ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Àwọn Ọba 19
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Àwọn Ọba

      • Èlíjà sá lọ nítorí ìbínú Jésíbẹ́lì (1-8)

      • Jèhófà fara han Èlíjà ní Hórébù (9-14)

      • Ọlọ́run ní kí Èlíjà fòróró yan Hásáẹ́lì, Jéhù àti Èlíṣà (15-18)

      • Ọlọ́run yan Èlíṣà sí ipò Èlíjà (19-21)

1 Àwọn Ọba 19:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 16:29; 21:25
  • +1Ọb 16:31
  • +1Ọb 18:40

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ, ojú ìwé 101

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2011, ojú ìwé 18-19

1 Àwọn Ọba 19:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ṣe ọkàn rẹ bí ọkàn ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ, ojú ìwé 101

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2011, ojú ìwé 19

1 Àwọn Ọba 19:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọkàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 2:15; 1Sa 27:1
  • +Jẹ 21:31
  • +Joṣ 15:21, 28

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ, ojú ìwé 101-102

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2011, ojú ìwé 19

1 Àwọn Ọba 19:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọkàn òun.”

  • *

    Tàbí “ọkàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 11:15; Job 3:21; Jon 4:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    6/2019, ojú ìwé 15-16

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2014, ojú ìwé 15

    7/1/2011, ojú ìwé 19-20

    5/15/1997, ojú ìwé 13

    Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ, ojú ìwé 102-103

1 Àwọn Ọba 19:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 10:8-10; Iṣe 12:7
  • +Sm 34:7; Heb 1:7, 14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ, ojú ìwé 103

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2011, ojú ìwé 20

1 Àwọn Ọba 19:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ, ojú ìwé 103

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2011, ojú ìwé 20

1 Àwọn Ọba 19:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ, ojú ìwé 103

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2011, ojú ìwé 20

1 Àwọn Ọba 19:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 3:1; 19:18; Mal 4:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ, ojú ìwé 103-104

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2011, ojú ìwé 20-21

1 Àwọn Ọba 19:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 11:32, 38

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ, ojú ìwé 104

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2011, ojú ìwé 21

1 Àwọn Ọba 19:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọkàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 20:4, 5; Nọ 25:11; Sm 69:9
  • +Di 29:24, 25; Ond 2:20; 1Ọb 8:9; 2Ọb 17:15
  • +1Ọb 18:4
  • +1Ọb 19:2; Ro 11:2, 3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ, ojú ìwé 104

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2011, ojú ìwé 21

1 Àwọn Ọba 19:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 33:22
  • +Sm 50:3; Ais 29:6
  • +1Sa 14:15; Job 9:6; Sm 68:8; Na 1:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 37-38, 42-43

    Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ, ojú ìwé 104-106

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2011, ojú ìwé 21-22

1 Àwọn Ọba 19:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 4:11
  • +Ẹk 34:5, 6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 37-38, 42-43

    Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ, ojú ìwé 104-107

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2011, ojú ìwé 21-22

    5/15/1997, ojú ìwé 13

1 Àwọn Ọba 19:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 3:6

1 Àwọn Ọba 19:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọkàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 31:20; Sm 78:37; Ais 1:4; Jer 22:9
  • +Ro 11:2, 3

1 Àwọn Ọba 19:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 8:7, 8; Emọ 1:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ, ojú ìwé 106-107

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2011, ojú ìwé 22

    5/15/1997, ojú ìwé 13

1 Àwọn Ọba 19:16

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ó túmọ̀ sí “Ọlọ́run Ni Ìgbàlà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 9:1-3, 30-33
  • +2Ọb 2:9, 15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    5/15/1997, ojú ìwé 13

1 Àwọn Ọba 19:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 8:12; 10:32; 13:3
  • +2Ọb 9:14, 24; 10:6, 7, 23, 25
  • +2Ọb 2:23, 24

1 Àwọn Ọba 19:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 11:4
  • +Ẹk 20:5
  • +Ho 13:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ, ojú ìwé 107

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2011, ojú ìwé 22

1 Àwọn Ọba 19:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 2:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2014, ojú ìwé 12

    11/1/1997, ojú ìwé 30-31

1 Àwọn Ọba 19:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/1/1997, ojú ìwé 30-31

1 Àwọn Ọba 19:21

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ó fi wọ́n rúbọ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 24:13; 2Ọb 2:3; 3:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/1/1997, ojú ìwé 30-31

Àwọn míì

1 Ọba 19:11Ọb 16:29; 21:25
1 Ọba 19:11Ọb 16:31
1 Ọba 19:11Ọb 18:40
1 Ọba 19:3Ẹk 2:15; 1Sa 27:1
1 Ọba 19:3Jẹ 21:31
1 Ọba 19:3Joṣ 15:21, 28
1 Ọba 19:4Nọ 11:15; Job 3:21; Jon 4:3
1 Ọba 19:5Da 10:8-10; Iṣe 12:7
1 Ọba 19:5Sm 34:7; Heb 1:7, 14
1 Ọba 19:8Ẹk 3:1; 19:18; Mal 4:4
1 Ọba 19:9Heb 11:32, 38
1 Ọba 19:10Ẹk 20:4, 5; Nọ 25:11; Sm 69:9
1 Ọba 19:10Di 29:24, 25; Ond 2:20; 1Ọb 8:9; 2Ọb 17:15
1 Ọba 19:101Ọb 18:4
1 Ọba 19:101Ọb 19:2; Ro 11:2, 3
1 Ọba 19:11Ẹk 33:22
1 Ọba 19:11Sm 50:3; Ais 29:6
1 Ọba 19:111Sa 14:15; Job 9:6; Sm 68:8; Na 1:5
1 Ọba 19:12Di 4:11
1 Ọba 19:12Ẹk 34:5, 6
1 Ọba 19:13Ẹk 3:6
1 Ọba 19:14Di 31:20; Sm 78:37; Ais 1:4; Jer 22:9
1 Ọba 19:14Ro 11:2, 3
1 Ọba 19:152Ọb 8:7, 8; Emọ 1:4
1 Ọba 19:162Ọb 9:1-3, 30-33
1 Ọba 19:162Ọb 2:9, 15
1 Ọba 19:172Ọb 8:12; 10:32; 13:3
1 Ọba 19:172Ọb 9:14, 24; 10:6, 7, 23, 25
1 Ọba 19:172Ọb 2:23, 24
1 Ọba 19:18Ro 11:4
1 Ọba 19:18Ẹk 20:5
1 Ọba 19:18Ho 13:2
1 Ọba 19:192Ọb 2:8
1 Ọba 19:21Ẹk 24:13; 2Ọb 2:3; 3:11
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
1 Àwọn Ọba 19:1-21

Àwọn Ọba Kìíní

19 Nígbà náà, Áhábù+ sọ gbogbo ohun tí Èlíjà ṣe fún Jésíbẹ́lì+ àti bí ó ṣe fi idà pa gbogbo àwọn wòlíì.+ 2 Ni Jésíbẹ́lì bá rán òjíṣẹ́ kan sí Èlíjà pé: “Kí àwọn ọlọ́run fìyà jẹ mí gan-an tí mi ò bá ṣe ọ́ bí ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn* ní ìwòyí ọ̀la!” 3 Ẹ̀rù wá bẹ̀rẹ̀ sí í bà á, torí náà, ó gbéra, ó sì sá nítorí ẹ̀mí* rẹ̀.+ Ó wá sí Bíá-ṣébà+ tó jẹ́ ti Júdà,+ ó sì fi ìránṣẹ́ rẹ̀ sílẹ̀ níbẹ̀. 4 Ó rin ìrìn ọjọ́ kan lọ sínú aginjù, ó dúró, ó jókòó sábẹ́ igi wíwẹ́, ó sì béèrè pé kí òun* kú. Ó sọ pé: “Ó tó gẹ́ẹ́! Jèhófà, gba ẹ̀mí* mi,+ nítorí mi ò sàn ju àwọn baba ńlá mi.”

5 Lẹ́yìn náà, ó dùbúlẹ̀, ó sì sùn lọ lábẹ́ igi náà. Àmọ́ lójijì, áńgẹ́lì kan fọwọ́ kàn án,+ ó sì sọ fún un pé: “Dìde, jẹun.”+ 6 Nígbà tó máa lajú, ó rí búrẹ́dì ribiti kan lórí àwọn òkúta gbígbóná níbi orí rẹ̀ àti ìgò omi. Ó jẹ, ó sì mu, lẹ́yìn náà, ó sùn pa dà. 7 Nígbà tó yá, áńgẹ́lì Jèhófà pa dà wá lẹ́ẹ̀kejì, ó fọwọ́ kàn án, ó sì sọ pé: “Dìde, jẹun, nítorí ibi tí ò ń lọ jìnnà gan-an, agbára rẹ ò ní lè gbé e.” 8 Nítorí náà, ó dìde, ó jẹ, ó mu, oúnjẹ náà sì fún un lágbára láti rin ìrìn ogójì (40) ọ̀sán àti ogójì (40) òru títí ó fi dé Hórébù, òkè Ọlọ́run tòótọ́.+

9 Ó wọnú ihò+ kan níbẹ̀, ó sì sùn mọ́jú; sì wò ó! Jèhófà bá a sọ̀rọ̀, ó sọ fún un pé: “Kí lò ń ṣe níbí, Èlíjà?” 10 Ó fèsì pé: “Ìtara Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun+ gbà mí lọ́kàn ni; nítorí àwọn èèyàn Ísírẹ́lì ti pa májẹ̀mú rẹ tì,+ wọ́n ti ya àwọn pẹpẹ rẹ lulẹ̀, wọ́n ti fi idà pa àwọn wòlíì rẹ,+ èmi nìkan ló sì ṣẹ́ kù. Ní báyìí, bí wọ́n ṣe máa gba ẹ̀mí* mi ni wọ́n ń wá.”+ 11 Àmọ́, ó sọ pé: “Jáde, kí o sì dúró sórí òkè níwájú Jèhófà.” Sì wò ó! Jèhófà ń kọjá lọ,+ ẹ̀fúùfù ńlá tó lágbára ń ya àwọn òkè, ó sì ń fọ́ àwọn àpáta níwájú Jèhófà,+ àmọ́ Jèhófà kò sí nínú ẹ̀fúùfù náà. Lẹ́yìn ẹ̀fúùfù náà, ìmìtìtì ilẹ̀+ wáyé, àmọ́ Jèhófà kò sí nínú ìmìtìtì ilẹ̀ náà. 12 Lẹ́yìn ìmìtìtì ilẹ̀ náà, iná sọ,+ àmọ́ Jèhófà kò sí nínú iná náà. Lẹ́yìn iná náà, ohùn jẹ́ẹ́jẹ́ẹ́ kan sọ̀rọ̀.+ 13 Bí Èlíjà ṣe gbọ́ báyìí, ó fi ẹ̀wù oyè rẹ̀ wé ojú,+ ó jáde, ó sì dúró sí ẹnu ọ̀nà ihò náà. Ohùn kan wá béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé: “Kí lò ń ṣe níbí, Èlíjà?” 14 Ó fèsì pé: “Ìtara Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun gbà mí lọ́kàn ni; nítorí àwọn èèyàn Ísírẹ́lì ti pa májẹ̀mú rẹ tì,+ wọ́n ti ya àwọn pẹpẹ rẹ lulẹ̀, wọ́n ti fi idà pa àwọn wòlíì rẹ, èmi nìkan ló sì ṣẹ́ kù. Ní báyìí, bí wọ́n ṣe máa gba ẹ̀mí* mi ni wọ́n ń wá.”+

15 Jèhófà sọ fún un pé: “Pa dà, lọ sí aginjù Damásíkù. Tí o bá débẹ̀, fi òróró yan Hásáẹ́lì+ ṣe ọba lórí Síríà. 16 Kí o fòróró yan Jéhù+ ọmọ ọmọ Nímúṣì ṣe ọba lórí Ísírẹ́lì, kí o sì yan Èlíṣà* ọmọ Ṣáfátì láti Ebẹli-méhólà ṣe wòlíì ní ipò rẹ.+ 17 Ẹni tó bá bọ́ lọ́wọ́ idà Hásáẹ́lì,+ Jéhù yóò pa á;+ ẹni tó bá sì bọ́ lọ́wọ́ idà Jéhù, Èlíṣà yóò pa á.+ 18 Mo ṣì ní ẹgbẹ̀rún méje (7,000) èèyàn ní Ísírẹ́lì,+ tí gbogbo wọn ò kúnlẹ̀ fún Báálì,+ tí wọn ò sì fẹnu kò ó lẹ́nu.”+

19 Torí náà, ó kúrò níbẹ̀, ó sì rí Èlíṣà ọmọ Ṣáfátì níbi tó ti ń fi àwọn akọ màlúù tí wọ́n dì ní méjì-méjì sọ́nà méjìlá (12) túlẹ̀ níwájú rẹ̀, ó sì wà pẹ̀lú ìkejìlá. Nítorí náà, Èlíjà lọ sọ́dọ̀ rẹ̀, ó sì ju ẹ̀wù oyè rẹ̀+ sí i lọ́rùn. 20 Ni ó bá fi àwọn akọ màlúù náà sílẹ̀, ó sì sáré tẹ̀ lé Èlíjà, ó sọ fún un pé: “Jọ̀wọ́, jẹ́ kí n lọ fẹnu ko bàbá àti ìyá mi lẹ́nu. Lẹ́yìn náà, màá tẹ̀ lé ọ.” Ó dá a lóhùn pé: “Pa dà lọ, kí nìdí tí màá fi dá ọ dúró?” 21 Nítorí náà, ó pa dà lọ, ó mú akọ màlúù méjì, ó pa wọ́n,* ó sì fi ọ̀pá ohun èlò ìtúlẹ̀ náà se ẹran wọn, ó fún àwọn èèyàn náà, wọ́n sì jẹ ẹ́. Lẹ́yìn náà, ó gbéra, ó tẹ̀ lé Èlíjà, ó sì ń ṣe ìránṣẹ́ fún un.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́