ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Oníwàásù 1
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Oníwàásù

      • Asán ni ohun gbogbo (1-11)

        • Ayé wà títí láé (4)

        • Àwọn ohun tó ń yí po ní ayé (5-7)

        • Kò sí ohun tuntun lábẹ́ oòrùn (9)

      • Ó níbi tí ọgbọ́n èèyàn mọ (12-18)

        • Ìmúlẹ̀mófo (14)

Oníwàásù 1:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “apenijọ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 8:1, 22
  • +1Ọb 2:12; 2Kr 9:30

Oníwàásù 1:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Òtúbáńtẹ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 39:5; Ro 8:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/1/2006, ojú ìwé 13

    6/1/1999, ojú ìwé 24

Oníwàásù 1:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “lábẹ́ oòrùn?”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Onw 2:11; Mt 16:26; Jo 6:27

Oníwàásù 1:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb.,“dúró.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 78:69; 104:5; 119:90

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde),

    No. 2 2021 ojú ìwé 4

Oníwàásù 1:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tan ìmọ́lẹ̀.”

  • *

    Tàbí “sáré tete.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 8:22; Sm 19:6

Oníwàásù 1:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “odò ìgbà òtútù; odò abágbàrìn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Job 38:8, 10
  • +Job 36:27, 28; Ais 55:10; Emọ 5:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 52-53

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2009, ojú ìwé 15-17

    2/15/1998, ojú ìwé 6

Oníwàásù 1:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/1/2006, ojú ìwé 13

Oníwàásù 1:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “lábẹ́ oòrùn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 8:22; Onw 1:4

Oníwàásù 1:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Onw 2:16; 9:5; Ais 40:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/1997, ojú ìwé 9

Oníwàásù 1:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 11:42; Onw 1:1

Oníwàásù 1:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 4:29, 30
  • +Onw 8:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/1997, ojú ìwé 13-14

Oníwàásù 1:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “lábẹ́ oòrùn.”

  • *

    Tàbí “lílépa ẹ̀fúùfù.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 39:5, 6; Onw 2:11, 18, 26; Lk 12:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2008, ojú ìwé 21

    2/15/1997, ojú ìwé 18

Oníwàásù 1:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/1/2006, ojú ìwé 14

    5/1/1999, ojú ìwé 28-29

    2/15/1997, ojú ìwé 9

Oníwàásù 1:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Onw 2:9
  • +1Ọb 3:28; 4:29-31; 2Kr 1:10-12

Oníwàásù 1:17

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìwà òmùgọ̀ tó burú jáì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Onw 2:2, 3, 12; 7:25

Oníwàásù 1:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Onw 2:15; 12:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/1997, ojú ìwé 9

    8/15/1993, ojú ìwé 12

Àwọn míì

Oníw. 1:11Ọb 8:1, 22
Oníw. 1:11Ọb 2:12; 2Kr 9:30
Oníw. 1:2Sm 39:5; Ro 8:20
Oníw. 1:3Onw 2:11; Mt 16:26; Jo 6:27
Oníw. 1:4Sm 78:69; 104:5; 119:90
Oníw. 1:5Jẹ 8:22; Sm 19:6
Oníw. 1:7Job 38:8, 10
Oníw. 1:7Job 36:27, 28; Ais 55:10; Emọ 5:8
Oníw. 1:9Jẹ 8:22; Onw 1:4
Oníw. 1:11Onw 2:16; 9:5; Ais 40:6
Oníw. 1:121Ọb 11:42; Onw 1:1
Oníw. 1:131Ọb 4:29, 30
Oníw. 1:13Onw 8:16
Oníw. 1:14Sm 39:5, 6; Onw 2:11, 18, 26; Lk 12:15
Oníw. 1:16Onw 2:9
Oníw. 1:161Ọb 3:28; 4:29-31; 2Kr 1:10-12
Oníw. 1:17Onw 2:2, 3, 12; 7:25
Oníw. 1:18Onw 2:15; 12:12
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Oníwàásù 1:1-18

Oníwàásù

1 Àwọn ọ̀rọ̀ akónijọ,*+ ọmọ Dáfídì, ọba ní Jerúsálẹ́mù.+

 2 Akónijọ sọ pé, “Asán* pátápátá gbáà!”

“Asán pátápátá gbáà! Asán ni gbogbo rẹ̀!”+

 3 Èrè wo ni èèyàn rí jẹ nínú gbogbo iṣẹ́ àṣekára rẹ̀

Èyí tó ń fi gbogbo agbára rẹ̀ ṣe lábẹ́ ọ̀run?*+

 4 Ìran kan ń lọ, ìran kan sì ń bọ̀,

Àmọ́ ayé wà* títí láé.+

 5 Oòrùn ń yọ,* oòrùn sì ń wọ̀;

Lẹ́yìn náà, ó ń yára* pa dà sí ibi tí á tún ti yọ.+

 6 Ẹ̀fúùfù ń lọ sí gúúsù, ó sì ń yí lọ sí àríwá;

Yíyí ló ń yí po nígbà gbogbo; ẹ̀fúùfù ń yí po ṣáá.

 7 Gbogbo odò* ló ń ṣàn lọ sínú òkun, síbẹ̀ òkun kò kún.+

Ibi tí àwọn odò ti ṣàn wá, ibẹ̀ ni wọ́n ń pa dà sí, kí wọ́n tún lè ṣàn jáde.+

 8 Ohun gbogbo ló ń kó àárẹ̀ báni;

Kódà, ó kọjá ohun téèyàn lè sọ.

Ìran kì í sú ojú;

Bẹ́ẹ̀ ni etí kì í kọ gbígbọ́.

 9 Ohun tó ti wà ni yóò máa wà,

Ohun tí a sì ti ṣe la ó tún pa dà ṣe;

Kò sí ohun tuntun lábẹ́ ọ̀run.*+

10 Ṣé ohun kan wà tí a lè sọ pé: “Wò ó, tuntun ni”?

Ó ti wà tipẹ́tipẹ́;

Ó ti wà ṣáájú àkókò wa.

11 Kò sí ẹni tó ń rántí àwọn èèyàn ayé àtijọ́;

Kò sì sí ẹni tó máa rántí àwọn tó ń bọ̀;

Bẹ́ẹ̀ ni àwọn tó máa wá nígbà tó bá yá kò ní rántí àwọn náà.+

12 Èmi, akónijọ, ló ti ń jọba lórí Ísírẹ́lì ní Jerúsálẹ́mù.+ 13 Mo fi ọgbọ́n+ ṣe ìwádìí àti àyẹ̀wò ohun gbogbo tí a ti ṣe lábẹ́ ọ̀run,+ ìyẹn iṣẹ́ tó ń tánni lókun tí Ọlọ́run fún ọmọ aráyé tó ń mú kí ọwọ́ wọn dí.

14 Mo rí gbogbo iṣẹ́ tí a ṣe lábẹ́ ọ̀run,*

Sì wò ó! asán ni gbogbo rẹ̀, ìmúlẹ̀mófo.*+

15 Ohun tó ti wọ́, a kò lè mú un tọ́,

Ohun tí kò sì sí, a kò lè kà á.

16 Nígbà náà, mo sọ lọ́kàn mi pé: “Wò ó! Mo ti ní ọgbọ́n tó pọ̀ gan-an ju ẹnikẹ́ni tó wà ṣáájú mi ní Jerúsálẹ́mù,+ ọkàn mi sì ti kó ọgbọ́n àti ìmọ̀+ tó pọ̀ gan-an jọ.” 17 Mo fi ọkàn mi sí mímọ ọgbọ́n àti mímọ ìwà wèrè* àti mímọ ìwà ẹ̀gọ̀,+ èyí pẹ̀lú jẹ́ ìmúlẹ̀mófo.

18 Nítorí ọ̀pọ̀ ọgbọ́n máa ń mú ọ̀pọ̀ ìbànújẹ́ wá,

Tó fi jẹ́ pé ẹni tó ń fi ìmọ̀ kún ìmọ̀ ń fi ìrora kún ìrora.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́