ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 32
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Ọba kan àti àwọn ìjòyè máa ṣàkóso fún ìdájọ́ òdodo (1-8)

      • A kìlọ̀ fún àwọn obìnrin tí ara tù (9-14)

      • Tí a bá tú ẹ̀mí jáde, ó máa mú ìbùkún wá (15-20)

Àìsáyà 32:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 49:10; Sm 2:6; Lk 1:32, 33; Jo 1:49
  • +Sm 45:6; 72:1; Ais 9:7; 11:4, 5; Jer 23:5; Sek 9:9; Heb 1:9; Ifi 19:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 164-166

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2007, ojú ìwé 25

    3/1/1999, ojú ìwé 16

    8/1/1998, ojú ìwé 15-17

    12/1/1995, ojú ìwé 18-19

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 329-332

Àìsáyà 32:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ibi ààbò.”

  • *

    Tàbí “ìlùmọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 35:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 20

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    1/2017, ojú ìwé 3

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2014, ojú ìwé 16

    2/15/2002, ojú ìwé 20, 23

    3/1/1999, ojú ìwé 16

    1/1/1996, ojú ìwé 30

    12/1/1995, ojú ìwé 18-19

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 166-167

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 330-334

Àìsáyà 32:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 334-335

Àìsáyà 32:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 35:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 335

Àìsáyà 32:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 335-336

Àìsáyà 32:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “hùwà àfojúdi.”

  • *

    Tàbí “ọkàn ẹni tí ebi ń pa.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mik 2:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 335-337

Àìsáyà 32:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 5:26; Mik 7:3
  • +1Ọb 21:9, 10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 337

Àìsáyà 32:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tó dáa.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 337-338

Àìsáyà 32:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 3:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 338-339

Àìsáyà 32:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ida 2:12; Sef 1:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 338-339

Àìsáyà 32:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “aṣọ àpò ìdọ̀họ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 3:24

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 338-339

Àìsáyà 32:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 339

Àìsáyà 32:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 22:2; Ida 2:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 339

Àìsáyà 32:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 25:9, 10
  • +2Kr 27:1, 3; Ne 3:26
  • +Ais 27:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 339-340

Àìsáyà 32:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 44:3
  • +Ais 29:17; 35:1, 2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 340

Àìsáyà 32:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 42:1, 4; 60:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 340-341

Àìsáyà 32:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 119:165; Ais 55:12
  • +Isk 37:26; Mik 4:3, 4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 340-341

Àìsáyà 32:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 60:18; 65:22; Jer 23:6; Isk 34:25; Ho 2:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 341

Àìsáyà 32:19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 341

Àìsáyà 32:20

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tú akọ màlúù àti kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ sílẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 30:23, 24

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 341

Àwọn míì

Àìsá. 32:1Jẹ 49:10; Sm 2:6; Lk 1:32, 33; Jo 1:49
Àìsá. 32:1Sm 45:6; 72:1; Ais 9:7; 11:4, 5; Jer 23:5; Sek 9:9; Heb 1:9; Ifi 19:11
Àìsá. 32:2Ais 35:6
Àìsá. 32:4Ais 35:6
Àìsá. 32:6Mik 2:1
Àìsá. 32:7Jer 5:26; Mik 7:3
Àìsá. 32:71Ọb 21:9, 10
Àìsá. 32:9Ais 3:16
Àìsá. 32:10Ida 2:12; Sef 1:13
Àìsá. 32:11Ais 3:24
Àìsá. 32:13Ais 22:2; Ida 2:15
Àìsá. 32:142Ọb 25:9, 10
Àìsá. 32:142Kr 27:1, 3; Ne 3:26
Àìsá. 32:14Ais 27:10
Àìsá. 32:15Ais 44:3
Àìsá. 32:15Ais 29:17; 35:1, 2
Àìsá. 32:16Ais 42:1, 4; 60:21
Àìsá. 32:17Sm 119:165; Ais 55:12
Àìsá. 32:17Isk 37:26; Mik 4:3, 4
Àìsá. 32:18Ais 60:18; 65:22; Jer 23:6; Isk 34:25; Ho 2:18
Àìsá. 32:20Ais 30:23, 24
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 32:1-20

Àìsáyà

32 Wò ó! Ọba+ kan máa jẹ fún òdodo,+

Àwọn ìjòyè sì máa ṣàkóso fún ìdájọ́ òdodo.

 2 Ẹnì kọ̀ọ̀kan máa dà bí ibi tó ṣeé fara pa mọ́ sí* kúrò lọ́wọ́ ẹ̀fúùfù,

Ibi ààbò* kúrò lọ́wọ́ ìjì òjò,

Bí omi tó ń ṣàn ní ilẹ̀ tí kò lómi,+

Bí òjìji àpáta ńlá ní ilẹ̀ tó gbẹ táútáú.

 3 Ojú àwọn tó ń ríran kò ní lẹ̀ pọ̀ mọ́,

Etí àwọn tó ń gbọ́ràn sì máa ṣí sílẹ̀.

 4 Ọkàn àwọn tí kì í fara balẹ̀ máa ronú nípa ìmọ̀,

Ahọ́n tó sì ń kólòlò máa sọ̀rọ̀ tó já geere, tó sì ṣe kedere.+

 5 Wọn ò tún ní pe aláìnírònú ní ọ̀làwọ́ mọ́,

Wọn ò sì ní pe oníwàkiwà ní èèyàn pàtàkì mọ́;

 6 Torí aláìnírònú máa sọ̀rọ̀ òmùgọ̀,

Ọkàn rẹ̀ sì máa gbèrò ibi,+

Láti gbé ìpẹ̀yìndà lárugẹ,* kó sì máa sọ ọ̀rọ̀kọrọ̀ sí Jèhófà,

Láti mú kí ẹni tí ebi ń pa* wà láìjẹun,

Kó sì fi ohun mímu du ẹni tí òùngbẹ ń gbẹ.

 7 Ohun búburú ni ọkùnrin oníwàkíwà ń gbèrò;+

Ìwà àìnítìjú ló ń gbé lárugẹ,

Kó lè fi irọ́ ba ti ẹni tí ìyà ń jẹ jẹ́,+

Kódà nígbà tí aláìní bá ń sọ ohun tó tọ́.

 8 Àmọ́ èrò ọ̀làwọ́ ló wà lọ́kàn ẹni tó lawọ́;

Kì í sì í jáwọ́ nínú àwọn ìṣe ọ̀làwọ́.*

 9 “Ẹ̀yin obìnrin tí ara tù, ẹ dìde, kí ẹ fetí sí ohùn mi!

Ẹ̀yin ọmọbìnrin+ tí ẹ ò ka nǹkan sí, ẹ fiyè sí ohun tí mò ń sọ!

10 Láàárín ọdún kan ó lé díẹ̀, jìnnìjìnnì máa bá ẹ̀yin tí ẹ ò ka nǹkan sí,

Torí a ò ní tíì kó èso kankan jọ nígbà tí ìkórè èso àjàrà bá dópin.+

11 Ẹ wárìrì, ẹ̀yin obìnrin tí ara tù!

Ẹ gbọ̀n jìnnìjìnnì, ẹyin tí kò ka nǹkan sí!

Ẹ bọ́ra yín sí ìhòòhò,

Kí ẹ sì ró aṣọ ọ̀fọ̀* mọ́ ìbàdí yín.+

12 Ẹ lu ọmú yín bí ẹ ṣe ń dárò

Torí àwọn pápá tí ẹ fẹ́ràn àti àjàrà tó ń méso jáde.

13 Torí ẹ̀gún àti òṣùṣú máa bo ilẹ̀ àwọn èèyàn mi;

Wọ́n máa bo gbogbo ilé tí wọ́n ti ń yọ̀,

Àní, ìlú tó ń yọ̀ gidigidi.+

14 Torí wọ́n ti pa ilé gogoro tó láàbò tì;

Wọ́n ti pa ìlú aláriwo tì.+

Ófélì+ àti ilé ìṣọ́ ti di ahoro títí láé,

Ààyò àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ igbó,

Ibi ìjẹko àwọn agbo ẹran,+

15 Títí dìgbà tí a bá tú ẹ̀mí jáde sórí wa látòkè,+

Tí aginjù di ọgbà eléso,

Tí a sì ka ọgbà eléso sí igbó.+

16 Ìdájọ́ òdodo á wá máa gbé ní aginjù,

Òdodo á sì máa gbé inú ọgbà eléso.+

17 Àlàáfíà ni òdodo tòótọ́ máa mú wá, +

Èso òdodo tòótọ́ sì máa jẹ́ ìparọ́rọ́ àti ààbò tó máa wà pẹ́ títí.+

18 Ibi tí àlàáfíà ti jọba làwọn èèyàn mi á máa gbé,

Nínú àwọn ibi tó ní ààbò àtàwọn ibi ìsinmi tó pa rọ́rọ́.+

19 Àmọ́ yìnyín máa mú kí igbó tẹ́ pẹrẹsẹ,

Ìlú sì máa di ibi tó tẹ́jú pátápátá.

20 Aláyọ̀ ni ẹ̀yin tí ẹ̀ ń fún irúgbìn sétí gbogbo omi,

Tí ẹ̀ ń rán akọ màlúù àti kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ jáde.”*+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́