ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jémíìsì 1
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jémíìsì

      • Ìkíni (1)

      • Ìfaradà ń jẹ́ ká láyọ̀ (2-15)

        • A máa ń dán ìgbàgbọ́ wò ní ti bó ṣe jẹ́ ojúlówó tó (3)

        • Ẹ máa fi ìgbàgbọ́ béèrè (5-8)

        • Ìfẹ́ ọkàn máa ń yọrí sí ẹ̀ṣẹ̀ àti ikú (14, 15)

      • Gbogbo ẹ̀bùn rere wá láti òkè (16-18)

      • Olùgbọ́ àti olùṣe ọ̀rọ̀ náà (19-25)

        • Ẹni tó ń wo ara rẹ̀ nínú dígí (23, 24)

      • Ìjọsìn tó mọ́, tí kò sì ní ẹ̀gbin (26, 27)

Jémíìsì 1:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 13:55

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    6/2018, ojú ìwé 31

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 117-118

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 8

    12/15/1995, ojú ìwé 16-17

    7/1/1995, ojú ìwé 12

    3/15/1991, ojú ìwé 23

Jémíìsì 1:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 5:11, 12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    2/2021, ojú ìwé 26-28

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 59

    A Ṣètò Wa, ojú ìwé 172-173

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2014, ojú ìwé 26

    6/15/2005, ojú ìwé 30-31

    7/15/1999, ojú ìwé 16-17

    5/15/1998, ojú ìwé 16

    11/15/1997, ojú ìwé 8-9

    12/15/1995, ojú ìwé 17-18

    9/15/1993, ojú ìwé 9-10

    11/1/1991, ojú ìwé 15

Jémíìsì 1:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Pe 1:6, 7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    2/2021, ojú ìwé 28

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 59

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2002, ojú ìwé 31

    7/15/1999, ojú ìwé 16-17

    5/15/1998, ojú ìwé 16

    11/15/1997, ojú ìwé 8-9

    11/1/1991, ojú ìwé 15

Jémíìsì 1:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 14:20; Ef 4:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    2/2021, ojú ìwé 28

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 59

    A Ṣètò Wa, ojú ìwé 172

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    4/2016, ojú ìwé 14

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2009, ojú ìwé 10

    8/1/2005, ojú ìwé 25

    7/15/1999, ojú ìwé 16-17

    8/15/1998, ojú ìwé 30

    5/15/1998, ojú ìwé 16

    11/15/1997, ojú ìwé 9

    12/15/1995, ojú ìwé 17-18

    11/1/1991, ojú ìwé 15

Jémíìsì 1:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “dáni lẹ́bi.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 3:9; Mk 11:24; 1Jo 3:22
  • +Owe 2:3-6; Jo 15:7; 1Jo 5:14
  • +Mt 7:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    2/2021, ojú ìwé 29-30

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 9

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2006, ojú ìwé 25

    9/1/2003, ojú ìwé 14

    1/15/2003, ojú ìwé 11

    11/15/1997, ojú ìwé 9

    12/15/1995, ojú ìwé 18-19

    Ọ̀nà Tó Lọ sí Ìyè, ojú ìwé 29

Jémíìsì 1:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 7:7
  • +Mt 21:22; Heb 11:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    2/2021, ojú ìwé 30

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2003, ojú ìwé 11

    7/1/2001, ojú ìwé 19

    11/15/1997, ojú ìwé 9

    12/15/1995, ojú ìwé 18-19

Jémíìsì 1:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2003, ojú ìwé 11

    11/15/1997, ojú ìwé 9

Jémíìsì 1:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jem 4:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2003, ojú ìwé 11

    11/15/1997, ojú ìwé 9

Jémíìsì 1:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “yangàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jem 2:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 9-10

Jémíìsì 1:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ti 6:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 9-10

Jémíìsì 1:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 40:6, 7; Mt 19:24

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 10

Jémíìsì 1:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 5:10; Jem 1:2
  • +2Ti 4:8; 1Pe 5:4; Ifi 2:10
  • +Jem 2:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 10-11

Jémíìsì 1:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    2/2021, ojú ìwé 31

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 13

    Ilé Ìṣọ́,

    7/1/2014, ojú ìwé 4

    6/15/2009, ojú ìwé 13

    11/15/1997, ojú ìwé 11

Jémíìsì 1:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “mú un bí ìdẹ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 3:6; 1Jo 2:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2015, ojú ìwé 24

    10/15/2001, ojú ìwé 26

    11/15/1997, ojú ìwé 11

Jémíìsì 1:15

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “lóyún.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 5:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jí!,

    No. 4 2017 ojú ìwé 14

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2010, ojú ìwé 4

    10/15/2001, ojú ìwé 26

    11/15/1997, ojú ìwé 11

Jémíìsì 1:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 11

Jémíìsì 1:17

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ẹni tí kò sí ìyípadà òjìji lọ́dọ̀ rẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 7:11
  • +Jer 31:35; 2Kọ 4:6
  • +Mal 3:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/15/2008, ojú ìwé 7

    7/15/2005, ojú ìwé 26

    6/1/2001, ojú ìwé 4

    11/15/1997, ojú ìwé 11

    8/1/1994, ojú ìwé 11

    12/1/1993, ojú ìwé 28-29

Jémíìsì 1:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 1:12, 13; Ro 8:28; Ef 1:13, 14; 2Tẹ 2:13; 1Pe 1:23
  • +Ifi 14:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2007, ojú ìwé 22

    11/15/1997, ojú ìwé 11

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 202-203

Jémíìsì 1:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 10:19; 17:27
  • +Onw 7:9; Mt 5:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 50

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    9/2018, ojú ìwé 6

    Ilé Ìṣọ́,

    5/15/2013, ojú ìwé 21-23

    11/15/1997, ojú ìwé 12

    12/15/1995, ojú ìwé 19

    Jí!,

    1/2011, ojú ìwé 30

    8/8/1997, ojú ìwé 8-9

    Ayọ̀ Ìdílé, ojú ìwé 156, 186

Jémíìsì 1:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jem 3:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 50

    Ìjọsìn Mímọ́, ojú ìwé 190

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 12

Jémíìsì 1:21

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ ìwà burúkú.”

  • *

    Tàbí “gba ọkàn yín là.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Kol 3:8; 1Pe 2:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 12

    12/15/1995, ojú ìwé 19-20

Jémíìsì 1:22

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 18:5; 1Sa 15:22; Mt 7:21; 1Jo 3:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 3/2022,

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2014, ojú ìwé 16

    4/15/2005, ojú ìwé 27-28

    7/15/2003, ojú ìwé 22

    6/15/2001, ojú ìwé 13-14

    11/15/1997, ojú ìwé 12

    9/15/1997, ojú ìwé 6

    12/15/1995, ojú ìwé 16-21

    6/1/1994, ojú ìwé 14

    3/15/1991, ojú ìwé 23

Jémíìsì 1:23

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ojú àdánidá rẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Lk 6:46; Jem 2:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2022, ojú ìwé 12

    Ilé Ìṣọ́,

    8/1/2011, ojú ìwé 21

    8/1/2009, ojú ìwé 13

    6/15/2008, ojú ìwé 25

    6/15/2001, ojú ìwé 13-14

    1/1/1996, ojú ìwé 31

    12/15/1995, ojú ìwé 20

    7/15/1995, ojú ìwé 32

Jémíìsì 1:24

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2022, ojú ìwé 12

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2014, ojú ìwé 8

    6/15/2001, ojú ìwé 13-14

Jémíìsì 1:25

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 19:7
  • +Mt 7:24; Lk 11:28; Jo 13:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    4/2018, ojú ìwé 4

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2014, ojú ìwé 8-9, 11

    7/15/2012, ojú ìwé 7-10

    8/1/2009, ojú ìwé 13

    6/15/2008, ojú ìwé 25

    7/15/2005, ojú ìwé 24

    5/1/1999, ojú ìwé 5

    11/15/1997, ojú ìwé 12

    9/1/1996, ojú ìwé 15

    1/1/1996, ojú ìwé 31

    12/15/1995, ojú ìwé 20

    7/15/1995, ojú ìwé 32

    3/15/1991, ojú ìwé 23

    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba,

    7/2014, ojú ìwé 2

Jémíìsì 1:26

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “òun gba Ọlọ́run gbọ́.”

  • *

    Tàbí “kó ahọ́n rẹ̀ níjàánu.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 39:1; Owe 12:18; 15:2; 1Pe 3:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 51

    ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run’, ojú ìwé 125-126, 135, 161

    Ilé Ìṣọ́,

    9/15/2006, ojú ìwé 21

    11/15/1997, ojú ìwé 12-13

    12/1/1991, ojú ìwé 16

    Jí!,

    6/8/2004, ojú ìwé 31

Jémíìsì 1:27

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ẹ̀sìn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 14:29; 27:19; Sm 68:5
  • +Ais 1:17; 1Ti 5:3
  • +Job 29:12, 13; Ais 58:7
  • +1Kọ 5:7; Jem 4:4; Ifi 18:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 55

    Ilé Ìṣọ́,

    6/1/2006, ojú ìwé 5

    5/15/2004, ojú ìwé 19-20

    6/15/2001, ojú ìwé 9-12

    5/1/2001, ojú ìwé 5-6

    12/1/1998, ojú ìwé 14-15

    11/15/1997, ojú ìwé 13

    10/1/1996, ojú ìwé 14-15

    12/1/1991, ojú ìwé 16-18

Àwọn míì

Jém. 1:1Mt 13:55
Jém. 1:2Mt 5:11, 12
Jém. 1:31Pe 1:6, 7
Jém. 1:41Kọ 14:20; Ef 4:13
Jém. 1:51Ọb 3:9; Mk 11:24; 1Jo 3:22
Jém. 1:5Owe 2:3-6; Jo 15:7; 1Jo 5:14
Jém. 1:5Mt 7:11
Jém. 1:6Mt 7:7
Jém. 1:6Mt 21:22; Heb 11:6
Jém. 1:8Jem 4:8
Jém. 1:9Jem 2:5
Jém. 1:101Ti 6:17
Jém. 1:11Ais 40:6, 7; Mt 19:24
Jém. 1:12Mt 5:10; Jem 1:2
Jém. 1:122Ti 4:8; 1Pe 5:4; Ifi 2:10
Jém. 1:12Jem 2:5
Jém. 1:14Jẹ 3:6; 1Jo 2:16
Jém. 1:15Ro 5:21
Jém. 1:17Mt 7:11
Jém. 1:17Jer 31:35; 2Kọ 4:6
Jém. 1:17Mal 3:6
Jém. 1:18Jo 1:12, 13; Ro 8:28; Ef 1:13, 14; 2Tẹ 2:13; 1Pe 1:23
Jém. 1:18Ifi 14:4
Jém. 1:19Owe 10:19; 17:27
Jém. 1:19Onw 7:9; Mt 5:22
Jém. 1:20Jem 3:18
Jém. 1:21Kol 3:8; 1Pe 2:1
Jém. 1:22Le 18:5; 1Sa 15:22; Mt 7:21; 1Jo 3:7
Jém. 1:23Lk 6:46; Jem 2:14
Jém. 1:25Sm 19:7
Jém. 1:25Mt 7:24; Lk 11:28; Jo 13:17
Jém. 1:26Sm 39:1; Owe 12:18; 15:2; 1Pe 3:10
Jém. 1:27Di 14:29; 27:19; Sm 68:5
Jém. 1:27Ais 1:17; 1Ti 5:3
Jém. 1:27Job 29:12, 13; Ais 58:7
Jém. 1:271Kọ 5:7; Jem 4:4; Ifi 18:4
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Jémíìsì 1:1-27

Lẹ́tà Jémíìsì

1 Jémíìsì,+ ẹrú Ọlọ́run àti ti Jésù Kristi Olúwa, sí ẹ̀yà méjìlá (12) tó wà káàkiri:

Mo kí yín!

2 Ẹ̀yin ará mi, tí oríṣiríṣi àdánwò bá dé bá yín, ẹ ka gbogbo rẹ̀ sí ayọ̀,+ 3 kí ẹ mọ̀ pé ìgbàgbọ́ yín tí a dán wò ní ti bó ṣe jẹ́ ojúlówó tó máa mú kí ẹ ní ìfaradà.+ 4 Àmọ́ ẹ jẹ́ kí ìfaradà ṣe iṣẹ́ rẹ̀ láṣeparí, kí ẹ lè pé pérépéré, kí ẹ sì máa ṣe ohun tó tọ́ nínú ohun gbogbo, láìkù síbì kan.+

5 Torí náà, tí ẹnikẹ́ni nínú yín ò bá ní ọgbọ́n, kó máa béèrè lọ́wọ́ Ọlọ́run,+ ó sì máa fún un,+ torí ó lawọ́ sí gbogbo èèyàn, kì í sì í pẹ̀gàn*+ tó bá ń fúnni. 6 Àmọ́ kó máa fi ìgbàgbọ́ béèrè,+ kó má ṣiyèméjì rárá,+ torí ẹni tó ń ṣiyèméjì dà bí ìgbì òkun tí atẹ́gùn ń fẹ́ káàkiri. 7 Kódà, kí ẹni náà má rò pé òun máa rí ohunkóhun gbà lọ́dọ̀ Jèhófà;* 8 aláìnípinnu ni onítọ̀hún,+ kò sì dúró sójú kan ní gbogbo ọ̀nà rẹ̀.

9 Àmọ́ kí arákùnrin tó rẹlẹ̀ máa yọ̀* torí a gbé e ga,+ 10 àti ọlọ́rọ̀ torí a ti rẹ̀ ẹ́ sílẹ̀,+ torí ó máa kọjá lọ bí òdòdó inú pápá. 11 Bí oòrùn ṣe máa ń mú ooru tó ń jóni jáde tó bá yọ, tó sì máa mú kí ewéko rọ, tí òdòdó rẹ̀ á já bọ́, tí ẹwà rẹ̀ tó tàn sì máa ṣègbé, bẹ́ẹ̀ náà ni ọlọ́rọ̀ máa pa rẹ́ bó ṣe ń lépa ọrọ̀.+

12 Aláyọ̀ ni ẹni tó ń fara da àdánwò,+ torí tó bá rí ìtẹ́wọ́gbà, ó máa gba adé ìyè,+ tí Jèhófà* ṣèlérí pé òun máa fún àwọn tí ò yéé nífẹ̀ẹ́ Rẹ̀.+ 13 Tí àdánwò bá dé bá ẹnikẹ́ni, kó má ṣe sọ pé: “Ọlọ́run ló ń dán mi wò.” Torí a ò lè fi ibi dán Ọlọ́run wò, òun náà kì í sì í dán ẹnikẹ́ni wò. 14 Àmọ́ àdánwò máa ń dé bá kálukú nígbà tí ìfẹ́ ọkàn rẹ̀ bá fà á mọ́ra, tó sì tàn án jẹ.*+ 15 Tí ìfẹ́ ọkàn náà bá ti gbilẹ̀,* ó máa bí ẹ̀ṣẹ̀; tí ẹ̀ṣẹ̀ náà bá sì ti wáyé, ó máa yọrí sí ikú.+

16 Ẹ̀yin ará mi ọ̀wọ́n, ẹ má ṣe jẹ́ kí ẹnikẹ́ni ṣì yín lọ́nà. 17 Gbogbo ẹ̀bùn rere àti gbogbo ọrẹ pípé wá láti òkè,+ ó ń wá látọ̀dọ̀ Baba àwọn ìmọ́lẹ̀ àtọ̀runwá,+ ẹni tí kì í yí pa dà, tí kì í sì í sún kiri bí òjìji.*+ 18 Ìfẹ́ rẹ̀ ni pé kó fi ọ̀rọ̀ òtítọ́ mú wa wá,+ ká lè di oríṣi àkọ́so kan nínú àwọn ohun tó dá.+

19 Ẹ̀yin ará mi ọ̀wọ́n, ẹ mọ èyí: Ó yẹ kí gbogbo èèyàn yára láti gbọ́rọ̀, kí wọ́n lọ́ra láti sọ̀rọ̀,+ kí wọ́n má sì tètè máa bínú,+ 20 torí ìbínú èèyàn kì í mú òdodo Ọlọ́run wá.+ 21 Torí náà, ẹ mú gbogbo èérí àti gbogbo ohun tó jẹ mọ́ ìwà burúkú* kúrò,+ kí ìwà tútù yín sì mú kí ọ̀rọ̀ tó lè gbà yín là* fìdí múlẹ̀ nínú yín.

22 Àmọ́, ẹ máa ṣe ohun tí ọ̀rọ̀ náà sọ,+ ẹ má kàn máa gbọ́ ọ lásán, kí ẹ wá máa fi èrò èké tan ara yín jẹ. 23 Torí tí ẹnikẹ́ni bá ń gbọ́ ọ̀rọ̀ náà, àmọ́ tí kò ṣe é,+ ẹni yìí dà bí èèyàn tó ń wo ojú ara rẹ̀* nínú dígí. 24 Torí ó wo ara rẹ̀, ó lọ, ó sì gbàgbé irú ẹni tí òun jẹ́ lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀. 25 Àmọ́ ẹni tó bá ń fara balẹ̀ wo inú òfin pípé+ tó jẹ́ ti òmìnira, tí kò sì yéé wò ó, kì í ṣe olùgbọ́ tó ń gbàgbé, àmọ́ ó ti di olùṣe iṣẹ́ náà; ohun tó ń ṣe á sì máa múnú rẹ̀ dùn.+

26 Tí ẹnikẹ́ni bá rò pé òun ń jọ́sìn Ọlọ́run,* àmọ́ tí kò ṣọ́ ahọ́n rẹ̀ gidigidi,*+ ṣe ló ń tan ọkàn ara rẹ̀ jẹ, asán sì ni ìjọsìn rẹ̀. 27 Ìjọsìn* tó mọ́, tí kò sì ní ẹ̀gbin lójú Ọlọ́run àti Baba wa nìyí: láti máa bójú tó àwọn ọmọ aláìlóbìí+ àti àwọn opó+ nínú ìpọ́njú wọn,+ ká sì máa pa ara wa mọ́ láìní àbààwọ́n nínú ayé.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́