ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 35
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Ayé pa dà di Párádísè (1-7)

        • Afọ́jú máa ríran; adití máa gbọ́ràn (5)

      • Ọ̀nà Ìjẹ́mímọ́ fún àwọn tí a tún rà (8-10)

Àìsáyà 35:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 29:17; 32:14, 15
  • +Ais 4:2; 27:6; 35:6; 51:3; Isk 36:35

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jí!,

    No. 1 2021 ojú ìwé 13

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 369-372, 378-380

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    2/15/1996, ojú ìwé 10-11, 14-15, 18

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 129-130, 132

    “Kí Ijọba Rẹ Dé,” ojú ìwé 23

Àìsáyà 35:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ho 14:5, 6
  • +Ais 60:13
  • +Jer 50:19
  • +Ais 65:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 369-372, 379-380

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    8/15/1996, ojú ìwé 7

    2/15/1996, ojú ìwé 10-11, 14-15, 16-17

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 129-130

    “Kí Ijọba Rẹ Dé,” ojú ìwé 23

Àìsáyà 35:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 12:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 372-373, 379, 381

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    2/15/1996, ojú ìwé 11, 14

Àìsáyà 35:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 51:56
  • +Ais 25:9; Sef 3:16, 17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 372-373, 381

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    2/15/1996, ojú ìwé 11

Àìsáyà 35:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 146:8; Ais 42:16; Mt 9:28-30
  • +Ais 29:18; Jer 6:10; Mk 7:32-35; Lk 7:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 303

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 373-374, 378-381

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    2/15/1996, ojú ìwé 11, 14-15, 18

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 130-132

Àìsáyà 35:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 11:5; Iṣe 8:7; 14:8-10
  • +Mt 15:30

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 303

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 373-376, 378-381

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    2/15/1996, ojú ìwé 11-12, 16, 18

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 130-132

Àìsáyà 35:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, koríko etí omi.

  • *

    Tàbí “akátá.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 44:3
  • +Jer 9:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 374-376, 378-379

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    2/15/1996, ojú ìwé 11-12, 18

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 130-132

Àìsáyà 35:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹsr 1:3; Ais 11:16; 49:11; 62:10; Jer 31:21
  • +Ais 52:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    5/15/2008, ojú ìwé 26-28

    2/15/1996, ojú ìwé 12, 16

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 56-57

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 376-377, 380-381

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 132-135

Àìsáyà 35:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 11:6, 7; 65:25; Isk 34:25; Ho 2:18
  • +Sm 107:2, 3; Ais 62:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    5/15/2008, ojú ìwé 28

    2/15/1996, ojú ìwé 12

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 376-377, 380-381

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 133, 134-135

Àìsáyà 35:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 30:4
  • +Ais 51:11; Jer 31:11, 12
  • +Jer 33:10, 11
  • +Ais 30:19; 65:19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 303

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 377-379, 380-381

    Ilé Ìṣọ́,

    5/1/1997, ojú ìwé 20-21

    2/15/1996, ojú ìwé 8, 12, 16-18

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 135

Àwọn míì

Àìsá. 35:1Ais 29:17; 32:14, 15
Àìsá. 35:1Ais 4:2; 27:6; 35:6; 51:3; Isk 36:35
Àìsá. 35:2Ho 14:5, 6
Àìsá. 35:2Ais 60:13
Àìsá. 35:2Jer 50:19
Àìsá. 35:2Ais 65:10
Àìsá. 35:3Heb 12:12
Àìsá. 35:4Jer 51:56
Àìsá. 35:4Ais 25:9; Sef 3:16, 17
Àìsá. 35:5Sm 146:8; Ais 42:16; Mt 9:28-30
Àìsá. 35:5Ais 29:18; Jer 6:10; Mk 7:32-35; Lk 7:22
Àìsá. 35:6Mt 11:5; Iṣe 8:7; 14:8-10
Àìsá. 35:6Mt 15:30
Àìsá. 35:7Ais 44:3
Àìsá. 35:7Jer 9:11
Àìsá. 35:8Ẹsr 1:3; Ais 11:16; 49:11; 62:10; Jer 31:21
Àìsá. 35:8Ais 52:1
Àìsá. 35:9Ais 11:6, 7; 65:25; Isk 34:25; Ho 2:18
Àìsá. 35:9Sm 107:2, 3; Ais 62:12
Àìsá. 35:10Di 30:4
Àìsá. 35:10Ais 51:11; Jer 31:11, 12
Àìsá. 35:10Jer 33:10, 11
Àìsá. 35:10Ais 30:19; 65:19
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 35:1-10

Àìsáyà

35 Aginjù àti ilẹ̀ tí kò lómi máa yọ̀,+

Aṣálẹ̀ tó tẹ́jú máa yọ̀ ṣẹ̀ṣẹ̀, ó sì máa yọ ìtànná bíi sáfúrónì.+

 2 Ó dájú pé ó máa yọ ìtànná;+

Ó máa yọ̀ ṣẹ̀ṣẹ̀, ó sì máa kígbe ayọ̀.

A máa fún un ní ògo Lẹ́bánónì,+

Ẹwà Kámẹ́lì+ àti ti Ṣárónì.+

Wọ́n máa rí ògo Jèhófà, ẹwà Ọlọ́run wa.

 3 Ẹ fún àwọn ọwọ́ tí kò lágbára lókun,

Ẹ sì mú kí àwọn orúnkún tó ń gbọ̀n dúró gbọn-in.+

 4 Ẹ sọ fún àwọn tó ń ṣàníyàn nínú ọkàn wọn pé:

“Ẹ jẹ́ alágbára. Ẹ má bẹ̀rù.

Ẹ wò ó! Ọlọ́run yín máa wá gbẹ̀san,

Ọlọ́run máa wá láti fìyà ẹ̀ṣẹ̀ jẹni.+

Ó máa wá gbà yín sílẹ̀.”+

 5 Ní àkókò yẹn, ojú àwọn afọ́jú máa là,+

Etí àwọn adití sì máa ṣí.+

 6 Ní àkókò yẹn, ẹni tó yarọ máa fò sókè bí àgbọ̀nrín,+

Ahọ́n ẹni tí kò lè sọ̀rọ̀ sì máa kígbe ayọ̀.+

Torí omi máa tú jáde ní aginjù,

Odò sì máa ṣàn ní aṣálẹ̀ tó tẹ́jú.

 7 Ilẹ̀ tí ooru ti mú kó gbẹ táútáú máa di adágún omi tí esùsú* kún inú rẹ̀,

Ilẹ̀ gbígbẹ sì máa di ìsun omi.+

Koríko tútù, esùsú àti òrépèté

Máa wà ní ibùgbé tí àwọn ajáko* ti ń sinmi.+

 8 Ọ̀nà kan sì máa wà níbẹ̀,+

Àní, ọ̀nà tí à ń pè ní Ọ̀nà Ìjẹ́mímọ́.

Aláìmọ́ kò ní gba ibẹ̀ kọjá.+

Àwọn tó ń rìn lójú ọ̀nà ló wà fún;

Òmùgọ̀ kankan ò sì ní rìn gbéregbère lọ síbẹ̀.

 9 Kò ní sí kìnnìún kankan níbẹ̀,

Ẹranko ẹhànnà kankan kò sì ní wá sórí rẹ̀.

A ò ní rí wọn níbẹ̀;+

Àwọn tí a tún rà nìkan ló máa gba ibẹ̀.+

10 Àwọn tí Jèhófà rà pa dà máa pa dà wá,+ wọ́n sì máa kígbe ayọ̀ wá sí Síónì.+

Ayọ̀ tí kò lópin máa dé orí wọn ládé.+

Wọ́n á máa yọ̀ gidigidi, inú wọn á sì máa dùn,

Ẹ̀dùn ọkàn àti ìbànújẹ́ kò ní sí mọ́.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́