ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Pétérù 3
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 2 Pétérù

      • Àwọn tó ń fini ṣẹlẹ́yà kò ka ìparun tó ń bọ̀ sí (1-7)

      • Jèhófà kì í fi nǹkan falẹ̀ (8-10)

      • Ẹ ronú nípa irú ẹni tó yẹ kí ẹ jẹ́ (11-16)

        • Ọ̀run tuntun àti ayé tuntun (13)

      • Ẹ ṣọ́ra kí wọ́n má bàa ṣì yín lọ́nà (17, 18)

2 Pétérù 3:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 15:15; 2Pe 1:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2003, ojú ìwé 9

    6/1/1998, ojú ìwé 5

    9/1/1997, ojú ìwé 19

    Yiyan, ojú ìwé 167-168

2 Pétérù 3:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ti sọ tẹ́lẹ̀.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2003, ojú ìwé 9

    9/1/1997, ojú ìwé 19-20

    Yiyan, ojú ìwé 167-170

2 Pétérù 3:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jud 17, 18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2010, ojú ìwé 6

    12/15/2006, ojú ìwé 16-17

    8/15/2005, ojú ìwé 16

    6/1/1998, ojú ìwé 4

    9/1/1997, ojú ìwé 20-21

    3/1/1997, ojú ìwé 18-19

    Yiyan, ojú ìwé 167, 170-171

2 Pétérù 3:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 17:15; Mt 24:48; Lk 12:45
  • +Isk 12:22, 27

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2013, ojú ìwé 7-8

    12/15/2006, ojú ìwé 16-17

    6/1/1998, ojú ìwé 4

    9/1/1997, ojú ìwé 20-21

    3/1/1997, ojú ìwé 18-19

    12/15/1994, ojú ìwé 16-17

    Yiyan, ojú ìwé 167, 170, 173-174

2 Pétérù 3:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 1:6, 9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2013, ojú ìwé 5

    12/15/2006, ojú ìwé 16-17

    9/1/1997, ojú ìwé 20-21

    Yiyan, ojú ìwé 171-173, 177, 178-179

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 72

2 Pétérù 3:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 7:11, 23; Mt 24:38, 39

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    5/1/2015, ojú ìwé 5

    1/1/2013, ojú ìwé 5

    9/1/1997, ojú ìwé 20-21

    Yiyan, ojú ìwé 171-173

2 Pétérù 3:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 7:10; 2Tẹ 1:7-9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde),

    No. 1 2017 ojú ìwé 14

    Ilé Ìṣọ́,

    5/1/2015, ojú ìwé 5

    1/1/2013, ojú ìwé 5

    9/1/2012, ojú ìwé 17

    2/1/2012, ojú ìwé 25

    8/1/2010, ojú ìwé 7-8

    4/15/2000, ojú ìwé 11, 15

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 111

    Jí!,

    1/8/1997, ojú ìwé 27

    Yiyan, ojú ìwé 173, 177-180

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 186

2 Pétérù 3:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 90:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2006, ojú ìwé 17-18

    1/1/2003, ojú ìwé 10

    6/1/1999, ojú ìwé 4-5

    6/1/1998, ojú ìwé 5-6

    9/1/1997, ojú ìwé 22

    Yiyan, ojú ìwé 174-175

2 Pétérù 3:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Hab 2:3
  • +Ro 2:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    9/2021, ojú ìwé 31

    7/2021, ojú ìwé 13

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2010, ojú ìwé 23

    2/1/2006, ojú ìwé 17-18

    1/1/2003, ojú ìwé 10

    8/15/2001, ojú ìwé 28-29

    6/1/1999, ojú ìwé 5

    9/1/1997, ojú ìwé 22

    8/15/1997, ojú ìwé 17-18

    Yiyan, ojú ìwé 174, 175-176

2 Pétérù 3:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

  • *

    Tàbí “ariwo tó ń yára kọjá lọ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joẹ 2:31; Sef 1:14
  • +1Tẹ 5:2
  • +Ifi 21:1
  • +Sm 37:10; Ais 13:9; Sef 1:18; Ifi 6:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2012, ojú ìwé 25

    7/15/2010, ojú ìwé 3-5

    10/1/2009, ojú ìwé 20

    8/15/2003, ojú ìwé 11

    1/1/2003, ojú ìwé 10-11

    6/1/1999, ojú ìwé 5

    5/1/1998, ojú ìwé 12

    9/1/1997, ojú ìwé 22-23

    11/1/1995, ojú ìwé 20-21

    5/1/1992, ojú ìwé 16-17

    Yiyan, ojú ìwé 174, 175-177, 179-180

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 186

2 Pétérù 3:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    10/2019, ojú ìwé 6

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    3/2016, ojú ìwé 14-15

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2013, ojú ìwé 23

    7/15/2010, ojú ìwé 8

    3/15/2009, ojú ìwé 19

    11/15/2008, ojú ìwé 22

    12/15/2006, ojú ìwé 19

    10/1/2004, ojú ìwé 21

    2/1/2004, ojú ìwé 22

    7/15/2003, ojú ìwé 10-13

    6/1/1998, ojú ìwé 6

    9/15/1997, ojú ìwé 20

    9/1/1997, ojú ìwé 23

    3/1/1997, ojú ìwé 13-14

    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba,

    8/1995, ojú ìwé 1

    Yiyan, ojú ìwé 180

2 Pétérù 3:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

  • *

    Tàbí “tó sì ń wù yín gidigidi.” Ní Grk., “tí ẹ sì ń fẹ́ kó yára kánkán.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sef 1:14
  • +Ais 34:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2007, ojú ìwé 17

    12/15/2006, ojú ìwé 19

    10/1/2004, ojú ìwé 21

    7/15/2003, ojú ìwé 10-11, 15

    1/1/2003, ojú ìwé 10-11

    6/1/1998, ojú ìwé 6

    9/15/1997, ojú ìwé 20

    9/1/1997, ojú ìwé 19, 23

    Jọ́sìn Ọlọ́run, ojú ìwé 176-177

    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba,

    8/1995, ojú ìwé 1

    Yiyan, ojú ìwé 180, 185

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 186

2 Pétérù 3:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 65:17; 66:22; Ifi 21:1
  • +Ais 11:4, 5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìjọsìn Mímọ́, ojú ìwé 225

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    4/2017, ojú ìwé 11-12

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2010, ojú ìwé 5

    10/1/2008, ojú ìwé 8

    8/15/2007, ojú ìwé 25-26

    5/15/2006, ojú ìwé 5

    4/15/2000, ojú ìwé 11-12

    6/15/1998, ojú ìwé 32

    11/15/1997, ojú ìwé 6

    9/1/1997, ojú ìwé 23

    11/1/1995, ojú ìwé 20-21

    7/1/1995, ojú ìwé 20-21

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 301

    Ṣọ́nà!, ojú ìwé 16

    Olùkọ́, ojú ìwé 250

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 372-373, 382-383

    Yiyan, ojú ìwé 148-149

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 186

2 Pétérù 3:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kọ 13:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2010, ojú ìwé 9-10

    11/15/2008, ojú ìwé 22

    7/15/2003, ojú ìwé 13-15

    9/1/1997, ojú ìwé 23-24

    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba,

    8/1995, ojú ìwé 1

    Yiyan, ojú ìwé 185-186

2 Pétérù 3:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 2:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2000, ojú ìwé 13

    9/1/1997, ojú ìwé 23-24

    5/15/1995, ojú ìwé 16

    Yiyan, ojú ìwé 186-187

2 Pétérù 3:16

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “aláìlẹ́kọ̀ọ́.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2015, ojú ìwé 11

    9/1/1997, ojú ìwé 23-24

    5/15/1995, ojú ìwé 16

    Yiyan, ojú ìwé 186-187

2 Pétérù 3:17

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “fẹsẹ̀ múlẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 24:24; Ef 4:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2010, ojú ìwé 5, 8

    11/15/2008, ojú ìwé 22

    6/1/1998, ojú ìwé 6

    9/1/1997, ojú ìwé 24

    Yiyan, ojú ìwé 188

2 Pétérù 3:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/1999, ojú ìwé 27-28

    6/1/1998, ojú ìwé 6

    8/15/1993, ojú ìwé 12-13

Àwọn míì

2 Pét. 3:1Ro 15:15; 2Pe 1:13
2 Pét. 3:3Jud 17, 18
2 Pét. 3:4Jer 17:15; Mt 24:48; Lk 12:45
2 Pét. 3:4Isk 12:22, 27
2 Pét. 3:5Jẹ 1:6, 9
2 Pét. 3:6Jẹ 7:11, 23; Mt 24:38, 39
2 Pét. 3:7Di 7:10; 2Tẹ 1:7-9
2 Pét. 3:8Sm 90:4
2 Pét. 3:9Hab 2:3
2 Pét. 3:9Ro 2:4
2 Pét. 3:10Joẹ 2:31; Sef 1:14
2 Pét. 3:101Tẹ 5:2
2 Pét. 3:10Ifi 21:1
2 Pét. 3:10Sm 37:10; Ais 13:9; Sef 1:18; Ifi 6:14
2 Pét. 3:12Sef 1:14
2 Pét. 3:12Ais 34:4
2 Pét. 3:13Ais 65:17; 66:22; Ifi 21:1
2 Pét. 3:13Ais 11:4, 5
2 Pét. 3:142Kọ 13:11
2 Pét. 3:15Ro 2:4
2 Pét. 3:17Mt 24:24; Ef 4:14
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
2 Pétérù 3:1-18

Ìwé Kejì Pétérù

3 Ẹ̀yin ará mi ọ̀wọ́n, lẹ́tà kejì tí màá kọ sí yín nìyí, bíi ti àkọ́kọ́, mò ń rán yín létí kí n lè ta yín jí láti ronú jinlẹ̀,+ 2 kí ẹ máa rántí àwọn ọ̀rọ̀ tí àwọn wòlíì mímọ́ ti sọ ṣáájú* àti àṣẹ Olúwa àti Olùgbàlà nípasẹ̀ àwọn àpọ́sítélì yín. 3 Lákọ̀ọ́kọ́, kí ẹ mọ̀ pé ní àwọn ọjọ́ ìkẹyìn àwọn tó ń fini ṣẹlẹ́yà máa wá, wọ́n á máa fini ṣẹlẹ́yà, wọ́n á máa ṣe ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ara wọn,+ 4 wọ́n á máa sọ pé: “Ṣebí ó ṣèlérí pé òun máa wà níhìn-ín, òun wá dà?+ Ó ṣe tán, bí nǹkan ṣe rí gẹ́lẹ́ láti ọjọ́ tí àwọn baba ńlá wa ti sùn nínú ikú, bẹ́ẹ̀ náà ló rí láti ìbẹ̀rẹ̀ ìṣẹ̀dá.”+

5 Torí wọ́n mọ̀ọ́mọ̀ gbójú fo òótọ́ ọ̀rọ̀ yìí, pé nígbà àtijọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run mú kí ọ̀run àti ayé dúró digbí látinú omi, kí ó sì wà láàárín omi;+ 6 ìyẹn la sì fi pa ayé ìgbà yẹn run nígbà tí ìkún omi bò ó mọ́lẹ̀.+ 7 Ọ̀rọ̀ yẹn kan náà la fi tọ́jú àwọn ọ̀run àti ayé tó wà báyìí pa mọ́ de iná, a sì ń fi wọ́n pa mọ́ de ọjọ́ ìdájọ́ àti ti ìparun àwọn èèyàn tí kò ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run.+

8 Síbẹ̀, ẹ̀yin ará mi ọ̀wọ́n, ẹ má gbàgbé pé lójú Jèhófà* ọjọ́ kan dà bí ẹgbẹ̀rún ọdún àti pé ẹgbẹ̀rún ọdún dà bí ọjọ́ kan.+ 9 Jèhófà* kò fi ìlérí rẹ̀ falẹ̀,+ bí àwọn èèyàn kan ṣe rò pé ó ń fi falẹ̀, àmọ́ ó ń mú sùúrù fún yín torí kò fẹ́ kí ẹnikẹ́ni pa run ṣùgbọ́n ó fẹ́ kí gbogbo èèyàn ronú pìwà dà.+ 10 Àmọ́ ọjọ́ Jèhófà*+ máa dé bí olè,+ nígbà yẹn àwọn ọ̀run máa kọjá lọ+ pẹ̀lú ariwo tó rinlẹ̀,* àmọ́ àwọn ohun ìpìlẹ̀ tó gbóná janjan máa yọ́, a sì máa tú ayé àti àwọn iṣẹ́ tó wà nínú rẹ̀ síta.+

11 Bí gbogbo nǹkan yìí ṣe máa yọ́ báyìí, ẹ ronú nípa irú ẹni tó yẹ kí ẹ jẹ́ nínú ìwà mímọ́ àti àwọn iṣẹ́ ìfọkànsin Ọlọ́run, 12 bí ẹ ti ń dúró de ìgbà tí ọjọ́ Jèhófà*+ máa wà níhìn-ín, tí ẹ sì ń fi í sọ́kàn dáadáa,* nípasẹ̀ èyí tí àwọn ọ̀run máa pa run  + nínú iná, tí àwọn ohun ìpìlẹ̀ máa yọ́ nítorí ooru tó gbóná janjan! 13 Àmọ́ à ń retí ọ̀run tuntun àti ayé tuntun tó ṣèlérí,+ níbi tí òdodo á máa gbé.+

14 Nítorí náà, ẹ̀yin ará mi ọ̀wọ́n, bí ẹ ṣe ń retí àwọn nǹkan yìí, ẹ sa gbogbo ipá yín kó lè bá yín nígbẹ̀yìn-gbẹ́yín láìní èérí àti àbààwọ́n àti ní àlàáfíà.+ 15 Bákan náà, ẹ ka sùúrù Olúwa wa sí ìgbàlà, bí Pọ́ọ̀lù arákùnrin wa ọ̀wọ́n náà ṣe lo ọgbọ́n tí Ọlọ́run fún un láti kọ̀wé sí yín,+ 16 ó sọ̀rọ̀ nípa àwọn nǹkan yìí bó ti ṣe nínú gbogbo lẹ́tà rẹ̀. Àmọ́ àwọn nǹkan kan nínú wọn ṣòroó lóye, àwọn nǹkan yìí sì ni àwọn aláìmọ̀kan* àti àwọn tí kò dúró ṣinṣin ń lọ́ po sí ìparun ara wọn, bí wọ́n ti ń ṣe sí àwọn ibi yòókù nínú Ìwé Mímọ́.

17 Torí náà, ẹ̀yin ará mi ọ̀wọ́n, bí ẹ ṣe mọ àwọn nǹkan yìí tẹ́lẹ̀, ẹ máa ṣọ́ra yín kí àṣìṣe àwọn arúfin má bàa ṣì yín lọ́nà pẹ̀lú wọn, tí ẹ ò sì ní dúró ṣinṣin* mọ́.+ 18 Àmọ́ ẹ túbọ̀ máa dàgbà nínú inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí àti ìmọ̀ nípa Olúwa àti Olùgbàlà wa Jésù Kristi. Òun ni kí ògo jẹ́ tirẹ̀ báyìí àti títí láé. Àmín.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́