ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Àwọn Ọba 11
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Àwọn Ọba

      • Àwọn ìyàwó Sólómọ́nì yí i lọ́kàn pa dà (1-13)

      • Àwọn alátakò dìde sí Sólómọ́nì (14-25)

      • Ọlọ́run ṣèlérí ẹ̀yà mẹ́wàá fún Jèróbóámù (26-40)

      • Sólómọ́nì kú; wọ́n fi Rèhóbóámù jọba (41-43)

1 Àwọn Ọba 11:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 17:15, 17; Ne 13:26
  • +1Ọb 3:1
  • +Jẹ 19:36, 37
  • +1Ọb 14:21
  • +1Ọb 16:30, 31
  • +Jẹ 26:34, 35

1 Àwọn Ọba 11:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ẹ ò gbọ́dọ̀ fẹ́ wọn, wọn ò sì gbọ́dọ̀ fẹ́ yín.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 34:16; Di 7:3; Joṣ 23:12, 13; 2Kọ 6:14

1 Àwọn Ọba 11:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìyàwó onípò kejì.” Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀, “Wáhàrì.”

  • *

    Tàbí “àwọn ìyàwó rẹ̀ mú kí ọkàn rẹ̀ ṣí kúrò lọ́dọ̀ Ọlọ́run.”

1 Àwọn Ọba 11:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 11:42
  • +Di 7:3, 4; Ne 13:26

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2005, ojú ìwé 29

1 Àwọn Ọba 11:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ond 2:11, 13; 10:6; 1Sa 7:3
  • +Sef 1:5

1 Àwọn Ọba 11:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ní kíkún.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 15:5

1 Àwọn Ọba 11:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 26:30; Nọ 33:52; 2Ọb 21:1, 3
  • +Le 18:21; Iṣe 7:43
  • +2Ọb 23:13

1 Àwọn Ọba 11:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 7:3, 4; Owe 4:23
  • +1Ọb 3:5; 9:2

1 Àwọn Ọba 11:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 7:19, 20

1 Àwọn Ọba 11:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 17:21

1 Àwọn Ọba 11:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 10:18, 19

1 Àwọn Ọba 11:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Sa 7:12, 15
  • +1Ọb 12:20; 2Kr 11:1
  • +Di 12:11

1 Àwọn Ọba 11:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Sa 7:12, 14
  • +Jẹ 27:40

1 Àwọn Ọba 11:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Sa 8:13

1 Àwọn Ọba 11:16

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ké gbogbo ọkùnrin tó wà ní Édómù kúrò.”

1 Àwọn Ọba 11:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 10:12

1 Àwọn Ọba 11:20

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “gba ọmú lẹ́nu rẹ̀.”

1 Àwọn Ọba 11:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 2:10
  • +1Ọb 2:34

1 Àwọn Ọba 11:23

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 11:14
  • +2Sa 8:3

1 Àwọn Ọba 11:24

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “akónilẹ́rù.”

  • *

    Ní Héb., “pa.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Sa 10:18
  • +2Sa 8:5; 1Ọb 19:15; Ais 7:8

1 Àwọn Ọba 11:26

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “gbé ọwọ́ rẹ̀ sókè.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 11:31; 12:32; 14:10; 2Kr 11:14; 13:3, 20
  • +1Ọb 9:22
  • +2Kr 13:6

1 Àwọn Ọba 11:27

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Mílò.” Ọ̀rọ̀ Hébérù tó túmọ̀ sí “iyẹ̀pẹ̀ tí a kó jọ gègèrè.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 9:15, 24
  • +2Sa 5:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, ojú ìwé 1709

1 Àwọn Ọba 11:28

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 5:16

1 Àwọn Ọba 11:29

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 12:15; 14:2; 2Kr 9:29

1 Àwọn Ọba 11:31

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 12:16

1 Àwọn Ọba 11:32

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 12:20; 2Kr 11:1
  • +Jẹ 49:10
  • +Di 12:5, 6; 1Ọb 11:13; Sm 132:13

1 Àwọn Ọba 11:33

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 28:15; 2Kr 15:2

1 Àwọn Ọba 11:34

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 9:4, 5; Sm 89:49; 132:17; Ais 9:7

1 Àwọn Ọba 11:35

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 12:20; 2Kr 10:16

1 Àwọn Ọba 11:36

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ní fìtílà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Sa 7:29; 1Ọb 15:4; 2Ọb 8:19

1 Àwọn Ọba 11:37

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọkàn rẹ.”

1 Àwọn Ọba 11:38

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 15:5
  • +2Sa 7:11

1 Àwọn Ọba 11:39

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 12:16
  • +Jẹ 49:10; Ais 11:1; Lk 1:32, 33

1 Àwọn Ọba 11:40

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 14:25
  • +2Kr 10:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2005, ojú ìwé 30

1 Àwọn Ọba 11:41

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 9:29-31

1 Àwọn Ọba 11:42

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “Àwọn ọjọ́.”

1 Àwọn Ọba 11:43

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kr 3:10; 2Kr 13:7; Mt 1:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2005, ojú ìwé 31

Àwọn míì

1 Ọba 11:1Di 17:15, 17; Ne 13:26
1 Ọba 11:11Ọb 3:1
1 Ọba 11:1Jẹ 19:36, 37
1 Ọba 11:11Ọb 14:21
1 Ọba 11:11Ọb 16:30, 31
1 Ọba 11:1Jẹ 26:34, 35
1 Ọba 11:2Ẹk 34:16; Di 7:3; Joṣ 23:12, 13; 2Kọ 6:14
1 Ọba 11:41Ọb 11:42
1 Ọba 11:4Di 7:3, 4; Ne 13:26
1 Ọba 11:5Ond 2:11, 13; 10:6; 1Sa 7:3
1 Ọba 11:5Sef 1:5
1 Ọba 11:61Ọb 15:5
1 Ọba 11:7Le 26:30; Nọ 33:52; 2Ọb 21:1, 3
1 Ọba 11:7Le 18:21; Iṣe 7:43
1 Ọba 11:72Ọb 23:13
1 Ọba 11:9Di 7:3, 4; Owe 4:23
1 Ọba 11:91Ọb 3:5; 9:2
1 Ọba 11:102Kr 7:19, 20
1 Ọba 11:112Ọb 17:21
1 Ọba 11:122Kr 10:18, 19
1 Ọba 11:132Sa 7:12, 15
1 Ọba 11:131Ọb 12:20; 2Kr 11:1
1 Ọba 11:13Di 12:11
1 Ọba 11:142Sa 7:12, 14
1 Ọba 11:14Jẹ 27:40
1 Ọba 11:152Sa 8:13
1 Ọba 11:18Nọ 10:12
1 Ọba 11:211Ọb 2:10
1 Ọba 11:211Ọb 2:34
1 Ọba 11:231Ọb 11:14
1 Ọba 11:232Sa 8:3
1 Ọba 11:242Sa 10:18
1 Ọba 11:242Sa 8:5; 1Ọb 19:15; Ais 7:8
1 Ọba 11:261Ọb 11:31; 12:32; 14:10; 2Kr 11:14; 13:3, 20
1 Ọba 11:261Ọb 9:22
1 Ọba 11:262Kr 13:6
1 Ọba 11:271Ọb 9:15, 24
1 Ọba 11:272Sa 5:7
1 Ọba 11:281Ọb 5:16
1 Ọba 11:291Ọb 12:15; 14:2; 2Kr 9:29
1 Ọba 11:311Ọb 12:16
1 Ọba 11:321Ọb 12:20; 2Kr 11:1
1 Ọba 11:32Jẹ 49:10
1 Ọba 11:32Di 12:5, 6; 1Ọb 11:13; Sm 132:13
1 Ọba 11:33Di 28:15; 2Kr 15:2
1 Ọba 11:341Ọb 9:4, 5; Sm 89:49; 132:17; Ais 9:7
1 Ọba 11:351Ọb 12:20; 2Kr 10:16
1 Ọba 11:362Sa 7:29; 1Ọb 15:4; 2Ọb 8:19
1 Ọba 11:381Ọb 15:5
1 Ọba 11:382Sa 7:11
1 Ọba 11:391Ọb 12:16
1 Ọba 11:39Jẹ 49:10; Ais 11:1; Lk 1:32, 33
1 Ọba 11:401Ọb 14:25
1 Ọba 11:402Kr 10:2
1 Ọba 11:412Kr 9:29-31
1 Ọba 11:431Kr 3:10; 2Kr 13:7; Mt 1:7
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
  • 28
  • 29
  • 30
  • 31
  • 32
  • 33
  • 34
  • 35
  • 36
  • 37
  • 38
  • 39
  • 40
  • 41
  • 42
  • 43
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
1 Àwọn Ọba 11:1-43

Àwọn Ọba Kìíní

11 Àmọ́ Ọba Sólómọ́nì nífẹ̀ẹ́ ọ̀pọ̀ obìnrin ilẹ̀ àjèjì,+ yàtọ̀ sí ọmọbìnrin Fáráò,+ àwọn tó tún nífẹ̀ẹ́ ni: àwọn obìnrin tó jẹ́ ọmọ Móábù,+ ọmọ Ámónì,+ ọmọ Édómù, ọmọ Sídónì+ àti ọmọ Hétì.+ 2 Wọ́n wá láti àwọn orílẹ̀-èdè tí Jèhófà sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé: “Ẹ ò gbọ́dọ̀ lọ sí àárín wọn,* wọn ò sì gbọ́dọ̀ wá sí àárín yín, torí ó dájú pé wọ́n á mú kí ọkàn yín fà sí títẹ̀lé àwọn ọlọ́run wọn.”+ Àmọ́ ọkàn Sólómọ́nì kò kúrò lọ́dọ̀ wọn, ó sì nífẹ̀ẹ́ wọn. 3 Ó ní ọgọ́rùn-ún méje (700) ìyàwó tí wọ́n jẹ́ ọmọ ọba àti ọgọ́rùn-ún mẹ́ta (300) wáhàrì,* ní kẹ̀rẹ̀kẹ̀rẹ̀, àwọn ìyàwó rẹ̀ yí i lọ́kàn pa dà.* 4 Nígbà tí Sólómọ́nì darúgbó,+ àwọn ìyàwó rẹ̀ mú kí ọkàn rẹ̀ fà sí títẹ̀lé àwọn ọlọ́run míì,+ kò sì fi gbogbo ọkàn rẹ̀ sin Jèhófà Ọlọ́run rẹ̀ bíi Dáfídì bàbá rẹ̀. 5 Sólómọ́nì yíjú sí Áṣítórétì,+ abo ọlọ́run àwọn ọmọ Sídónì àti Mílíkómù,+ ọlọ́run ìríra àwọn ọmọ Ámónì. 6 Sólómọ́nì ṣe ohun tí ó burú lójú Jèhófà, kò sì tẹ̀ lé Jèhófà délẹ̀délẹ̀* bí Dáfídì bàbá rẹ̀ ti ṣe.+

7 Ìgbà náà ni Sólómọ́nì kọ́ ibi gíga+ kan fún Kémóṣì, ọlọ́run ìríra Móábù, lórí òkè tó wà níwájú Jerúsálẹ́mù, ó sì tún kọ́ òmíràn fún Mólékì,+ ọlọ́run ìríra àwọn ọmọ Ámónì.+ 8 Ohun tí ó ṣe fún gbogbo ìyàwó ilẹ̀ àjèjì tó fẹ́ nìyẹn, àwọn tó ń mú ẹbọ rú èéfín, tí wọ́n sì ń rúbọ sí àwọn ọlọ́run wọn.

9 Inú bí Jèhófà gan-an sí Sólómọ́nì, nítorí ọkàn rẹ̀ ti kúrò lọ́dọ̀ Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì,+ ẹni tó fara hàn án lẹ́ẹ̀mejì,+ 10 tí ó sì kìlọ̀ fún un nípa nǹkan yìí pé kí ó má ṣe tẹ̀ lé àwọn ọlọ́run míì.+ Àmọ́ kò ṣe ohun tí Jèhófà pa láṣẹ. 11 Jèhófà wá sọ fún Sólómọ́nì pé: “Nítorí ohun tí o ṣe yìí, tí o kò pa májẹ̀mú mi àti òfin mi mọ́, bí mo ṣe pa á láṣẹ fún ọ, màá rí i dájú pé mo fa ìjọba náà ya kúrò lọ́wọ́ rẹ, màá sì fún ọ̀kan lára àwọn ìránṣẹ́ rẹ.+ 12 Àmọ́, nítorí Dáfídì bàbá rẹ, mi ò ní ṣe èyí nígbà ayé rẹ. Ọwọ́ ọmọ rẹ ni màá ti fà á ya,+ 13 àmọ́ kì í ṣe gbogbo ìjọba náà+ ni màá fà ya. Màá fún ọmọ rẹ ní ẹ̀yà kan,+ nítorí Dáfídì ìránṣẹ́ mi àti nítorí Jerúsálẹ́mù tí mo yàn.”+

14 Lẹ́yìn náà, Jèhófà gbé alátakò kan dìde sí Sólómọ́nì,+ ìyẹn Hádádì ọmọ Édómù, láti ìdílé ọba Édómù.+ 15 Nígbà tí Dáfídì ṣẹ́gun Édómù,+ Jóábù olórí ọmọ ogun lọ sin àwọn tó kú, ó sì wá ọ̀nà láti pa gbogbo ọkùnrin tó wà ní Édómù. 16 (Nítorí oṣù mẹ́fà ni Jóábù àti gbogbo Ísírẹ́lì fi gbé ibẹ̀ títí ó fi pa gbogbo ọkùnrin tó wà ní Édómù run.*) 17 Àmọ́ Hádádì fẹsẹ̀ fẹ pẹ̀lú àwọn kan lára ìránṣẹ́ bàbá rẹ̀ tí wọ́n jẹ́ ọmọ Édómù, wọ́n sì lọ sí Íjíbítì; ọmọdé ni Hádádì nígbà yẹn. 18 Nítorí náà, wọ́n kúrò ní Mídíánì, wọ́n sì wá sí Páránì. Wọ́n kó àwọn ọkùnrin kan láti Páránì,+ wọ́n sì wá sí Íjíbítì, lọ́dọ̀ Fáráò ọba Íjíbítì, ẹni tó fún un ní ilé, tó ṣètò bí á ṣe máa rí oúnjẹ gbà, tó sì fún un ní ilẹ̀. 19 Hádádì rí ojú rere Fáráò débi pé ó fún un ní àbúrò ayaba Tápénésì, ìyàwó rẹ̀, pé kó fi ṣe aya. 20 Nígbà tó yá, àbúrò Tápénésì bí ọmọkùnrin kan fún un, Génúbátì lorúkọ rẹ̀, Tápénésì tọ́ ọ dàgbà* ní ilé Fáráò, Génúbátì sì ń gbé ní ilé Fáráò láàárín àwọn ọmọ Fáráò.

21 Hádádì gbọ́ ní Íjíbítì pé Dáfídì ti sinmi pẹ̀lú àwọn baba ńlá rẹ̀+ àti pé Jóábù olórí ọmọ ogun ti kú.+ Torí náà, Hádádì sọ fún Fáráò pé: “Jẹ́ kí n lọ, kí n lè lọ sí ilẹ̀ mi.” 22 Àmọ́ Fáráò sọ fún un pé: “Kí lo fẹ́ tí o kò ní lọ́dọ̀ mi tí o fi fẹ́ lọ sí ilẹ̀ rẹ?” Ó fèsì pé: “Kò sí, àmọ́ jọ̀wọ́ jẹ́ kí n lọ.”

23 Ọlọ́run tún gbé alátakò míì dìde+ sí Sólómọ́nì, ìyẹn Résónì ọmọ Élíádà, ẹni tó sá kúrò lọ́dọ̀ olúwa rẹ̀, Hadadésà+ ọba Sóbà. 24 Ó kó àwọn ọkùnrin jọ sọ́dọ̀ ara rẹ̀, ó sì di olórí àwọn jàǹdùkú* nígbà tí Dáfídì ṣẹ́gun*+ àwọn ọkùnrin Sóbà. Nítorí náà, wọ́n lọ sí Damásíkù,+ wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í gbé ibẹ̀, wọ́n sì ń ṣàkóso ní Damásíkù. 25 Ó di alátakò Ísírẹ́lì ní ìgbà ayé Sólómọ́nì, ó dá kún jàǹbá tí Hádádì ṣe, ó sì kórìíra Ísírẹ́lì gan-an nígbà tó ń jọba lórí Síríà.

26 Ẹnì kan wà tó ń jẹ́ Jèróbóámù+ ọmọ Nébátì nínú ẹ̀yà Éfúrémù, ó wá láti Sérédà, ìránṣẹ́ Sólómọ́nì+ ni. Sérúà lorúkọ ìyá rẹ̀, opó sì ni. Òun náà bẹ̀rẹ̀ sí í ṣọ̀tẹ̀* sí ọba.+ 27 Ohun tó jẹ́ kó ṣọ̀tẹ̀ sí ọba ni pé: Sólómọ́nì mọ Òkìtì,*+ ó sì dí àlàfo Ìlú Dáfídì bàbá rẹ̀.+ 28 Ọkùnrin tó dáńgájíá ni Jèróbóámù. Nígbà tí Sólómọ́nì rí i pé ọ̀dọ́kùnrin náà jẹ́ òṣìṣẹ́ kára, ó fi í ṣe alábòójútó+ gbogbo àwọn tó ń ṣe iṣẹ́ ọ̀ranyàn ní ilé Jósẹ́fù. 29 Ní àkókò yẹn, Jèróbóámù jáde kúrò ní Jerúsálẹ́mù, wòlíì Áhíjà+ ọmọ Ṣílò sì rí i lọ́nà. Ẹ̀wù tuntun ló wà lọ́rùn Áhíjà, àwọn méjèèjì nìkan ló sì wà ní pápá. 30 Áhíjà di ẹ̀wù tuntun tó wà lọ́rùn rẹ̀ mú, ó sì fà á ya sí ọ̀nà méjìlá (12). 31 Lẹ́yìn náà, ó sọ fún Jèróbóámù pé:

“Gba mẹ́wàá yìí, torí ohun tí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ nìyí: ‘Wò ó, màá fa ìjọba náà ya kúrò ní ọwọ́ Sólómọ́nì, màá sì fún ọ ní ẹ̀yà mẹ́wàá.+ 32 Àmọ́ ẹ̀yà kan ṣì máa jẹ́ tirẹ̀+ nítorí ìránṣẹ́ mi Dáfídì+ àti nítorí Jerúsálẹ́mù, ìlú tí mo yàn nínú gbogbo ẹ̀yà Ísírẹ́lì.+ 33 Ohun tí màá ṣe nìyí torí pé wọ́n ti fi mí sílẹ̀,+ wọ́n sì ń forí balẹ̀ fún Áṣítórétì, abo ọlọ́run àwọn ọmọ Sídónì, fún Kémóṣì, ọlọ́run Móábù àti fún Mílíkómù, ọlọ́run àwọn ọmọ Ámónì, wọn ò rìn ní àwọn ọ̀nà mi láti máa ṣe ohun tí ó tọ́ lójú mi àti láti máa pa àwọn àṣẹ mi àti àwọn ìdájọ́ mi mọ́ bí Dáfídì bàbá Sólómọ́nì ti ṣe. 34 Àmọ́ mi ò ní gba gbogbo ìjọba náà kúrò lọ́wọ́ rẹ̀, màá ṣì fi ṣe olórí ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀, nítorí Dáfídì ìránṣẹ́ mi tí mo yàn,+ torí ó pa àwọn àṣẹ àti òfin mi mọ́. 35 Ṣùgbọ́n màá gba ìjọba náà kúrò lọ́wọ́ ọmọ rẹ̀, màá sì fi í fún ọ, ìyẹn ẹ̀yà mẹ́wàá.+ 36 Màá fún ọmọ rẹ̀ ní ẹ̀yà kan ṣoṣo, kí Dáfídì ìránṣẹ́ mi lè máa ṣàkóso* níwájú mi nígbà gbogbo ní Jerúsálẹ́mù,+ ìlú tí mo yàn fún ara mi láti fi orúkọ mi sí. 37 Màá yàn ọ́, wàá ṣàkóso lórí gbogbo ohun tí o* fẹ́, wàá sì di ọba lórí Ísírẹ́lì. 38 Tí o bá ṣe gbogbo ohun tí mo pa láṣẹ fún ọ, tí o rìn ní àwọn ọ̀nà mi, tí o sì ṣe ohun tí ó tọ́ lójú mi láti máa pa àwọn òfin àti àṣẹ mi mọ́, bí Dáfídì ìránṣẹ́ mi ti ṣe,+ èmi náà á wà pẹ̀lú rẹ. Màá kọ́ ilé tó máa wà títí lọ fún ọ, bí mo ṣe kọ́ ọ fún Dáfídì,+ màá sì fún ọ ní Ísírẹ́lì. 39 Màá dójú ti àtọmọdọ́mọ Dáfídì nítorí èyí,+ àmọ́ kò ní jẹ́ títí lọ.’”+

40 Torí náà, Sólómọ́nì wá ọ̀nà láti pa Jèróbóámù, àmọ́ Jèróbóámù sá lọ sí Íjíbítì, lọ́dọ̀ Ṣíṣákì+ ọba Íjíbítì,+ ó sì ń gbé ní Íjíbítì títí Sólómọ́nì fi kú.

41 Ní ti ìyókù ìtàn Sólómọ́nì, gbogbo ohun tí ó ṣe àti ọgbọ́n rẹ̀, ǹjẹ́ kò wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé ìtàn Sólómọ́nì?+ 42 Gbogbo ọdún* tí Sólómọ́nì fi jọba lórí gbogbo Ísírẹ́lì ní Jerúsálẹ́mù jẹ́ ogójì (40) ọdún. 43 Níkẹyìn, Sólómọ́nì sinmi pẹ̀lú àwọn baba ńlá rẹ̀, wọ́n sì sin ín sí Ìlú Dáfídì bàbá rẹ̀; Rèhóbóámù+ ọmọ rẹ̀ sì jọba ní ipò rẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́