ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 127
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Sáàmù

      • Láìsí Ọlọ́run, asán ni gbogbo nǹkan

        • “Bí Jèhófà ò bá kọ́ ilé” (1)

        • Àwọn ọmọ jẹ́ èrè láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run (3)

Sáàmù 127:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 3:6; 10:22; 16:3
  • +Ais 27:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    12/1/1993, ojú ìwé 32

Sáàmù 127:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 3:5; Onw 5:12

Sáàmù 127:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ọmọkùnrin.”

  • *

    Tàbí “ilé ọlẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 33:4, 5; 48:3, 4; 1Sa 2:21
  • +Jẹ 41:51, 52; Le 26:9; Job 42:12, 13; Sm 128:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2019, ojú ìwé 22

    Ilé Ìṣọ́,

    4/1/2005, ojú ìwé 8-19

    10/1/1996, ojú ìwé 31

    Jí!,

    8/8/1997, ojú ìwé 10

    Ayọ̀ Ìdílé, ojú ìwé 126

Sáàmù 127:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 17:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2019, ojú ìwé 27

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2013, ojú ìwé 17

    4/1/2008, ojú ìwé 13-16

    9/1/2007, ojú ìwé 26, 30

Sáàmù 127:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 50:23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/1/2008, ojú ìwé 13-16

Àwọn míì

Sm 127:1Owe 3:6; 10:22; 16:3
Sm 127:1Ais 27:3
Sm 127:2Sm 3:5; Onw 5:12
Sm 127:3Jẹ 33:4, 5; 48:3, 4; 1Sa 2:21
Sm 127:3Jẹ 41:51, 52; Le 26:9; Job 42:12, 13; Sm 128:3
Sm 127:4Owe 17:6
Sm 127:5Jẹ 50:23
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Sáàmù 127:1-5

Sáàmù

Orin Ìgòkè. Ti Sólómọ́nì.

127 Bí Jèhófà ò bá kọ́ ilé,

Lásán ni àwọn tó ń kọ́ ọ ṣiṣẹ́ kára lórí rẹ̀.+

Bí Jèhófà ò bá ṣọ́ ìlú,+

Lásán ni ẹ̀ṣọ́ wà lójúfò.

2 Lásán lẹ̀ ń dìde ní kùtùkùtù,

Tí ẹ̀ ń pẹ́ kí ẹ tó sùn,

Tí ẹ sì ń fi gbogbo agbára ṣiṣẹ́ kí ẹ lè rí oúnjẹ,

Torí Ọlọ́run ń pèsè fún àwọn tó fẹ́ràn, ó sì ń jẹ́ kí wọ́n rí oorun sùn.+

3 Wò ó! Àwọn ọmọ* jẹ́ ogún láti ọ̀dọ̀ Jèhófà;+

Èso ikùn* jẹ́ èrè.+

4 Bí ọfà ní ọwọ́ alágbára ọkùnrin,

Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọ téèyàn bí nígbà ọ̀dọ́.+

5 Aláyọ̀ ni ọkùnrin tó fi wọ́n kún apó rẹ̀.+

Ojú kò ní tì wọ́n,

Nítorí wọ́n á bá àwọn ọ̀tá sọ̀rọ̀ ní ẹnubodè ìlú.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́