77:20
Àìsá. 63:11Nọ 11:16, 17
Àìsá. 63:12Ẹk 6:1, 6; 15:16
Àìsá. 63:12Ẹk 14:21, 22
Àìsá. 63:12Ẹk 9:15, 16; 14:17; Ro 9:17
Àìsá. 63:14Joṣ 22:4
Àìsá. 63:142Sa 7:23; Ne 9:10
Àìsá. 63:15Jer 31:20
Àìsá. 63:15Di 4:31; Ne 9:17
Àìsá. 63:16Ẹk 4:22
Àìsá. 63:16Ais 41:14
Àìsá. 63:17Ais 6:10
Àìsá. 63:17Sm 74:2; 80:14, 15
Àìsá. 63:182Kr 36:19; Ais 64:11; Ida 1:10
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 63:1-19

Àìsáyà

63 Ta ló ń bọ̀ láti Édómù+ yìí,

Tó ń bọ̀ láti Bósírà,+ tó wọ aṣọ tí àwọ̀ rẹ̀ ń tàn yòò,*

Tó wọ aṣọ tó dáa gan-an,

Tó ń yan bọ̀ nínú agbára ńlá rẹ̀?

“Èmi ni, Ẹni tó ń fi òdodo sọ̀rọ̀,

Ẹni tó lágbára gan-an láti gbani là.”

 2 Kí ló dé tí aṣọ rẹ pọ́n,

Kí ló sì dé tí ẹ̀wù rẹ dà bíi ti ẹni tó ń tẹ àjàrà ní ibi tí wọ́n ti ń fún wáìnì?+

 3 “Èmi nìkan ni mo tẹ wáìnì nínú ọpọ́n.

Ìkankan nínú àwọn èèyàn náà ò sí lọ́dọ̀ mi.

Mò ń fi ìbínú tẹ̀ wọ́n ṣáá,

Mo sì ń fi ìrunú tẹ̀ wọ́n mọ́lẹ̀.+

Ẹ̀jẹ̀ wọn ta sára ẹ̀wù mi,

Ó sì ti yí gbogbo aṣọ mi.

 4 Torí pé ọjọ́ ẹ̀san wà lọ́kàn mi,+

Ọdún àwọn tí mo tún rà sì ti dé.

 5 Mo wò, àmọ́ kò sẹ́ni tó ṣèrànwọ́;

Ẹnu yà mí pé kò sẹ́ni tó tì mí lẹ́yìn.

Apá mi wá mú ìgbàlà* wá fún mi,+

Ìbínú mi sì tì mí lẹ́yìn.

 6 Mo fi ìbínú tẹ àwọn èèyàn mọ́lẹ̀,

Mo mú kí wọ́n mu ìrunú mi yó,+

Mo sì da ẹ̀jẹ̀ wọn sórí ilẹ̀.”

 7 Màá sọ̀rọ̀ nípa àwọn ohun tí Jèhófà ṣe torí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀,

Àwọn iṣẹ́ Jèhófà tó yẹ ká yìn,

Torí gbogbo ohun tí Jèhófà ti ṣe fún wa,+

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ohun rere tó ti ṣe fún ilé Ísírẹ́lì,

Nínú àánú rẹ̀ àti ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ tó lágbára.

 8 Torí ó sọ pé: “Ó dájú pé èèyàn mi ni wọ́n, àwọn ọmọ tí kò ní di aláìṣòótọ́.”*+

Ó wá di Olùgbàlà wọn.+

 9 Nínú gbogbo ìdààmú wọn, ìdààmú bá òun náà.+

Ìránṣẹ́ òun fúnra rẹ̀* sì gbà wọ́n là.+

Ó tún wọn rà nínú ìfẹ́ rẹ̀ àti ìyọ́nú rẹ̀,+

Ó gbé wọn sókè, ó sì rù wọ́n ní gbogbo ìgbà àtijọ́.+

10 Àmọ́ wọ́n ṣọ̀tẹ̀ sí i,+ wọ́n sì kó ẹ̀dùn ọkàn bá ẹ̀mí mímọ́ rẹ̀.+

Ó wá di ọ̀tá wọn,+

Ó sì bá wọn jà.+

11 Wọ́n rántí àwọn ìgbà àtijọ́,

Àwọn ọjọ́ Mósè ìránṣẹ́ rẹ̀:

“Ẹni tó mú wọn jáde látinú òkun dà,+ àwọn àti àwọn olùṣọ́ àgùntàn agbo ẹran rẹ̀?+

Ẹni tó fi ẹ̀mí mímọ́ Rẹ̀ sínú rẹ̀ dà,+

12 Ẹni tó mú kí apá Rẹ̀ ológo bá ọwọ́ ọ̀tún Mósè lọ,+

Ẹni tó pín omi níyà níwájú wọn,+

Kó lè ṣe orúkọ tó máa wà títí láé fún ara rẹ̀,+

13 Ẹni tó mú kí wọ́n rìn gba inú omi tó ń ru gùdù,*

Tó fi jẹ́ pé wọ́n rìn láìkọsẹ̀,

Bí ẹṣin ní ìgbèríko?*

14 Bí ìgbà tí ẹran ọ̀sìn bá ń sọ̀ kalẹ̀ lọ sí pẹ̀tẹ́lẹ̀,

Ẹ̀mí Jèhófà mú kí wọ́n sinmi.”+

Bí o ṣe darí àwọn èèyàn rẹ nìyí,

Kí o lè ṣe orúkọ tó gbayì* fún ara rẹ.+

15 Wo ilẹ̀ láti ọ̀run, kí o sì rí i

Láti ibùgbé rẹ mímọ́ àti ológo* tó ga.

Ìtara rẹ àti agbára rẹ dà,

Ìyọ́nú rẹ tó ń ru sókè*+ àti àánú rẹ dà?+

A ti fà wọ́n sẹ́yìn kúrò lọ́dọ̀ mi.

16 Torí ìwọ ni Bàbá wa;+

Bí Ábúráhámù ò tiẹ̀ mọ̀ wá,

Tí Ísírẹ́lì ò sì dá wa mọ̀,

Ìwọ Jèhófà, ni Bàbá wa.

Olùtúnrà wa látìgbà àtijọ́ ni orúkọ rẹ.+

17 Jèhófà, kí ló dé tí o gbà ká* rìn gbéregbère kúrò ní àwọn ọ̀nà rẹ?

Kí ló dé tí o gbà kí* ọkàn wa le, tí a ò fi bẹ̀rù rẹ?+

Pa dà, torí àwọn ìránṣẹ́ rẹ,

Àwọn ẹ̀yà ogún rẹ.+

18 Ó jẹ́ ti àwọn èèyàn mímọ́ rẹ fúngbà díẹ̀.

Àwọn ọ̀tá wa ti tẹ ibi mímọ́ rẹ mọ́lẹ̀.+

19 Ó pẹ́ gan-an tí a ti dà bí àwọn tí o kò ṣàkóso wọn rí,

Bí àwọn tí a ò fi orúkọ rẹ pè rí.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́